Culture › Re: .. by FORTHNIGHT(f): 9:50am On Nov 10, 2017 |
Midumighty: ewe rere ni ede adugbo ni u ti won fi si THANKS |
Culture › Re: .. by FORTHNIGHT(f): 12:40pm On Nov 07, 2017 |
Nudewhenu31: Eku agba o, Baba health, e pe, e gbo, Ororun Oba ayeraye, Oba orun yio wa pelu yin, ejo eranmi lowo fun oruko mi ti yoruba npe ewe Urere, moti bere lowo awon elewe omo, sugbon wan ni awon ko mo ewe to n je be, mo fe fi se ise yin kan te fi si ta ni, eyi ti eni ama gun ewe Urere yen ati Abamoda papo, a wa fun omi re sinu adin, fun arun oju ara obinrin. Eseun gan an ni EJO KINI ORUKO MIRAN FUN EWE URERE? |
Culture › Re: .. by FORTHNIGHT(f): 12:23pm On Nov 07, 2017 |
baba healthfirst ati baba kadunasouth ejowo shey ogun wa ti o le mu oko olomokurin to kere tobi dada?baba healthfirst ati baba kadunasouth ejowo shey ogun wa ti o le mu oko olomokurin to kere tobi dada? EKU ISE TAKUNTAKUN LORI FORAN YI. BABA EJO SIR EFUN WA NI OGUN IWOSAN FUN ENITI AYE FI AISAN PAMO SI LARA... ESE SIR |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by FORTHNIGHT(f): 11:29am On Nov 07, 2017 |
ayokomi1010: OGUN IWOSAN AYE ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo. EJO SIR E BAMI SALAYE BI ASE MA FA OGUN YAN SI ENU AKUKO YEN, TORI MO TI LO OGUN OFA SI ARA MI TITI PELU OGUN OYINBO SIBE KO SI IYATO, NKAN MA NRIN KAKIRI ARA MI |
Culture › Re: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by FORTHNIGHT(f): 11:21am On Nov 07, 2017 |
OK, AGREED |