₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,329,767 members, 8,442,158 topics. Date: Thursday, 09 July 2026 at 05:13 PM

Toggle theme

Ilera - Health - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralHealthIlera (529 Views)

1 Reply

Ilera by AkoduAkeem(op): 7:59am On Nov 04, 2021
OJULOWO EWE ATI EGBO FUN ARA RIRO,AWOKA ATI LAKUREGBE
1) Ororo to n jade lati ara ewe ati itakun (stem) ara igi tomato.A o ma fi wo/ pa(rub)awon ibi to n ro wa.
2)A o lo awon nkan wonyii kuna aloe vera,ginger ( eni ba ni aisan ogbe inu/ ulcer ko lo ginger ni iwonba tabi ko ma lo rara) ayu(garlic),kanafuru (clove).A o se bi ogi A o tun lo kanafuru ogun miran mo iyi ta ti se.yii A o fi sile fun wakati marun si meje.
A o ma mu ife( cup) kekere kan laaro ati lale
3) Sise epo ahun ni mimu
4)A o wa egbo sapo ati egbo aidan
A o maa mu ilaji ife kan laaro ati lale.
5)Sise epo ori ope oyinbo(pineapple) bi tea.
6) A o ge ayu tabi alubosa tabi ewe bomubomu si wewe, a o to won si atelese, ao wo ibose wa (socks) le lori di aaro ojo keji.
7) Ki a fi awon ororo bi olive oil (eyi ti won ko extra virgin) si lara lo dara ju, tabi adi agbon, tabi black seeds oil.Ki a fi pa awon oke ese wa ati atelese wa daada ati awon ibi to n ro wa nigbogbo igba, agaga ki a to sun lale
7)Ewe osepotu to po die, a o lo alubosa nla meta mo ,A o se daada lori ina.A o maa mu ife kan leemeji lojumo
AKIYESI PATAKI
A.le lo awon ti a o fi para pelu awon ti ao fi sinu ibose Sun pelu okan ninu eyikeyi awon ti a daruko wonyi.
Egbo sapo ati egbo aidan dara gan fun enikeni ti aisan sangunsangun tabi awoka ti wo lara gan
Ki a lo eyikeyi ti a ba ri ninu awon.nkan wonyi titi alaafia ma fi pade de sara wa .Ki a ma se lo gbogbo won papo lekan naa.
Olohun Oba a lo won lati da alaafia pada si ara wa.Amin
1 Reply

Ilera Eko: Lagosians Groan Under Heavy Medical Bills Despite Insurance CoverIlera Eko: Affordable Health Insurance In Lagos You Need To Know AboutIlera Eko - Lagos Health Insurance Scheme234

RE: Black Soot And InfertilityHeavy Blacksoot 8:15AM At Obiwali Road, Port Harcourt.Treat As Urgent