₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,036 members, 8,443,567 topics. Date: Sunday, 12 July 2026 at 03:56 AM

Toggle theme

Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira - Culture - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureAwon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira (1250 Views)

1 Reply (Go Down)

Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by SisiGbeborun(op): 1:43pm On Sep 22, 2015
Ojo to ye ko je ojo idunnu ati ayo, lo ti ja si ojo ibanuje bayi fun agba oje oloselu ati oludije fun ipo aare tele ri labe asia egbe oselu AD l'odun 1999, oloye Olu Falae, eni to tun ti fi igba kan ri je akowe fun ijoba apapo ile wa. Olu Falae la gbo pe awon kan ti won fura si pe Fulani daran-daran ji gbe salo lojo ti o n se ayeye ojo ibi re. Oko Falae to wa ni Ilado, l'oju ona Igbatoro l'Akure ni awon ajinigbe lo ka mo, ti won si ji gbe salo.
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/awon-to-ji-olu-falae-gbe-n-beere-ogorun.html
Re: Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by ellachuku: 1:53pm On Sep 22, 2015
Too much amala is bad.
Re: Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by Wulfruna(f): 2:15pm On Sep 22, 2015
ellachuku:
Too much amala is bad.
And a little stupidity is worse.
Re: Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by ellachuku: 2:18pm On Sep 22, 2015
Wulfruna:
And a little stupidity is worse.
The amala eaters are crawling out... cheesy cheesy
Re: Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by Cuddlebugie(f): 7:24pm On Sep 22, 2015
You like our amala, yes? ..........We also love your akpu undecided

So, you see, the feeling is mutual
ellachuku:
The amala eaters are crawling out... cheesy cheesy
1 Reply

Eze Chukwuemeka Eri, Aka Ji Ovo Igbo Leads Community To Omambala RiverOgun Awon Bàba WaThe Sculpture Located At Beere, Ibadan234

Myths - Sorounding Oranmiyan-staffShort Story Of People Of Ijaiye And KurunmiMantafien Gbako Local Gov't-aliyu Mantafien