Iyunlade's Posts
Nairaland Forum › Iyunlade's Profile › Iyunlade's Posts
1 (of 1 pages)
I think this is in Alawiye...primary 4, 5, or 6 Kini won o fole she laye ti mo wa 2x Laye ti mowa, kaka kin jale, ma kuku deru Kini won o fole she laye ti moway Teni to jale ba lola laye 2x Bo lola laye, kole rorun wo, bolojo bade Teni to jale ba lola laye Aye ema fole she eni ti a ni 2x Eni ti a ni Kaka koja le .... Ewon ko sun won fun omoluabi.... And this one Ijuba, baba alawo to ba fe kifa Aa ranti opon ifa Akope to ba fe koyin Koni fi igba seyin Bo shere ba fe lo sode Aa si ranti awon alarinrin Kere won le larin rin Mo she iba fun iwo... ... Mo juba foba alade gbogbo Ati iwo eniyan atata To n gbo mi ni akoko yii.... Mo ki e denu.. .... Asiri oga kii tu loju odan Asiri eko kii tu loju ewe Oba ti basirii egbe, yo basiri re A kii ri di... A kii ridi Atiwaye eni Oba onigelegele padi remo Oba oke, maje omo araye ridi re je I might have mess it up a bit...but wow! |
1 (of 1 pages)