Culture › Re: .. by ifasheun: 2:53pm On Aug 17, 2016 |
ogboliagba: Baba eku agba, ewe koni ko ohun yin o, e jowo e Funmi ni oogun ti tan (IMULE AWON AGBA ) number mi niyi 08066161217. Ella-boru, Ella-boye o Emi ko ni imule agba yi lowo o Baba wa Ifankaleluya ni won ni lowo, e le kan si won lori emaili won. Ifa o gbe wa o. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 10:54am On Jul 31, 2016 |
Ifankaleluya: Pelu ogo-olohun, ifa o tena si o ninu.
Ifa ni; Ahere nla aboju yau
Giri-giri ese leyin kule
Ona aboju tiun
Awon ni won sefa fun orunmila
Nijo ti baba n lore kofa-mofa,ko ogun mo ogun
Ko atenuso mora won
Won ni bawo ni o se ma gbo
O ni ogbo loni ki oun ma gbo gbogbo oun ti won ba n ko oun
Imo loni ki oun ma mo sikun
Iye ataa kiiku mo ata ninu
Iye obi kiiku mo obi ninu
Iye orogbo kiiku mo orogbo ninu
Iye o ni ku mo ninu
Gbogbo ifa ti o ba ko ni yio ma wo sikun re. Ase Ase Ase. Eseun modupe, ao ma ri yin ba. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 10:50am On Jul 31, 2016 |
Legendbaba1: BAWO NI ASE MASE IGBIN YE SE AFO NI KI ATO FI SI INU OSE TABI NI ODINDIN NI PELU KARAWUN RE Eo ti igbin na bo ose yen ni arin ni, eo ti bo ti yio kan isale isasun naa, aye(life) ni eo ti igbin na bo ose yen. Ki o to di ojo keeje ti e o bere sini we ose naa, igbin yen ati Ku si be. Ki e to we ose na tan, eo ma ri apere loju ala(dream). |
Culture › Re: .. by ifasheun: 10:58am On Jul 27, 2016 |
Ifankaleluya: EBE AWON AGBA
A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.
Abori, Aboye, Abo-sise! Ose Ebe Awon Agba yi ni mo nlo lowo, Apere ti mo ti ri so far ni wipe, 1. Awon olopa nle mi ni oju orun, mo si ri iya kan ni ojiji( sudenly) oni ki ntele owun wipe awon olopa(police) na ko le fi mi se nkan kan, 2. Awon omo iya mi ti won ti nbami ja lati ojo pipe nfi owo ranse simi wipe ki ebi o mo pami nitori ipe mio ni ise lowo(hand). TESTEDD CONFITMED, Ifankaleluya iba re oo. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 2:04am On Jul 26, 2016*. Modified: 10:49am On Jul 27, 2016 |
Zalam5: Alaye tie se lori ogun yii ko BA arawon mun rarara,e gbiyonju kir tun alaye yi se leekan sii@ifa kaleluya!!! Alaye tie se lori ogun yii ko BA arawon mun rarara,e gbiyonju kir tun alaye yi se leekan sii@ifa kaleluya!!! Alaye tie se lori ogun yii ko BA arawon mun rarara,e gbiyonju kir tun alaye yi se leekan sii@ifa kaleluya!!! |
Culture › Re: .. by ifasheun: 1:52am On Jul 26, 2016 |
Ifankaleluya: FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.
IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.
IFA YI JE AKO ATI ABO.
AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E.
IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.
SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.
1. IWE ASEYORI.
EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO. FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO. AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.
GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.
IKILO RE OOO OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.
2 IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.
NOTE;; TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.
