Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,351 members, 7,860,912 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 06:43 PM

Despiryer's Posts

Nairaland Forum / Despiryer's Profile / Despiryer's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Despiryer: 5:34am On Jan 28, 2017
Lionhearted:


E lo ye email yin wo. Eseun.
mo nilo ogun ti oko olomokunrin file tobi daada
Culture / Re: .. by Despiryer: 5:03am On Jan 28, 2017
keyguy59:
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIO
SI TOBI" ao
wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu
omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao
yo igbin naa pada, ao
fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo
gbogbo ara oko wa. oko wa yojade
ti yio si gun dada.
baba se igbin to ba ni kini funfun loju?
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Despiryer: 3:58am On Jan 28, 2017
kadunasouth:
Eyonu Aye
Eko kolobo ao tu ewe na lori ao fi oga bo ninu ao fi odidi atare kan bo legbe ao fi ewe na cover re ao we lowu dudu ati funfun ao jo ao lo kuna dada ao ma fi oyin la lararo pelu gbolounyi
Asiri eko kitu loju ewe, abati alagemo bada lorisa oke gba, atare ki idi tire labo ki asiri mi bo lonakona ki gbogbo omo araye yonu simi owu dudu ati owu funfun wanki jarawon niyan ki gbogbo aye ma femi
baba mo nilo oogun iferan to daju

1 Like

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.