BABAODE's Posts
Nairaland Forum › BABAODE's Profile › BABAODE's Posts
1 (of 1 pages)
Ise yi dara gan ni,ti obinrin ti nse nkan osu o bati debe rara, kosi wahala kankan(no repercusion) sugbon ewu wafun eni to se ogun owo na ti obinrin to nse nkan bati debe. |
OGUN OWO NLA TODAJU-Bi awon era ti ma nbo ounje beni ogun yiri. Ori oka kan,ori ere kan,ori eiye osin kan,owo osi eran aluki,(........),(........),odidi eiye etu kan,awo ekun die,iye agbe mewa,iye aluko mewa,ikoride mewa,(........),(........),eiyele funfun meji,iyanrin okun ati ti osa,ileke ifa,abeere lopolopo,ose dudu lopolopo,ao ko gbogbo re si inu odo, ao si gbe owo eyo(aje)nla kan le lori, ao gun gbogbo re papo, ao ko sinu awo fun fun olomori kan. ao fi obuko kan se sara fun ose yi, Aso funfun lao mofi bora sun, ao mo we ose na lemeji lososu. EWO RE:Obinrin ko gbodo de ibiti osena bawa................Gbogbo iseyi ko ni mofi sita o,sugbon enito ba nife ati gba eyi toku ko pemi sori number mi. 08063121300 |
1 (of 1 pages)