₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,331,220 members, 8,449,201 topics. Date: Tuesday, 21 July 2026 at 12:48 PM

Toggle theme

Ogun Ti Afeere Buruku Kii Fii Fee Lunii - Culture - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureOgun Ti Afeere Buruku Kii Fii Fee Lunii (2408 Views)

1 Reply

Ogun Ti Afeere Buruku Kii Fii Fee Lunii by Laniretiawoagba(op): 11:53am On Mar 23, 2020
Ewe odundun, ewe rinrin, ewe koropo, erofo odo tii kigbe, omi igbin bonu kan, eeru oju aaro ao lo kini yii papo Mon arawon, ao pomo ose dudu, tabi ose Toba wuwa, ibase lux, ao bu ose naa wee, ati eniyan waa, AFEERE BURUKU koni feelu waa tabi igbona buruku, eniti obari ariidaju pee (coronavirous ) bamun enikan ni orile ede Nigeria, ko pee number mii matoju enina ni irorun, kosi iru igbona tabi Arun naa lode aye ,08037492173.
Re: Ogun Ti Afeere Buruku Kii Fii Fee Lunii by adigun98(m): 3:21pm On May 26, 2020
Laniretiawoagba:
Ewe odundun, ewe rinrin, ewe koropo, erofo odo tii kigbe, omi igbin bonu kan, eeru oju aaro ao lo kini yii papo Mon arawon, ao pomo ose dudu, tabi ose Toba wuwa, ibase lux, ao bu ose naa wee, ati eniyan waa, AFEERE BURUKU koni feelu waa tabi igbona buruku, eniti obari ariidaju pee (coronavirous ) bamun enikan ni orile ede Nigeria, ko pee number mii matoju enina ni irorun, kosi iru igbona tabi Arun naa lode aye ,08037492173.
Aboru aboye
Baba ejowo shele bami she oruka Ashe Yahoo ti mole fi ma ba awon client mi soro ti won o sini ko ohun mi
1 Reply

Ogun Ti Afi Manjeun ( Bibo AsiriOgun Ti Afi Nri Owo Ni IrorunOgun Ti Afi Nwe Osi Kuro Lara , Ti Kofini Bani Wo Inu Odun Tuntun234

Is Tattooing The Body Evil In Nigeria?FACIAL TATTOOS: The Tribal Female Rite In Papau New GuineIntriguing African Proverbs.