₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,329,899 members, 8,442,854 topics. Date: Friday, 10 July 2026 at 06:37 PM

Toggle theme

Israelite's Posts

Nairaland ForumIsraelite's ProfileIsraelite's Posts

1 2 3 (of 3 pages)

CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:50pm On Jun 03, 2007
Ose o, peju oku aduro ti mi, mora kokoro abeokuta bo sugbon awon aburo mi ti je tan shaooo
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:42pm On Jun 03, 2007
how do u does, otio , how does u do, irooo, how do u done, kojejebe, how does u done, oooooo oyinbo yi gan ti ke semilese le nu moko fe kin yin ni jare, cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:30pm On Jun 03, 2007
Ekale nibibayi mosese ti abeokuta de ni sugbon oko je epo, grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:29pm On Jun 02, 2007
Eyin elegbe mo ronti igba ti awa ni ewe, baba kan wa ni adugbo wa tio o ma n pa alo fun wa ni ojo metameta, orisirisi alo lo man pa abi e fe kin pa okan ninu e fun yin kegbo bi,
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:37pm On Jun 01, 2007
oMki eyin elegbe mi gbogbo,  mo si nle fun bi ojo 3 kan, molo si oko obasanjo lo ki fun ise to se seyin, oni kin ki gbogbo, nile loko ati eyin ti e wa loke okun , pe e ku aduroti e fun odun mejo detiokrazy,
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:00pm On May 30, 2007
Ejo nitori ti olorun story ni gbogbo nkan ti e so, nkan tio n se mi lowo bayi, ebi n pami mofe omidan obirin kan ninu yin to bami seto IYAN, EFO RIRO, ERONGBE ATI OGURO OJO Kin je mama reti e.nitori ose pataki, tongue
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:35pm On May 29, 2007
Richlaw,
o sha fe mo oriki idile me,
oda naa, eyi ni oriki idile wa ni oke imesi, ADEMOLA OMO AJE OMO ORUJO OMO AFI OJOGBOGBO DARA OMO TO DE ODO TO PONMI WALE ,MO DELE TAPA WON NI KIN WO E NI ORITA BALE,MO DE ORITA BALE WON KIN WO NI AGBOLE IYALODE MODE ODE IYALODE,IYALODE NI ONJEUN LOWO NI YARA MI SE RI BI OMO NAA SE DARA TO.MO GBA FUN E TOO.KARE OMO AJE, molerope mo ti tefe ninu mi si e nibayi, grin wink huh
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:10pm On May 28, 2007
eje kasoro lori awon iwe yoruba eyi ti awon oloyinbo peni NOVEL eyan melo ninu yin loti ka iwe ALAGBA JERIMAYA
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:06pm On May 28, 2007
Eyin Elegbe mi,
mo ki gbogbo yin kabo pada.ejo motoro aforiji lowo eyin, eje ka ni suru toripe ose pataki.nigbati akin se majesi,
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:49pm On May 27, 2007
eje kin se ikilo kan fun awon eyankon nibi, awon bi OMOGENIJA, HOT CHIC, MUKINA ati bebelo, awa kofe yoruba eleyo kan kan ti eso ,infact omu orifomi ,ke ya lo kan ede yoruba dada,boya ke e pada si ile eko grama,abi telo ba awon ojogbon ninu ede yoruba ki won ko yin, UNDERSTAND?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 9:39pm On May 27, 2007
richylaw,
duro na, se orope eni ti ko mole ni mi ni,papajulo odabi pe o mo pe imesi meji lowa ikon wa ni ipinle OSUN ekeji wa ni ipinle EKITI iyato ti o wa larin won nipe imesi-ile ni ti OSUN, oke-imesi lowa ni EKITI ewo lofe nibe , so fun mi
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:39pm On May 26, 2007
gbogbo eyin ti en soro se emo abule yin, elomi ko mo agbole won eko mo pe omo OYO, OSUN, ONDO, EKITI, KWARA niyin oda ti elomo ile oooo, emi ti so temi
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 10:31pm On May 23, 2007
Oruko temi ni ADEMOLA OMOBA moje OMO OKEIMESI NI ARAMOKO IPINLE EKITI.gbogbo eyin ti ewa nibi mo ni ibere kan fun yin,  tani eni to koko joba ni ile yoruba, ati wipe ilu wo ni otijoba, eme pe lepe oooo, eyin omo karo ojire,
Music/RadioRe: I Am Not My Hair (remix): India Arie Ft Akon by israelite(m): 9:43pm On May 03, 2007
i can stop to play the music over and over in the album, i love the lyrics and the combination of the voice, akon is good singer i also love pot of gold as well. cool wink
European Football (EPL, UEFA, La Liga)Re: I Can't Wait To See Chelsea Start Losing by israelite(m): 4:33pm On May 01, 2007
I think there is always a winner and there is always a loser ,i want u so-call gunners to accept ur fate of lossing this season ur time as expired and it is time for ur OGA to take over,dont be suprise that the blues will lift the champions leauge cup b4 u arsenal just accept it as ur destiny and jubilate with thw winning team to to envy, up chelsea, up blues, for life
Nairaland GeneralRe: You Are Welcome, Please Introduce Yourself Here. by israelite(m): 8:30pm On Apr 09, 2007
Waz up folks,what pomping, in case u dont know my name is israel, lagos boy to the core , and am looking for friends both male and female to be a message mate to,am friendly ,jovial and cherfull.get me on my mail adress, demmisab@yahoo.com, thx dude
RomanceRe: She Only 'Kisses' Me On The Phone by israelite(m): 8:15pm On Apr 08, 2007
atimes some girls normally feel shy at the prsent of their boyfriend i guess that's her problem,bu u need to brush her up, dam
angry smiley
Dating And Meet-up ZoneRe: Who Is Your Nairaland Val? by israelite(m): 5:42pm On Feb 11, 2007
I don't believe the fact that there will val, since am awear, now all i need to do is to hang myself around all go to the cinema alone and ve fun and sleep that's all for my val so far i dont ve anybody, 08025822806 cry[color=#000099][/color]

1 2 3 (of 3 pages)