Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser - Politics (2) - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Politics › Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser (2641 Views)
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:21pm On Dec 03, 2015 |
Firefire:Omode ti o ba ri agbalagba fin, a ma nran iru won sile ni. Bi o ti lewu ki o ri, ma to aburo fun awon baami re. Omoluabi ko gbodo ma yaju si eeyan lawujo. Koda ki o ma mo iru eniti eni naa je. O baje pupo ju. Akobi mi le ni odun merinla. Bi a ba jo nsere ni NL, ki a mo iwon ara wa. |
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 3:29pm On Dec 03, 2015 |
PassingShot:Osi pelebe, emolutu pebe, arifin ile-igbe ![]() Ose ni lanu fun ee gan, to ri wipe a ti jo n se Geography ni bi lo fi un ya map ojo ori ee fun mi ? I ba se pe I wo mo eni to wa ni idi Firefire ni, iwo I ba gbe enu re dake. Bakana, oki se Omoluabi rara, iba je pe iwo je Omoluabi, o ni ma bu aburo baba bayi. Nonsense. |
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:36pm On Dec 03, 2015 |
Firefire:Ki ba dara ki o so ojo ori re fun mi boya onikaluku a mo iwon ara re. Iwo lo ko so wipe n o kan abuku. Mo si nigbagbo wipe emi ma to aburo baami re ni mo fi ran o sile. Akobi mi je omo odun merinla ati aabo. E so tiyin o, buroda firefire. |
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 3:44pm On Dec 03, 2015 |
PassingShot:Number lasan lojo ori ooo, ade ju ra wa lo, tija kadi ko. Kele gbe mo egbe eee. Owo die die de ni ara nfe. Emi na de ti ran pada sile bayi, lo ji se fun won, pe o gba eko. |
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:57pm On Dec 03, 2015 |
Firefire:Bi ogo se nje ti Olohun ti mo fi ju e lojo ori, bee naa ni Olohun ko fi ipo jemi niya. Eeyan ninu awon ti o je sawaawu mi, ti o fi ipo jumi ko to awon ti mo fi ipo ju. Mo dupe fun Olohun lori iyen naa. Ilu okere ni emi, iyawo ati awon omo ti ngbadun aye wa lati bi odun mewa seyin. Bee ko si odun ti a o ki nwa sile fun isinmi olodoodun. Oore ti Olohun ti se fun mi po pupo. Se ile ni ki a so ni? Abi owo, abi ise alalubarika? Abi awon omo aridunnu? Aburo, igberaga ko, Olohun gbadura mi koja ki n ma tara nkan ki nkan ti iwo i baaje lo. Alhamdulillah. Lo ko eko bi a se nwuwa lawujo pelu omo Yoruba. O dabo. |
| Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 4:17pm On Dec 03, 2015 |
PassingShot:Mo rerin,igba iwase' ![]() Mo ba e dupe lowo Olorun Oba. Sugbon ma gbagbe pe, igbega ko ti I'wo orun, tabi ila'orun wa. Pelu gbogbo alaye ati atotonu ee, emi a ti e ki si se egbe. boya o gba ta bi o gba. (Ni gbogbo Ona, inclusive of all you mentioned). So, so ara eee, ki Olorun so. Ma lo kan idin ninu iyo. Mi oni so ju be lo. Alafia fun ee o. O di gba. ![]() |
Kwankwaso, Amaechi, Others Bought Their Way To APC With N100m Each — Bafarawa • Arms Deal: I Got N100m From Mu’azu, Not Yuguda – Nwobodo • Bode George, Odili Got N100M Each From Dasuki In Arms Purchase Scam - Sahara Rep • 2 • 3 • 4
Don’t Accept Excuses For Power Failure, Fashola Tells Nigerians • Help!Nigerian Army Should Tell Us What Happened To this gallant soldier • A Nairalander And Kanu PICS


