₦airaland Forum

Welcome, Guest: Register • Login • With Google • Trending • Recent • New

Stats: 3,346,810 members, 8,525,199 topics. Date: Thursday, 26 November 2026 at 09:28 AM

Toggle theme

Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? - Culture - Nairaland

Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? (4067 Views)

1 Reply (Go Down)

Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(op): 3:40pm On Jul 15, 2015
Itan je ohun to se pataki lati igba awon baba baba wa, le yi to je pe won tun fi le awa odo isin yi l'owo. E je ki a wo itan "Akara Oogun" ninu iwe "Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmole". Itan yi je okan pataki ninu awon itan isembaye ti o is je wipe sasa ni ogidi omo Yoruba ti ko ti ni gbo ri.

O daa, ewo ni eyin rantihuh E je ka sare se ere opolo yen ni pa pa pa....
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by ahmedtijani(m): 3:47pm On Jul 15, 2015
[color=#000099][/color] Idamu paadi
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by Wealthyone: 3:48pm On Jul 15, 2015
Mo ka itan lopolopo ni igba timo wa ni ile iwe girama. Awon eyi ti aka ni yara ikawe ati awon eyi ti baba mi ma nra fun akagbadun. Iwe D.O Fagunwa ama po, aasi tun ma dunka. Inumi dun pupo pee mo mo yooba ko, mo si mooka daada.

1. Ireke onibudo
2. Eru Obodo
3. Ogbuju Ode ninu igbo Olodumare
4. Adiitu.........
5. Idaamu Mikailu ati Paadi
6. Ati awon mi ti mio ranti mo
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by omitooguns(m): 3:52pm On Jul 15, 2015
Sisigbeborun, oruko e yi le kuu oo. Oda na...emi ko ka itan ni ri.

Die ninu eyi ti moka ni "Sisi jet'we"..."Tijapa tiroko"..."Ruutu abokoku" ati be be lo...oya e sa wo...ki ni itan ti o da ru ko ye da le lori.
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(op): 4:41pm On Jul 15, 2015
omitooguns:
Sisigbeborun, oruko e yi le kuu oo. Oda na...emi ko ka itan ni ri.

Die ninu eyi ti moka ni "Sisi jet'we"..."Tijapa tiroko"..."Ruutu abokoku" ati be be lo...oya e sa wo...ki ni itan ti o da ru ko ye da le lori.
Itan yen da le ori awon akoni meje ti won won lo si'nu igbo irunmole. L'ara won ni Akara oogun, Imodoye, Olohun Iyo, Kako onikumo ekun, ati bee bee lo. Ibi ti mo feran ju ninu iwe yi ni ibi ti won ti so wipe "Awa ti a je akoni je meje"....hehehe
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by omitooguns(m): 4:56pm On Jul 15, 2015
SisiGbeborun:
"Awa ti a je akoni je meje"....hehehe
se o si ni iwe yin?...ma fe lati ka won...mo ti n ka iwe ede oyinbo poju...ati ede faranse.
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by scholes0(m): 7:04pm On Jul 15, 2015
Wealthyone:
Mo ka itan lopolopo ni igba timo wa ni ile iwe girama. Awon eyi ti aka ni yara ikawe ati awon eyi ti baba mi ma nra fun akagbadun. Iwe D.O Fagunwa ama po, aasi tun ma dunka. Inumi dun pupo pee mo mo yooba ko, mo si mooka daada.

1. Ireke onibudo
2. Eru Obodo
3. Ogbuju Ode ninu igbo Olodumare
4. Adiitu.........
5. Idaamu Mikailu ati Paadi
6. Ati awon mi ti mio ranti mo
Emi naa ka Igbo Olodumare ati Aditu Olodumare.
mo ka Ireke onibudo ati beee bee lo

1 Reply

#yorubanews Iru Idajọ Wo Ni Ile-ẹjọ Fẹ Da Fun Seun Egbegbe • [Audio] "Bayii Ni E Se Le Se Awari Ebun Yin": Alaye Lati Enu Olayemi Oniroyin • Ogun Awon Bàba Wa • 2 • 3 • 4

Translate These Yoruba Sentence Into English. Linguista • Michael Jackson's Brothers Attend Ofala Festival At Onitsha • Is Nigeria Central Africa?