₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,331,409 members, 8,450,196 topics. Date: Wednesday, 22 July 2026 at 10:36 PM

Toggle theme

MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si - Culture - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureMAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si (909 Views)

1 Reply (Go Down)

MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by SisiGbeborun(op): 10:51pm On Jul 19, 2015
L'ana ode yi ni MAMA2015 waye ni ilu South Africa, to si je wipe awon omo Naija ko meje(7) ninu gbogbo awon ami eye(Awards) ti won fi da awon olorin lati ile adulawo(African Artistes) l'ola...

E woo, ki n ma soro ju, e ka ekunrere awon ishele yen ni'bi - www.sisigbeborun..com
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by Nobody: 10:59pm On Jul 19, 2015
asee lonso
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by SisiGbeborun(op): 11:06pm On Jul 19, 2015
Hehehe, iwo lo ro be...nje omo Yoruba tooto ni e?
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by bigt2(m): 11:17pm On Jul 19, 2015
Gbogbo yin ni lati lo ko bi se n lo akoto to jinna. Ire o.
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by scholes0(m): 11:52pm On Jul 19, 2015
Se otito ni wipe Davido ati Phyno ko gba Ife-eye kankan rara ni?
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by tmanis(m): 3:46am On Jul 20, 2015
gbogbo yorùbá yín tí kò tiè lámì.....
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by damiloladuke: 9:12am On Jul 20, 2015
tmanis:
gbogbo yorùbá yín tí kò tiè lámì.....
is it every computing device that can use the Amin?
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by scholes0(m): 9:17am On Jul 20, 2015
tmanis:
gbogbo yorùbá yín tí kò tiè lámì.....
Ìgbàgbó mi ni wípé, fún àwon eni tó lè ka Èdè Yorùbá dáadáa, kìí se dandan ni, kí Yorùbá kíko won ní aàmì lórí
Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by tmanis(m): 9:32am On Jul 20, 2015
damiloladuke:
is it every computing device that can use the Amin?
probably... most phones can use it, and Yoruba books with àmì are typed with computers...
1 Reply

Ogun Awon Bàba WaOpe O! Ijoba Ipinle Osun Ti F'owo Si Sisan Owo Awon OsiseAwon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin???234

High-ways Out Of Poverty And LackAfia Olu Nnewi; Preserve, Improve, Invent; Ezeemo, Igboezue AdvocateYoruba Alphabet