Hamykaz's Posts
Nairaland Forum › Hamykaz's Profile › Hamykaz's Posts
1 (of 1 pages)
Aku Dede asiko yii ooo, eku ogbon ooo....ejowo e fun wa ni asiri (ogun) ti eniyan fi ri alaanu....eyi ti omo araye fin se eyan laanu gidi....ewe a maa je oooo |
ewe a maa he o, ejowo kinni WO n pe ni, awure owo agboojo, nitoriwipe omo ile eko giga ni mi, a si to fe wole sugbon kosi agbara fun a won obi mi lati san owo ile iwe mi, ejowo mo ni lo Ogun ti alaanu fi n was eniyan ri, ipari OSU yii ni a maa wole, owo naa si din die ni egberun lona ogorun,#100,000 |
eku asiko yii ooo, ejowo iko asthma maa n se mi, ogun wo ni mo le lo....ewe a maa je ooo |
ewe a maa je ooooo....ejowo ogun wo ni eyan fi maa san gbese ti eyan ba je |
1 (of 1 pages)