keyguy59: ¤OOGUN OHUNMO¤ Ao wa odidin eiye kaaro kan, ori olongbo kan, egungun eiye akala, eja ojiji kan, odindi imo ope kan,odindi atare kan, ikodidere meta,ao jo Gbogbo re po ao fi sin gbere kan si igba aya wa, ao fi iyoku je Ogede omini pupa, kosi ohun kan ti o ma sapamo siwa koda won a tunma kowa ni OGUN loju orun wa (Oju Ala) pelu. BI OKO OKUNRIN BA NWALE NI IBAPADE OBINRIN Ao wa egbo Ajara, ao ge keke sinu igo kan, ao fo eyin adie ibile 7 si, ao da opolopo omi agbon si, lehin ojo keta ao ma Mun. zaudi mr copy &paste ise onmo yen oye ki o le refrence ayokomi 1010 toti copy e wa. |