₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,935 members, 8,428,705 topics. Date: Wednesday, 17 June 2026 at 08:43 PM

Toggle theme

Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser - Politics (2) - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralPoliticsOde George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser (2642 Views)

1 2 Reply (Go Down)

Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:21pm On Dec 03, 2015
Firefire:
Alakogba, won ko e sugbon o gba eko.

Kilo kan aburo baba ee ninu oro to wa nle yi ? undecided
Omode ti o ba ri agbalagba fin, a ma nran iru won sile ni. Bi o ti lewu ki o ri, ma to aburo fun awon baami re.

Omoluabi ko gbodo ma yaju si eeyan lawujo. Koda ki o ma mo iru eniti eni naa je. O baje pupo ju. Akobi mi le ni odun merinla. Bi a ba jo nsere ni NL, ki a mo iwon ara wa.
Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 3:29pm On Dec 03, 2015
PassingShot:
Omode ti o ba ri agbalagba fin, a ma nran iru won sile ni. Bi o ti lewu ki o ri, ma to aburo fun awon baami re.

Omoluabi ko gbodo ma yaju si eeyan lawujo. Koda ki o ma mo iru eniti eni naa je. O baje pupo ju.
Osi pelebe, emolutu pebe, arifin ile-igbe undecided

Ose ni lanu fun ee gan, to ri wipe a ti jo n se Geography ni bi lo fi un ya map ojo ori ee fun mi ?

I ba se pe I wo mo eni to wa ni idi Firefire ni, iwo I ba gbe enu re dake.

Bakana, oki se Omoluabi rara, iba je pe iwo je Omoluabi, o ni ma bu aburo baba bayi. Nonsense.
Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:36pm On Dec 03, 2015
Firefire:
Osi pelebe, emolutu pebe, arifin ile-igbe undecided

Ose ni lanu fun ee gan, to ri wipe a ti jo n se Geography ni bi lo fi un ya map ojo ori ee fun mi ?

I ba se pe I wo mo eni to wa ni idi Firefire ni, iwo I ba gbe enu re dake.

Bakana, oki se Omoluabi rara, iba je pe iwo je Omoluabi, o ni ma bu aburo baba bayi. Nonsense.
Ki ba dara ki o so ojo ori re fun mi boya onikaluku a mo iwon ara re. Iwo lo ko so wipe n o kan abuku. Mo si nigbagbo wipe emi ma to aburo baami re ni mo fi ran o sile. Akobi mi je omo odun merinla ati aabo.
E so tiyin o, buroda firefire.
Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 3:44pm On Dec 03, 2015
PassingShot:
Ki ba dara ki o so ojo ori re fun mi boya onikaluku a mo iwon ara re. Iwo lo ko so wipe n o kan abuku. Mo si nigbagbo wipe emi ma to aburo baami re ni mo fi ran o sile . Akobi mi je omo odun merinla ati aabo.
E so tiyin o, buroda firefire.
Number lasan lojo ori ooo, ade ju ra wa lo, tija kadi ko.

Kele gbe mo egbe eee. Owo die die de ni ara nfe.

Emi na de ti ran pada sile bayi, lo ji se fun won, pe o gba eko.
Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by PassingShot(m): 3:57pm On Dec 03, 2015
Firefire:
Number lasan lojo ori ooo, ade ju ra wa lo, tija kadi ko.

Kele gbe mo egbe eee. Owo die die de ni ara nfe.

Emi na de ti ran pada sile bayi, lo ji se fun won, pe o gba eko.
Bi ogo se nje ti Olohun ti mo fi ju e lojo ori, bee naa ni Olohun ko fi ipo jemi niya. Eeyan ninu awon ti o je sawaawu mi, ti o fi ipo jumi ko to awon ti mo fi ipo ju. Mo dupe fun Olohun lori iyen naa. Ilu okere ni emi, iyawo ati awon omo ti ngbadun aye wa lati bi odun mewa seyin. Bee ko si odun ti a o ki nwa sile fun isinmi olodoodun. Oore ti Olohun ti se fun mi po pupo. Se ile ni ki a so ni? Abi owo, abi ise alalubarika? Abi awon omo aridunnu?
Aburo, igberaga ko, Olohun gbadura mi koja ki n ma tara nkan ki nkan ti iwo i baaje lo. Alhamdulillah.
Lo ko eko bi a se nwuwa lawujo pelu omo Yoruba.

O dabo.
Re: Ode George, Former Governor Odili Got N100M Each From National Security Adviser by Firefire(m): 4:17pm On Dec 03, 2015
PassingShot:
Bi ogo se nje ti Olohun ti mo fi ju e lojo ori, bee naa ni Olohun ko fi ipo jemi niya. Eeyan ninu awon ti o je sawaawu mi, ti o fi ipo jumi ko to awon ti mo fi ipo ju. Mo dupe fun Olohun lori iyen naa. Ilu okere ni emi, iyawo ati awon omo ti ngbadun aye wa lati bi odun mewa seyin. Bee ko si odun ti a o ki nwa sile fun isinmi olodoodun. Oore ti Olohun ti se fun mi po pupo. Se ile ni ki a so ni? Abi owo, abi ise alalubarika? Abi awon omo aridunnu?
Aburo, igberaga ko, Olohun gbadura mi koja ki n ma tara nkan ki nkan ti iwo i baaje lo. Alhamdulillah.
Lo ko eko bi a se nwuwa lawujo pelu omo Yoruba.

O dabo.
Mo rerin,igba iwase' cheesy

Mo ba e dupe lowo Olorun Oba.

Sugbon ma gbagbe pe, igbega ko ti I'wo orun, tabi ila'orun wa.

Pelu gbogbo alaye ati atotonu ee, emi a ti e ki si se egbe. boya o gba ta bi o gba. (Ni gbogbo Ona, inclusive of all you mentioned).

So, so ara eee, ki Olorun so.

Ma lo kan idin ninu iyo. Mi oni so ju be lo.

Alafia fun ee o.

O di gba. tongue
1 2 Reply

Kwankwaso, Amaechi, Others Bought Their Way To APC With N100m Each — BafarawaArms Deal: I Got N100m From Mu’azu, Not Yuguda – NwobodoBode George, Odili Got N100M Each From Dasuki In Arms Purchase Scam - Sahara Rep234

Femi Fani-kayode Gives First Son Igbo Name (Lotanna Fani-kayode)Tell Me What Happened While I Was Away - BuhariPHOTOS: Ondo APC Candidate,Rotimi Akeredolu Celebrates Sallah With Bisi Akande