Bwayomide's Posts
Nairaland Forum › Bwayomide's Profile › Bwayomide's Posts
1 (of 1 pages)
eejo baba,se ao ka omo ileke itun ati ifa ye ni woro kankan ti yio fi pe merindinlogun ni tabi a o ka ni eyokan bi won se di si ara igi re titi ti yio fi pe merindinlogun,ese baba,oodua a gbe wa ooo. |
ki ni je abaweku?ajuwase ooo. |
mo ki gbogbo ile ooo,olohun a ran gbogbo wa lowo ooo,e jo mo nfe ogun ti eyan to nwa ise le fi ri ise,ooodua agbewa ooo. |
baba e jo kini oruko miran ti a le pe ewe eeyo,oodua agbewa ooo,ase |
mo ki eyin baba mejeji ni kiki ola,olohun a ma ranyin se ooo,imo yin ko ni dobaa lola olohun,ejoo se {ewe oyo} yi ni a npe ni {ewe ayoyo tabi ewedu}. |
adagba yowokowo olohun o ni fi si inu oro yin baba,mo dupe fun idahun yin si ibere mi,mo dupe lowo olohun ati eyin baba mejeji ti e ntowa sonan,mo nri iyato ninu aye mi lowolowo,e jo ohun ti o ku fun mi ni alanu ati aranse,e jo baba,inu mi adun gidigidi ti e ba le fun mi ni ogun ti eeyan fi nri alanu.e sehun baba.olohun a ran yin lowo ooooooo. |
eejo baba,ki ni oruko miran ti a npe ewe firiganmu?olohun a ran yin se oooooo. |
1 (of 1 pages)