Stats: 3,166,413 members, 7,864,831 topics. Date: Wednesday, 19 June 2024 at 07:50 AM |
Nairaland Forum / Ilaje43's Profile / Ilaje43's Posts
(1) (of 1 pages)
![]() |
Osinbajo 1 Saraki 0 |
![]() |
GAZZUZZ:Hello Gaz, just want to ask if you repair Mitsubishi? I have to do a general maintenance check, and change the shock absorber possibly. The steering needs to be checked as well, because it is over sensitive. |
![]() |
The smear campaign against Buhari in 2015 shows their fingers was in that elections. APC political consultants were probably more effective, and Goodluck's own Malheur played very well into the hands of APC too. |
![]() |
iamcapela: Dear Sirs, What modell of BB is that? |
![]() |
olasdot: Ola, bawo ni? Se o ti resolve wahala e lori bb e nipa IT-Policy? If not, it is possible to get it resolved. Wa nilo lati WIPE bb e ki o wa restore OS e pada. BB Desktop manager ko lo ma lo o. Programm kan wa ti won ng pe ni BBSAK http://www.bbsak.org/. Lo si site yen lati lo download e. Donationware ni, ko cost e ni Kobo. Oun ni ki o lo lati WIPE BB e back si original state laisi IT-Policy. Ka instruction bi o se le pa bb e re pelu bbask lori site won yen naa. Mo ni ireti wipe informeshon yi le je iranlowo die fun e. Ko je bi o ti je. |
![]() |
This article has really simplified the Nigerian scenario by comparing it with SEA, North Africa, and Latin America. How many of these countries are as diversed ethnically, culturally, mentally, religiously as Nigeria? The reason for the explosion in population are many fold, but the one that hardly get mentioned is the ethnic population competition. The author never thought about that. Somebody said Nigeria is not overcrowded, that may not be entirely true, because some areas are indeed already congested. Generally speaking, there is enough space in Nigeria. And to the solution of dividing Nigeria, that could work in some areas where there is nearly ethnical homogenity, or atleast there are no multiple majority ethnic groups as we have now. BTW, if Nigeria divides, the ascending nations would definitely be economically disproportionate. Some nations would have oil, some not. And no one can force them as sovereign nations to share their wealth with their improverished neighbours. |
![]() |
Gbawe, mo ma ro e ki o ye fun awon oponu wonyi lesi. Pupo ninu won ni kii rin irin ajo, ti won ko mo ibi kankan rara, sibesibe won a ma pariwo bi wipe awon lo mo nkan ti won nso ju. Gegebi owe Yoruba, won ni agba ofifo li ma ng pariwo ju. Jeki won maa wi, ma da awon omode wonyi lohun jare. Alaimokan ni won, won ko da 'kan mo. |
![]() |
strangerf: Ti o ba ni baba abi awon egbon nile yin, o ko ni so iru isokuso yi. Ti a ba de s'oko s'oja, ara ile eni ni nba, nitori idi eyi, mo da oko ti o so fun mi yii pada si ile yin. Adabi ti mo ba fi iru funfun puro... |
![]() |
Desola: Desola:Idi akoko ni wipe ki awon opolopo le kopa ninu idibo naa. Nipa ebe mi fun awon enia wa lati re iwosi yi danu, mo gbagbo wipe Nairaland je itakun ti o wulo fun ijiroro ati ifikunlukun fun ilosiwaju gbogbo eya Naijiriya. Ija eleyameya ti won nja nibi kii se ohun ti o boju mu rara. Ati paapaa, oye Aare kii se oye yenpere ti o ye ki a fi ma wo'le. Wonyi ni die ninu awon idi ti mo fi nra owo ebe si gbogbo awon omoluabi Yoruba ti won mo pataki oye Aare lati se ojuse won. Gegebi asha awon agba: Abo oro ni... |
![]() |
As an elderly Yoruba mon, I wish to implore the moderators to place this poll on the FRONTPAGE even if it is just gonna be for the last 24 hours of voting. Thanks Moderators, e joo, mo fi irun funfun die ti mo ni be yin lati gbe poll yi lo si frontpage, ki awon omo kaaro-oojire gbogbo le ri. Gbogbo eyin omo Yoruba rere, e se ojuse yin. A mo nkan ti a fe, e re iwosi yi danu. Oodua a gbe wa o. |
(1) (of 1 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 22 |