Bostilo's Posts
Nairaland Forum › Bostilo's Profile › Bostilo's Posts
1 (of 1 pages)
Titiloye247:Am interested too. Numeber mi niyi- 07065707337 |
E kale sir o. E jowo kini mole lo fun enitojewipe oti loma nfi gbogbo ojo aye re mu. E jowo egbami o egbon mi kotoju iyawo ati awon omo e. Oti lonfi gbogbo ojo aye won mu. Please help Me o. |
E kasan o baba healthfirst. E jowo monilo email address yin tabi nomber yin mofe ba ifa ni gbolohun. My own email is(abosedenaomi@gmail.com) please baba get back to me |
E jowo monilo ogun ti omode toban jeun daada yi o fi sanra e dakun esanu mi o. Ewe a ma je o |
E jowo kini eni tikoba kin je eja oro lelo dipo? healthFirst: |
Ejowo kini ogun teyan lelo fun oko eniyan ti kofi nile se sina mo. E gbami o tori arun karun towa nita. Ewe a ma je funyin sir o. Pls am waitin 4 my reply. |
Ejowo kini ogun teyan lelo fun oko eniyan ti kofi nile se sina mo. E gbami o tori arun karun towa nita. Ewe a ma je funyin sir o. |
kadunasouth:Ogberi nimi koye mi raara. Esanu mi |
Modupe lopolopo sir. E jowo baba ogberi ni mi mio mo biwon se te ifa. Ejowo esanu mi sir. Kini mole se bayi toriwipe ogun promise and fail yi bami ja gidigan ni o kadunasouth: |
ewe a maa je ooooo....ejowo ogun wo ni eyan fi maa ri anu gba. (Ogun promise and fail) a maa sese fun yin o. |
Ekaaro o baba kadunasouth ejowo mo nilo nomba ti eniyan le peyin si esanu mi ejowo (abosedenaomi@gmail.com) that's my email address. Lionhearted: |
Ekaaro o baba health ati baba kadunasouth ejowo month nilo nomba ti eniyan le peyin si esanu mi ejowo (abosedenaomi@gmail.com) that's my email address. ![]() |
1 (of 1 pages)
Ekaaro o baba health ati baba kadunasouth ejowo month nilo nomba ti eniyan le peyin si esanu mi ejowo (abosedenaomi@gmail.com) that's my email address.