₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,684 members, 8,427,611 topics. Date: Tuesday, 16 June 2026 at 08:36 AM

Toggle theme

Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá - Culture - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureOrúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá (772 Views)

1 2 Reply (Go Down)

Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 11:07pm On Oct 30, 2025
Mo shí abala yi láti She àfihàn onírúurú Àwọ̀ ní Yorùbá pẹ̀lú àwọn àwòrán wọn kí o lè rọrùn fún wa láti dá wọn mọ̀

Awọn míràn nínú àwọn awọ̀ yí tí ni orúkọ tẹlẹ rí, Shugbọ́n awọn míràn wà tí o jẹ wípé awa ni a sh fún wọn ní orúkọ Titun

Ọpẹ pàtàkì fún @Science_in_yoruba ati @Agbarotede Ti wọn fún púpọ nínú àwọn awọ̀ yí ni orúkọ Titun


Dúdú — Black

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 11:11pm On Oct 30, 2025
Funfun — White

Àwọ̀ Funfun ballau ni yoruba

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 11:12pm On Oct 30, 2025
Pupa — Red

Àwọ̀ Pupa ti wà ní èdè Yorùbá tẹlẹ rí

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Ọ̀bẹdọ̀ — Green

Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni a ma ùn pe (Green) ni àwọ̀ ewé - Shugbọ́n nínú ishẹ́ ìwádìí mi, Mo She alabapade orúkọ yi (Ọ̀bẹdọ̀) nínú ìwé Àjàyí crowther fun Àwọ̀ ewé

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Ẹ̀pọ́nrúsú — Brown

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Òfèhèfè — Yellow

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 8:43am On Oct 31, 2025
Aró — Blue

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 8:44am On Oct 31, 2025
Sọwé — Emerald

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Tayorshd87(m): 8:56am On Oct 31, 2025
Nice just heard of yellow for the first time
Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:21am On Oct 31, 2025
Ewéyòò — Neon green

Tí a bá fẹ she atúpalẹ̀ "Ewéyòò" , Nkan ti o tunmọ̀ sì ni wípé "Ewé tí o tàn Yòò"

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Èsèèdú — Purple

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:28am On Oct 31, 2025
Èsè-Àlùkò — Violet

@ScienceInyoruba ni ó sọ àwọ̀ yi ni orúkọ

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:30am On Oct 31, 2025
Ẹ̀lù — Indigo

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:32am On Oct 31, 2025
Arówé — Cyan

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:33am On Oct 31, 2025
Lúkúsù — Peach

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:34am On Oct 31, 2025
Ọlọ́yẹ́ — Grey

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:37am On Oct 31, 2025
Ọsànwọ̀ — Orange

Orúkọ yi wáyé látàrì àpapọ Ọsàn ati Àwọ̀

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:39am On Oct 31, 2025
Ìtuná — Pink

A tún lè pèé ní"Gbúre

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Maj196(m): 10:12am On Oct 31, 2025
Ese pupo, opolopo Omo Yoruba o ma awon awo yato si dudu, pupa, funfun ati booya aro
Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Pupadú — Burgundy

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op):
Pupayòò — Scarlet

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by fmlala: 11:07am On Oct 31, 2025
You have done well to lecture some of us who are Yorubas but are not familiar with the colours in our own language.


Kundusi fun yin o
Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Yemmysworld91: 12:09pm On Oct 31, 2025
This is brilliant. I just learnt about colours in Yoruba. Good job
Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 12:13pm On Oct 31, 2025
Èfì — Cream

Àwọ̀ eléyìí jẹ ìkan lára àwọn àwọ̀ ti mo fẹràn jù

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Elliotwaveforec: 12:49pm On Oct 31, 2025
E ku ise takuntakun!
Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:11pm On Oct 31, 2025
Wúrà — Gold

Mo lérò wípé gbogbo wa pata ni a ti ri àwọ̀ wúrà rí

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:16pm On Oct 31, 2025
Àlárì — Maroon

O ní ìkan lára àwọn Adẹ́rìnpọ̀shónú L'órí tiktok ti o ùn lo "Àlàrí" gégébí inagijẹ rẹ, Púpọ lára wa lè ti ba fónrán rẹ pàdé rí (Kidbaby) — Shugbọ́n Njẹ ẹ mo wípé orúkọ "Àlàrí" yi jẹyọ latara Asho-òkè kan ti àwọ̀ rẹ̀ fi ará jọ Àwọ̀ (Maroon)

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:21pm On Oct 31, 2025
Sányán — Tan

Àwọ̀ Asho-òkè Sányán ni ó she àtinúda fún sísọ Àwọ̀ yi li orúkọ yi

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:25pm On Oct 31, 2025
Lenbe — Coral

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:29pm On Oct 31, 2025
Shúro — Navy blue

Ìsùnkì Àti ipàrójẹ wà nínú òrùkọ yìí
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ orúkọ yi gangan ni (Shú—Aró) Ni èyí tí o tunmọ sí Aró ti ó shú (Shú as in Dark)

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:31pm On Oct 31, 2025
Rínrin — Lemon

Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Justiceleague1: 1:47pm On Oct 31, 2025
Raydos:
Mo shí abala yi láti She àfihàn onírúurú Àwọ̀ ní Yorùbá pẹ̀lú àwọn àwòrán wọn kí o lè rọrùn fún wa láti dá wọn mọ̀

Awọn míràn nínú àwọn awọ̀ yí tí ni orúkọ tẹlẹ rí, Shugbọ́n awọn míràn wà tí o jẹ wípé awa ni a sh fún wọn ní orúkọ Titun

Ọpẹ pàtàkì fún @Science_in_yoruba ati @Agbarotede Ti wọn fún púpọ nínú àwọn awọ̀ yí ni orúkọ Titun


Dúdú — Black
Do some translation please
1 2 Reply

Orúkọ Awọn Ewe Pẹlu AworanÀwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú AwòránÀwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán234

What's With The Left Hand DeclinePlease Help!Your Names And Its Interpretation