Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,916 members, 7,863,200 topics. Date: Monday, 17 June 2024 at 12:57 PM

Beware16's Posts

Nairaland Forum / Beware16's Profile / Beware16's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by beware16: 8:42am On Dec 02, 2016
Moki Gbogbo Eyin Aworo Sasa O,amaaju Yin Se O.
Ejowo Mofe Imoran Ati Ohun Ti Mole Se Fun Iranse binrin Yii Ni O, Oti Bi Omo Kan Lati Bi Odun Mefa Sehin Bai,ise Abe Ni Won Se Fun,sugbon Lati Igba Naa Lo Tinwa Ki Ohun Loyun Sugbon Tiko Duro. Nigbamiran Toba Dabi Pe Nkan Fe Duro Si Lara,inu Atun Dede Mu,inu Re Amakun Bi Igbati Eniyan Ba nso,ti Obati Le Ri Bayen,oma Rin Nkan Osu Re Niyen,otilo Orisirisi Ogun Aran,ifibe Ati bebelo Sugbon Kosi Iyipada,ejowo Kini Kia Se? Ewe Amaaje O.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 6:23pm On Nov 24, 2016
ayokomi1010:
beni ajegun Miran wa
Ejowo Sir, Efun Wa Ni Ajegun Miran. Baba Ayokomi
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 7:47am On Nov 24, 2016
ayokomi1010:
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o.

Eku Ise O Baba Eledua Amaa Fun Yin Se O,ase.
Ejowo Baba Efun Wa Ni Ogun Ifibe Obinrin Todaju Atipe Ti Ara Eniyan Ba Dede Nfala Lojojumo Ti O Nta Eniyen Bi Wipe Won Naa Eniyen, Ejowo Ki Lale Sesi. Ejowo Ebami Wa Solution Si, Isese Se Agbe Wa Oooo.
Culture / Re: .. by beware16: 2:23pm On Nov 14, 2016
Moki Gbogbo Awo Patapata Ewe Amaje O, Ejowo Ise Wo Ni Alelo Ti Won Ba Ran Ofa Sini Lati Oju Orun. Oju Oni Tiwa O.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 10:09am On Nov 11, 2016
ayokomi1010:
oruka bi meta tabi Meje lama lo fun Ogun na

Eku Ise,eledua Atiyin Lehin,ase. Ejowo Kini Ama Fi Adie Ye se Ti Abati Ko Oruka Kuro Ninu E Tan, Se Ale Je Abi Kaju Danu. Ati Pe Ti Aba Fa Ogun Yen Ni Emeta Toba Ku Sinu Omori Isaasun Yen Se Koni Si Nkankan Ati Pe Se Ka Fo Omori Ikoko Yeni Abi Asi Le Pada Lo.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 6:57am On Nov 11, 2016
Eku Ise Opplo O, Eledua Ama Fun Yin Se, Amin. Ejowo Sir, Kini Mole Se Fun Omobinrin Yii, Oti Bi Omokan Tele Botile Jepe Ise Abe Ni Won Se Fun, Sugbon Lati Igba Naa Loti Ni Idaduro, Lati Bi Odun Meje Bayi. Otomi Sona Eyin Awo. Isese Agbewa O.Ase

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 10
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.