ALIUDAVID's Posts
Nairaland Forum › ALIUDAVID's Profile › ALIUDAVID's Posts
1 2 (of 2 pages)
EKALE gbogbo ile, baba health first ejo oruko wo ni won tun pe ewe IYALODE
iba agbagba iba eyin to laye. |
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni
ogun arobi todaju(BACK TO
SENDER) ko ju sita fun afani gbogbo
wa... Iba agbagba iba eyin to laye.. |
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni
ogun arobi todaju(BACK TO SENDER) ko ju sita fun afani
gbogbo wa... Iba agbagba iba eyin to
laye.. |
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni ogun arobi todaju ko ju sita fun afani gbogbo wa... Iba agbagba iba eyin to laye.. |
OmoOsanyin:baba mi o ri esi yen boya e send email yin si aliudavidodunayo@gmail.com isese agbewa iba agba agba o. |
Baba omoosanyin ekale o moti send mail si email ti efi sita sugbon mi otit ri esi baba ebami check e, isese agbewa o...iba agbagba iba eyin to laye.. |
IDENA ABIKU Akerengbe to fo sona odo. Igi oku ope, Eku ti olongbo jeku, Odindin atare kan, Ewe jokoje (201), Ewe rekureku (201), Ao jo po, ao fi sin gbere yi orikerike ara omo na Ofo re- isinku orun dehin lehin odo, ojo ti akerengbe ba fo ni dehin lehin odo, olongbo ki sala ko je eku ana.. Odaju omona koni kumo. Iba eyin agbagba, iba eyin to laye.. |
ayokomi1010:'.. baba se osole yii ko le pawa lara tabi omo wa tabi ebi wa, se ko de tuni ewo... ese ise se agbewa. igba eyin agbagba. |
EYONU AWON AGBA ATI APAMOWO OWO.. Ikoide meta, Alanbere meta, Odidin atare meta, Ao jo won po, ao fi sin gbere yii orun owo wa mejeeji, ao po eyi ti o ku mo ose dudu ao ma fi we... OGUN ATUDE TODAJU... Ewe tude, Egbo tude, Odindin atare, Ao jo po, ao lo kuna dada ao ma fi epo pupa lo. Iba eyin agbagba iba eyin to laye.. |
Baba wa ayomikun ati eyin
agbagba lori itakun yi, ejo ti e ba ni
atupa aye(lantern) ejo efun wa, aye
ko ni pa atupa wa ase... Iba eyin to
laye iba agbagba.. |
Ago onile
Baba wa ayomikun ati eyin agbagba lori itakun yi, ejo ti e ba ni atupa
aye(lantern) ejo efun wa, aye ko ni pa atupa
wa ase... Iba eyin to laye iba
agbagba.. |
Ekale baba, asiku odun emi wa ase opo re laye..
Iba eyin agbagba lori ikan ni yi.
Baba ejo ti e ba ni atupa aye ejo efun wa, aye ko ni pa atupa wa ase...
Iba eyin to laye iba agbagba.. |
OGUN ISE WIWA Oga gbibe, Ile eiye aro, Ewe igi ti eye aro ko ile si, Gbongbo igi ti eye aro ko ile si, Odindin atare kan, ao jo gbogbo re po ao wa da si inu ado ijamo, Ofo re: ire loni ki e fi ire owo wa mi ri, aro loni ki ire owo ro mo mi, aki fi alagemo si le ki atun bo orisa mi ran, atare kin kere ko ma le gba inu oko... Ale LO pelu otin,eko tutu.. Odaju o IBA EYIN AGBAGBA IBA EYIN TO NI AYE. |
baba Bi oromi ko ba de ye yin dada nje onmo toraye rorun was, toba wa nje elefi sanuwa Lori Ikani tawayi IBA AGBA, ISESE AGBEWA. |
Baba efun wa ni ogun (AWORAN)
tabi (OHUMO) ti Afin wo inkan ATI
(ATUPA-AYE) iba eyin agbagba |
Baba efun wa ni ogun (AWORAN)
tabi (OHUMO) ti Afin wo inkan ATI
(ATUPA-AYE) iba eyin agbagba |
Baba o ejo efi email tabi phone number yin sita.. Baba efun wa ni ogun (AWORAN) tabi (OHUMO) ti Afin wo inkan ATI (ATUPA-AYE) iba eyin agbagba, iba aye. |
Ago onile, baba healthfirst ati baba kadunasouth, ejo efun mi ni ogun catach
ton fa aya(heart),oju(eye) ati imu(nose) didun ti
aba ti sin tan...
