₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,614 members, 8,422,862 topics. Date: Monday, 08 June 2026 at 10:35 PM

Toggle theme

Ṣe Loooto Pé Gbogbo Eniyan Maa Farasin Lati Naijiria? - Nairaland General - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralṢe Loooto Pé Gbogbo Eniyan Maa Farasin Lati Naijiria? (153 Views)

1 Reply

Ṣe Loooto Pé Gbogbo Eniyan Maa Farasin Lati Naijiria? by omoOlorun3(op): 9:10pm On Jul 19, 2025
Ṣe loooto pé gbogbo eniyan maa farasin lati Naijiria?
Awa mọ pé gbogbo eniyan fẹ japa lati Naijiria. Won fẹ lọ si awon orilẹ-èdè Oyinbo nitori pé awa ni orisirisi wahala ati iṣoro ni Naijiria. Gbogbo eniyan sọ pé igbesi ayé ni Naijiria, ko daa, nitooto o buru gidi gan! Gbogbo eniyan fẹ japa. O wa ọrọ titun ni Naijiria lati èdè Yoruba fun irin ajo yii, awa n pe e «japa.» Ṣugbọn ki i ṣe gbogbo eniyan ti o ni agbara ati owo lati japa. Ṣugbọn ti won ba gba owo ati agbara lati japa, eniyan ti o pọ ju idaji ti Naijiria, won maa japa! Awa ni ẹri ati iṣiro fun e. Mo nireti pé awọn eniyan Yoruba ati eniyan ti Naijiria maa ro, «Ko wa nipa ohun ti orilẹ-èdè maa ṣe fun o, ṣugbon nipa ohun ti o maa ṣe fun orilẹ-èdè re.» Ona ti awa n ro nipa èdè wa, wa ona kan naa ti awa n ro nipa orilẹ-èdè wa. Awọn èdè wa, awọn èdè ti Naijiria, won fi ku ati èdè Yoruba pẹlu. Ati nissi orilẹ-èdè wa maa fi ku pẹlu, nitori pé gbogbo eniyan fẹ japa. Ni ọdun meji eniyan ti o pọ ju egbelegbe mẹta (3,000,000) si japa lati Naijiria lati ọdun egbaa-o-le-méjilelogun si egbaa-o-le-mẹtalelogun (2022-2023)! O pọ, o pọ oo! Awa n ro pé awon orilẹ-èdè Oyinbo ati èdè won ati gbogbo ohun nipa won daa ju wa. Ṣugbọn, ti awa ba de nibẹ, awa maa ni wahala ti o pọ ju. Ki lo dé, ko dara, awa n ro ni gbogbo asiko, «kini orile-èdè mi maa ṣe fun mi, kini orilẹ-èdè mi maa ṣe fun mi, ati emi ni nikan!» Lataro awa ma sọ ohun yii nikan, ṣugbọn, nigba wo awa si béèrè wa, «Kini mo le ṣe fun orilẹ-èdè mi» Idi ti Naijiria, orilẹ-èdè wa ni wahala ti o ni oni wa nitori gbogbo ènìyàn ro nipa ara won ati nipa ara won nikan, won ko bikita nipa awon ènìyàn miiran. Emi yoo tun sọ e nikan asiko keji, «Ko wa nipa ohun ti orilẹ-èdè le ṣe fun o, ṣugbọn nipa ohun ti e le ṣe fun orilẹ-èdè re» Awa fun ogo si Oluwa Olorun ati o maa ran wa lọwọ ni awọn asiko buburu ati ipọnju wa, ni oruko Jesu!
Kini awọn wahala ati iṣoro ti awa ni ni Naijiria?
Ọpọlọpọ eniyan ni Naijiria, talaka ati otoṣi ni won. Awa ni ibaje ni awọn ijoba wa pelu. Tele tele naira egberun mewaa (10,000) si je dola $mejilelogun (22) sugbon nissi naira egberun mewaa (10,000) si di dola $mefa (6)!! Ki lo dé?!?!

Re: Ṣe Loooto Pé Gbogbo Eniyan Maa Farasin Lati Naijiria? by DMCY: 9:41pm On Jul 19, 2025
[/quote]Bruh, is this ChatGPT or you ‘cause you want to make me convulse while reading it Pelu bi mo shey mo Yoruba kaa daradara toh even with the Amin on it. Try more ser!
Goodluck!
Re: Ṣe Loooto Pé Gbogbo Eniyan Maa Farasin Lati Naijiria? by omoOlorun3(op): 9:58pm On Jul 19, 2025
Ko si «sh» ni èdè Yoruba, awa n lo «ṣ» ati mi o ti lo ChatGPT, mo si lo ori mi, ati ki le n sọ, «ko ye mi» Yoruba rọrun ni e, abi?
DMCY:
Bruh, is this ChatGPT or you ‘cause you want to make me convulse while reading it Pelu bi mo shey mo Yoruba kaa daradara toh even with the Amin on it. Try more ser!
Goodluck!
1 Reply

E Maa Wo Ori Omo Yen O.... "Watch That Child's Head"BCS Ragasur - Iski Maa Ka Saakinaaka Lyrics - Letras2.com[photos] Davido Buys Lati A Brand New Benz234

Lagos Farmer Cries Out As Rolad Properties Withholds N3.15m Return On InvestmentGoodluck Nwaneri Condoles APC National Chairman Nentawe Over Mother's DemiseJODER Calls For Training Of Government Aides Over Harassment Of Journalists By S