Autoboy20's Posts
Nairaland Forum › Autoboy20's Profile › Autoboy20's Posts
1 (of 1 pages)
Baba e jowo e salaye funmi, bi won ba so wipe ki eniyan ri ogun mole fun ojo meje, ti eni naa wa ri mole ni ojo monday, ojo wo ni yio lo yo ogun na,,,,, IBERE KEJI: Ti eniyan ba fe ri eyin adie mole se ao fi eyin na sinu ora(nylon) ka to ri mole abi a ko ma ju si inu iho leyin ti ati pelo sinu re tan,, baba e jowo e salaye funmi. |
baba mo dupe lowo yin gan |
Eseun baba, se mo le ri ata ile na ra ni odo awon elewe omo? |
e se gan mr. emmyjahzy, sugbon ejowo e se alaye funmi lekunrere bi mo se ma lo ogun yi, se ma po igbe adie na mo tooth paste ni abi bawo, ejowo e salaye funmi lekunrere |
baba e dakun, e fun wa ni ogun bi enu eniyan ba n run |
baba ejo kini eyan to sanra ju lelo ti yo fi jo |
Baba ejo kini eyan lelo ti enu eniyab ba n run bi enipe ko n fo enu |
1 (of 1 pages)