iba eyin agbagba, ao ni fi inra logba. |
Ekale ni ile, ejo talo ni ogun catach ton fa aya(heart),oju ati imu didun ti aba ti sin tan... iba eyin agbagba, ao ni fi inra logba. |
OGUN IFERAN FUN ENIKENI TO DAJU. Awo ewure dudu, Irun abe, Ewe amunimuye, Odidi atare kan, Ekanna owo(10) ati ese(10), Iru ipenpeju eniyen die, Irun ori die.. Ao jo gbogbo re po ao ma fi sinu ounje tabi obe die fun eni naa, ti o ba ti je yio nife re.. Odaju Iba eyin agbagba, aye mujuba. |
OSE ILE TUTU FUN OMODE.... Ewo osan wewe, eru, adin, egbo efo yanrin ao gun mo ose dudu, ao ma fi we omo na. OGUN TI OWO ATI ESE OMO BA NWU.. Egbo tude, egbo ogano, eso pandoro. Ao gesi wewe ao ko si inu igo, ao da oti ibile odi mimu, 3 times loju mo OGUN KI OMODE TI KO LE SORO BA LE SORO... Ori odidere, eran owawa, ewe ela, ikoko titun, ao da ni agbo ao ma fun omode na mu,yi soro OGUN EHIN OMODE.. ki omode le wu eyin ni irorun, rugudu ori ogede wewe ao gun mo ose ao ma fi we omo naa.. OGUN OMO TON RU TON GBE... Adin, eeru alamo, alubosa elewe,kanfura pelebe, osan tanjarin, Ao fi se agbo omo naa a mamu atun mafi we omo na. |
Ogun eda ibule tabi oro... Egbo ajekobale, ewe bomubomu, obi 3, kahun die, eyo atare 3, ewe patanmo.. Ao gun gbogbo re po ao fi eko tutu lo. |
IBA IYAMI OSORONGA
ya mi osooringa.
Afin'jú eye.
A pa má wa a igún.
Onníwowó adó.
Orú mo l'óogun danu
Olçogbo dçudçu oro Olçokiki orun
A jé do tutú má bi
Obinrin dúdú regi régi, eyí ti i lo nigba oja ba tu
Da'se d'epenu ti í gbe ni mi bí kalokalo
Ojiji firí
Afé gégé niyeé, A ró igba aso má ba'le
Eléyin'jú egé, eye ní more
a-je-apa-je-orí, j'ebo-j ohun, a ti inú orooro
je'fun
O we nínu omi saló saló
Ode t'apó y' oró, arinimoja t'apó yoogun Eyin ebiti ká wo s'eyin s'oro
A ba l'ori igi iróko má ye
Oró gogoro l¡oko olóko
Oníbanté pelejá ti í bá ni ja lái fowo kan ni
Ológbo dúdú etí oja
Ese a b'irun golo gilo , Ají ká igboro, a rin ka igboro
Ejí ní kutu f'omi ogboro bó ju
Ti a bá pe'ri okoni, aá fi ida na'le
Iba tó tó tó |
IBA EYIN IYAMI OSORONGA. Ilè mopue o ! Ìyàmì Òsòróngà Mopue o ! Òdu-Logboje Ibá o ! Ibá Òsa-iyeku kibí odu Ìyàmì Òsòróngà Mojubá Obinrin Lode Olo Gèlèdè Ibà Ìyàmì o ! Ohun abáwi fun Agbà Ni agbà Ngbo Ohun awí fun Agbà Ni agbà Ngbá Ohun timowí loníjé osé Ohun mofé kose loní Je kori be e Ní orunkò éhiyn Ìyàmì Òsòróngà Olo hun Òla ! Olo kun Òla ! Ójó ojú ómó , baféfó Aki gbe pue Òòrúnmìlà Ko gbehun Agbe Asè o ! |
kadunasouth:baba ki lo nje 'imi ojo' se ti eniyan ni. |
Oriki Iyami
Iba Olodunmare
Iba Akoda
Iba Aseda
Iba Esu Lalu Ogiri Oko Iba Ogun Lakaiye
Iba Sango Olukoso Lalu
Iba Osun Ramu Ofide Wemo
Iba Eyin Iya mi o
Eyin Lajapa Jori O
Eyin Latifun Joronro Obalanta Omi tutu ni o temu Eja Bo
Oro tutu ni o tenu mi bo
Ki irawo Mi ma rele
Giga Giga Lan Bojo
Oke Oke Lolawa Yio ma re
Oke Oke Lolawa Iyo ma re Eyin Iya Eni Ki ma Su Sepo
Mo su sepo E O bami Wi Rara
Eni Kin Ma To Sala
Mo to Sala E O Ba Mi Wi Rara
Eni kin mafi Ikodide nudi
Mo fi ikodide nudi e o bami wi rara Eyin Iya Ke Je O ju Mi Se
Ase ti Eledunmare
Olodunmare Ase |
ERO ADAAJINA TABI TI ENIYAN BA TE OGUN MOLE. Ti o ba wu ni, ao wa igbe abo ewure ao po pelu ori, a o mafi ra ibi ti o wu. fun egbo ti ko jina, ao sa igbe ewure naa ti yio gbe ao ma ku si oju egbo naa. MADARIKAN ao fa irun ori wa ti yio dan, ao gbe ile(ground)koto, ao da irun naa si, ao wa yaa igbe le lori, ao fi odindin atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori, o kere sugbon o daju. IBA EYIN AGBAGBA, IBA EYIN TO LAYE |
ERO MAGUN (THUNDERBOOT) Ifun aja, igba eyo atare(200), igba obi pupa(200), igba obi ifin(200). A o gun po a o sa yio gbe, a o fi ran onde tabi igbadi si idi wa.. Ogun ti obirin ba nse isekuse.. Ewe ewura, ao fi nu oko nigbati a ba ba obinrin na lo po tan, ao wa odindin eko kan, ao gbo ewe ewura yen si omi to mo ti kopo ao yo omi re, ao fi foko mu ati obinrin yen... Ti obirin yen bati ba okunrin mi lo po yi bi si okunrin yen lara. |
Eku dede asiko yii, baba efun wa ni (ogun atupa aye) atupa wa ko ni ku o, ati (awo tabi digi aye) ti won fin woni. mo se iba eyin agbagba ati eyin to ni ile aye. |
1 2 (of 2 pages)