₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,743 members, 8,423,537 topics. Date: Tuesday, 09 June 2026 at 08:58 PM

Toggle theme

Ifatoki16's Posts

Nairaland ForumIfatoki16's ProfileIfatoki16's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by Ifatoki16: 5:42am On Jun 21, 2016
Ifankaleluya:
Mo ki gbogbo awa elesin ibile fun ayeye- odun OKE-ITASE ti a

ma n se ni ilu ILE-IFE ti, ti odun yi wa si ipari ni ana. Mecca ati

Jerusalem ti wa niyen, mo gbadura wipe emi wa yio se

opolopo re laye. Ase!

Ifa ni;

Isu ni fi ibi gbigbo sodun

Koko gbo ohun arira lale

Akere ni ikeyo, o gbo kuku ojo

O fo rere, fo rere si olohun

Adifa fun oye ti n rele ofun re sodun

Igba oye re ile ofun re sodun

A o jo-jo-jo(dance)

A o yo yo yo

A o feja san iyan

Ao si rera kebe.

Gbogbo awa ti a peju se odun yi, odun ayo ni ao ma se o!

Aboru, Aboye, Abo-sise!
..ASE O.Aboru Boye.
CultureRe: .. by Ifatoki16: 9:59am On Apr 30, 2016
Baaba mi Ifankaleluya,mo mo(know) wipe imule awon agba po,koda mo ti je orisirisi sugbon poo ju.mo ti je ti baba mi ti a nfi eko meta je ifa irosun oso lenu ona yara wa ni ihoho.sugbon koi ti to.nngo ba yin soro labe aso laipe.Ifa yio gbe yin,Orunmila yio gbe yin oo baba fun bi e se bami soro laipe yi.e ko fi oju kere mi.Mo dupe.
Ifankaleluya:
Omo baba-awo ifatoki, Imule awon agbalagba to tun lagbara ju iyen lo si wa. A ko mo ifa ni...Orunmila ni oko-oso ati Aje, so boya ka soro labe aso.
CultureRe: .. by Ifatoki16: 2:45pm On Apr 24, 2016
Baba mi Agbalagba oye.mo ti bere fun imule awon aje titi,sugbon o dabi e ko fe fun mi.mo kan sori mail yin,mo fi nomba ipe mi sile,sibe e ko tie wo ibiti mo wa.E joo mo fi orunmila beyin.ti mo ba seyin kie dara jimi.baba omo ni gbomo,irukere......09053297971 llcatz@yahoo.com
Ifankaleluya:
Fun awon ti won nilo Ifa imule awon aje yen ni pipe. E kan si mi lori e-mail yi; ifankaleluya@gmail.com. A si fi ranse si yin. Nko fe fi ifa yi si ori-afefe tan fun awon idi-kan. Ati wipe ifa yi ko se fi sere rara oooo. Iwo ti o ko bale dase fun ra re,ko ba dara ki o kan siwa ki a si bayin se.
NOTE
FUN IWADI LORI ORO AIYE RE, O LE KAN SIWA KI A SI BA O BI IFA(ELERI IPIN,ATUN ORI ENI TIO SUNHAN SE) LERE. ELEDUMARE YIO BA WA TO AYE WA OOO. To abala-esu!
CultureRe: .. by Ifatoki16: 8:56am On Apr 21, 2016
marv006:
Atupuru odo ni kose fi gunyan,
Atupuru ikoko ni won fa lokun danyin-danyin-danyin,
A dia fun Ori,
Ori wa nlo ode Ajalaye,
won ni ko sakaale ebo ni sise,
Ogbebo orubo,
Nje Awede we tie o mo,
Ella ifa, we Ori mi mo,
Ogede we tie o de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ara kii ni ogede koma de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ero woo ni ti igbin,
Ella ifa wa weri mi mo.

Ise keke kan nu fun awon ti ooye ye.
> E se oo baaba mi.Elaaarowa ooo @Ifatoki16 lo nki yin ooo. e jowo e fun mi ni email tabi nomba ipe yin. llcatz@yahoo.com 08144762240
CultureRe: .. by Ifatoki16: 8:38am On Apr 21, 2016
Ki e pe fun wa oo baba Ifankaleluya,ori ekerin niyi ti mo ti nkan si yin pe ki e joo fun mi ni ifa ti awon aje fi nfi ami igba si aya enito ba je ifa na.mo fi ipe aago mi sori ikanni yi ati email mi,e o dami lohun.ti mo ba seyin ki e dakun dabo e dari jinmi.Orunmila yio wa pelu yin o. llcatz@yahoo.com
CultureRe: .. by Ifatoki16: 1:13pm On Apr 16, 2016
Baaba mi Ifankaleluya.mo wari faye mo seba agba ooo.Ifatoki16 lo nkan si yin pe ke ma gbagbe mi,awon to laye ko ni gbagbe eyin na.ifa keji Imule awon Agba ti won nfi amin igba si aya wa ti mo bere lati ojo yi,eo ti fun mi.Se e nbinu simi ni? llcatz@yahoo.com
CultureRe: .. by Ifatoki16: 4:16pm On Apr 10, 2016
Baba mi agbalagba Ifankaleluya,e ma pe mo ba yin loye mope yin loruko,oruko la fi npoba alade.mo ti fi nomba ero ipe mi sori ibere mi tie ba fe ka soro labe aso. o nbe ninu o ku sikun.gbogbo nkan ko ni a le ma bere ni gbangba.Orunmila a gbe yin oo.
CultureRe: .. by Ifatoki16: 3:54pm On Apr 10, 2016
Baba Ifankaleluya,eku atunse ati agbaale wa lori ikanni yi.Ejoo emi Ifatoki16 bere fun imule awon aje ti won fi nfi ami igba si aya wa tie fi sita ti ko pe.mo bere ni ori email yin,sugbon e ko dami lohun lati igba na.tabi e nbinu simi ni.email mi ni eyi llcatz@yahoo.com
CultureRe: .. by Ifatoki16: 6:44am On Apr 08, 2016
Baba mi agbalagba Ifankaleluya,e jowo mo fi Orunmila beyin kie fun mi ni ise imule awon agba ti won fi nyo si wa loju orun fi ogun aye wa han wa yen kio pe.O fi tie sile gbo teni eleni, Olorun yio gbo tiyin na ooo.Ase. number mi 09053297971 @Ifatoki16

1 (of 1 pages)