ABORU,ABOYE,ABO-SISE. Mo ti dan ti akoko ti nse ti iwe na wo, mo si ri apere rere, awon eniyan nyonu si mi, even awon eniti mio mo ri ntami ni ore. Tested vere very ok. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 9:26pm On Jul 25, 2016 |
ifasheun: Eji Ogbe ni:
Otoototo, Oroororo Oto oto la njepa, oto oto la nje imumu loto loto la nfi olu esunsun senu oun ti ori ni ti ori, oun ti oori ni ti oori oun tori ntori la fi nf'oba ma'kin lode nranje k'oba le fi oun t'ori toori tani l'ore egbesan a dia fun ogoterere, ti nse awo re ilu gbendugbendu l'oke ehinwonran ogoteerere loruko a npe okunrin/oko ilu gbendugbendu la npe obirin/obo eyi amubo ibe, ire omo(child) loo je. Eji Ogbe kan na lo ni; Otoototo baba alawo olowo lo difa fun olowo(the rich) otoototo baba alawo oloro lo se ifa ijokan nni fun oloro(the wealthy) ka'je epa(groundnut) tan, ka' gbon owo s'awo poroporo OR kajepa tan, ka da epo re si igbo baba alawo olomo lo difa fun olomo olowo ku(die), owo e gbe oloro ku, oko oro e lo si orun(heaven) ero ipo, ero ofa aye olomo ni ko ni parun. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 9:15pm On Jul 25, 2016 |
ifasheun: Aboru, Aboye, Abo sise. Baba Ifankaleluya mo ki yin fun ise takuntakun ti e n se oo, Oba Adaniwaye a je ki epe fun wa o, ao si ma ri yin ba. Edakun iranlowoyin ni mo ntoro o Otipe ti mo ti ma nri arami(myself) ni atimole(cage) ni oju ala mi, koda ni igbami, mo ma nsun gidigan ni oju ala, ni igbami mo si ma nri arami ni ori akitan ti maa ti sun lo ni oju ala mi kan na, mo ti kirikiri, mo si ti gbinyanju titi sugbon ti mo ba fi owo(hand) mi tun nkan se, nise ni ma tun fi ese(leg) ba nkan na je. Ejowo nitori ti Olodumare se ele komi ni nkan ti mase lati fi bo ninu panmpe aye yi? Edakun mofe ki eran mi lowo, inu mi ibadun ti eba le ko mi ni oun ti mase nitori omo ikofa ni mo nse, osi damiloju wipe eminikan ko ni nbe ninu iru igbekun bayi lori feranyi. Ebe ni mo nbe yin o baba wa ifankaleluya. Eji Ogbe ni: Otoototo, Oroororo Oto oto la njepa, oto oto la nje imumu loto loto la nfi olu esunsun senu oun ti ori ni ti ori, oun ti oori ni ti oori oun tori ntori la fi nf'oba ma'kin lode nranje k'oba le fi oun t'ori toori tani l'ore egbesan a dia fun ogoterere, ti nse awo re ilu gbendugbendu l'oke ehinwonran ogoteerere loruko a npe okunrin/oko ilu gbendugbendu la npe obirin/obo eyi amubo ibe, ire omo(child) loo je. |
Culture › Re: .. by ifasheun: 8:52pm On Jul 25, 2016*. Modified: 11:03am On Jul 26, 2016 |
Ifankaleluya: IPESE TI A FI N TORO NKAN LOWO AWON AJE(OSA-MEJI)
Abodie dudu kan, ao pa eje re sinu awo abokadale, ao tu huhu re, ibose re ati tenu, ifun re ao jo papo. Ao te ebu yi ni osa-meji, ao fi iyere-osun pe ifa re ni ihoho loru, ao fi ebu yi fo eko-tutu mu, iyoku ebu yen ni ao da si iyoku adie yen ti a fi epo-pupa din lai fi omi kan adire yi lara ti ao si lo gbe si orita-meta
Ifa re: ipingun aje, Asanmimi ogun, obe ide lefi gun omo-olomo je, eje-eniyan lefi da omi-obe, nilawe odo le gbe pe, Adurogesin ni somobinrin ikej, aje mesan ti n be lalede orun, ori igi-gogoro orun leti ro waye, eni ta lo mo oruko yin bayi, mo ni emi lagbaja omo lagbaja ni, eni kin lode, mo ni nitori nkan bayi ni mo se pe yin ni ihoho ke wa siju anu yin wo mi, ke wa faso asiri yin bo mi lara, eni omode ki ridi osan ti fi pon, eni agbalagba ki ridi oru ti fi gan dudu, eewo ni, epo-gbigbona ki roju sun lailai, osa-meji sure tete ko lo sa ire ola bayi fun mi.
Fun imonran kan si ifankaleluya@gmail.com
Aboru, Aboye, Abo-sise Aboru, Aboye, Abo sise. Baba Ifankaleluya mo ki yin fun ise takuntakun ti e n se oo, Oba Adaniwaye a je ki epe fun wa o, ao si ma ri yin ba. Edakun iranlowoyin ni mo ntoro o Otipe ti mo ti ma nri arami(myself) ni atimole(cage) ni oju ala mi, koda ni igbami, mo ma nsun gidigan ni oju ala, ni igbami mo si ma nri arami ni ori akitan ti maa ti sun lo ni oju ala mi kan na, mo ti kirikiri, mo si ti gbinyanju titi sugbon ti mo ba fi owo(hand) mi tun nkan se, nise ni ma tun fi ese(leg) ba nkan na je. Ejowo nitori ti Olodumare se ele komi ni nkan ti mase lati fi bo ninu panmpe aye yi? Edakun mofe ki eran mi lowo, inu mi ibadun ti eba le ko mi ni oun ti mase nitori omo ikofa ni mo nse, osi damiloju wipe eminikan ko ni nbe ninu iru igbekun bayi lori feranyi. Ebe ni mo nbe yin o baba wa ifankaleluya. Email mi ni yi ; ifasheun11@gmail.com |