tubabie: Ohhhh mo feran nkan ti o kosi ibiyii. So sweet
. Truely, he loves it. And when I say joooooooo! (like Dagrin) he laughs. Sometimes I feel like crying for joy. It touches me to the bone. A plan l'ati lo si Naija to ba pe 1 yr.
tubabie: Yes o, maa lo to ba je fun bundle of joy yin. lol Any way mo le yoju si naija laipe so talomo . . . . . . . . . . .ka si maa wo But duro naa, omo yii ko ti lee ka nkan kan now
To ba wa si naija oma nice gan . In fact emi na n plan lati lo amo mi o ti mo igba na. . . ka si maa wo. Nitooto ni pe omo si kere, ko de ti lee ka iwe amo emi le kaa fun. But he likes it when I speak Yoruba to him. You need to see his smile. It melts my heart.
IFELEKE: FBS, uhmm. . .Igi nla lo wo l'ojo ti alabefe sun ti o ji mo. . .awa ololufe e n se ranti e a de mo wipe ise e ko le parun. Nipa iwe itan,apa ibo lo wa? Orile, Eeeyan mi mo wa daada joo, se alaafia ni? ise ati awon tibitibi nko? se gbogbo e n lo deede? yara mo 'se oo, ma se so le.
Gbenga Adeboye is classic.
Nipa ti iwe, Naija ko ni mo wa. its classified Mo de si ti check ori google amo mi o ri nkan ti mo fe.
tubabie: by FBS hmmm that will have to be in Naija, you can check Challenge bookstores in most major cities in naija. At least I know they are popular bookshops in Ibadan and Ilorin and Jos. You should get those there. Is it for our latest chelsea boy?
Yes oooh. Its for my Bundle of Joy . Amo idi ti mo fi bere ni gan gan ni yen. (see bolded). Ta ni mo fe ran lo si Naija abi wa lo fun mi?
Remii: ^^^^ FBS, O ya tun ibeere re beere, maa gbiyan ati dahun ti o ba moo. Emi naa feran Abefe jengbetiele, mo de ni almost gbogbo CD re lati ori PHD beatle, iboosi NEPA ati beebeelo.
Itu baba Ita hot gan. . .gbogbo tapes ati CDs E ni mo ra. In fact mo didi lo si office e l'ati lo wa amon ko si ni office ni gba ti mo de be.
Ibere mi ni wipe:
FBS: Ẹ jọ̀ wọ́ ta ló mọ ibi tí mo tí lè rí àlọ̣̣́ tàbí ìtàn (stories) ní èdè yòrùbá fún awọ́n ọmọ kékeré
eyin peeps l'ori tiredi yi, e nice ra ra . Mo be re ibere amo ko si eni to da mi l'ohun. ki lo de?
Sugbon mo ko ni binu si yin rara nitori wi pe mi o mo bi won shen bi nu.
Meanwhile. . .
Fun awon ti o mo, ti won si fe ran Gbenga Adeboye (R.I.P) a.k.a Itu Baba Ita. Emi ni temi O, Mo feran bobo na mo de miss e gan. Ni gbogbo alawada (ati awon MC's) Orile ede wa ati gbogbo aye, Gbenga Adeboya alias Mr Funwantan je NUMBER 1.
E gba ke woooooooo Mr Funwantan Alhaji Pastor Oluwo Gbenga Adeboye.
Oh Yes she is back. The Diva herself is back. Some cracking tracks on her album.
"I look to you" is a chart crasher. Damn, very refreshing to hear some natural voice again. (not some autotunes ) Whitney Houston is back. What a voice. What a woman. Classic.
[quote author=~Sauron~ link=topic=323870.msg4557449#msg4557449 date=1253127789]But wait a minute. . . . . .Are Standard Liege this good or what? They can work the ball neatly too. . . . . I am impressed!!!![/quote]Mehnnnn I initially thought the arses are the ones in red jerseys
[quote author=~Sauron~ link=topic=323870.msg4557386#msg4557386 date=1253127356]I was watching Inter V Barca before but i had to come back to this one. Bleep Messi. . . .Bleep Milito. This is where the party is. [/quote]Same here. . .
MrCrackles: Resolved? Fingers crossed. . . . . AW professor at poaching kids? That is not the issue here. . . If you have a centre of excellence and academies, you will cop kids. . . Going about it the wrong way is what we are talking about! Did you see Arsenal bribe Jack Wilshere's parents with a Ford Galaxy or did you see us buy Nintendo Wii's for Fran Merida's family? You guys went about the whole shit the wrong way and i hope you pay fully for it! Buncha useless Maloudas!
I laugh in tawi-tawi. We committed none of those crimes so quit it. You should be more concerned about Ade right now. Bunch of arseless asses.