₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,327,144 members, 8,429,519 topics. Date: Friday, 19 June 2026 at 04:15 AM

Toggle theme

Osole Nla Todaju - Culture - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureOsole Nla Todaju (1740 Views)

1 Reply (Go Down)

Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 7:33am On Feb 04, 2021
Osole je ogun ti ona fi Nla fun eniyan. Ti eniyan ba ri Osole toto Osole to tona Darin, Gbogbo nkan yio dabi igba wipe oluwa re Mose ju awon yoku lo. Nitori wipe, Gbogbo nkan ni yio ma dara, Owo yio maa wole fun ni ni Gbogbo ona ti ao si ma gbe nkan mere mere se bi ilekiko, moto Rira, opolopo ona ni yio sii. Sugbon Orisirisi ni Osole, nitori wipe tako-tabo ni ile aiye, bee naa ni Osole. Osole tutu wa,oso ako naa si wa pelu. Osole ti emi nsoro nipa re Yi je eleyi ti koni ipalara kankan, beeni Kosi ni ewu tabi alebu kankan. Osole Yi sise pupo tosi daju. Eleyi yato si ogun Owo gedegbe. Sugbon Osole Yi naa wo ni ati se re. Fun alaye ati ibeere, e le kan simi Lori whatsapp number mi : 08108458712 tabi email address mi : ogunfrayo@yahoo.com.
Ewe nje Ogun todaju si wa bi ti Atijo.
Re: Osole Nla Todaju by Pearlyakin(m): 12:03pm On Feb 04, 2021
Ogun owo ni osole na, won si man lo eya ara eniyan lati shey, abi shey mo puro.
Re: Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 1:45pm On Feb 04, 2021
Emi o mo Osole toni Eya ara eniyan ninu o. Emi o de daruko ogun Owo rara. Lilo Eya ara eniyan lodi si ofin ijoba. Ewe ati egbo ni mo nsoro nipa re. IMO lo jantirere ni.
Re: Osole Nla Todaju by Pearlyakin(m): 2:06am On Feb 05, 2021
ogunfrayo:
Emi o mo Osole toni Eya ara eniyan ninu o. Emi o de daruko ogun Owo rara. Lilo Eya ara eniyan lodi si ofin ijoba. Ewe ati egbo ni mo nsoro nipa re. IMO lo jantirere ni.
Okay, kosi wahala oluwa yo ma wa pelu yin. E jhur e ma bawa so fun awon onishegun ati babalawo to ku ki won jawo ninu ogun owo shishe fun awon odo orile-ede naijeria.
Re: Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 4:14am On Feb 06, 2021
Eledumare yio ko wo inu awon odo orilede yi
ati awon Odaju tiwon pe arawon ni babalawo. Sugbon ki gbogbo eniyan ni itelorun ati opolopo suuru, nitori wipe bintin laye.
Pearlyakin:
Okay, kosi wahala oluwa yo ma wa pelu yin. E jhur e ma bawa so fun awon onishegun ati babalawo to ku ki won jawo ninu ogun owo shishe fun awon odo orile-ede naijeria.
1 Reply

Ogun Osole To N Sise AjeOsole Gbewa 15 Million Tabi 9million.Osole Fun Eniti O Nse Yahoo234

NIGERIAN Longest Reigning Monarch: HRH Oba Aladesuru, Onigede Of Igede Ekiti MarSolved!!What If The West Decides To Bring Back Slave Trade Era???