Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,157,970 members, 7,835,258 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 07:47 AM

Jamiu3209's Posts

Nairaland Forum / Jamiu3209's Profile / Jamiu3209's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 6:41am On Mar 05, 2016
Ifankaleluya:
FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE
EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E.
IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.

SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.

1.
IWE ASEYORI.

EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO.
FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO.
AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.

GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.

IKILO RE OOO
OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.

2
IMULE AWON AJE TO DAJU
ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.

NOTE;;
TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.

ABORU,ABOYE,ABO-SISE.

E jowo baba efun mi nise yitan e Seun 08138622464

1 Like

Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 5:22am On Feb 13, 2016
Jamiu...08138622464
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 9:13am On Jan 07, 2016
Baba E jowo se eti gbe iwe iwulo ewe ati egbo tie so yen jade....ewe ama je o
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 4:01pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.

E Seun Baba, inu mi adun tia bale ri iwe naa ra ni arowoto lati Ilorin...ewe ama je o
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 12:38pm On Dec 18, 2015
healthFirst:

Sonso ori okuta ti won fi se Aaro
E Seun Baba ewe ama je o
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 8:42pm On Dec 17, 2015
healthFirst:
117
OSE APEGUN (OTUA MEELE TI AN PE NI OTUAWONRIN)

Eha odo ti won fi n guyan, Eha obe ti won fi n be Isu, omu aaro ti won fi n dana meteeta, Ewe Odan ti Eye Ega wa lori re, Erupe Oja to kun, Ewe Owu Akese, Awo Ijimere, Ite Eye Aroni,; Ao gun mose, ao te Iyerosun ni Odu re, ao fi Eje Obuko kan po Ose yi, ao ge ori Obuko na tele Igba tabi Ike, ao gbe Ose yen le...idi re ko gbudo kanle o.

OFO RE; Ope Eluju lo ko igba, lo ko Aake; difa fun Alaketu ti Otalele'gbesan eniyan nji ko otalele'gbesan edi ti, Ifa ni egun kegun ko tie lee mu mi, egun iyan kii modo, egun isu kii mobe, egun ina kii mu aaro, Ifa ni ariwo mi ti omo araye n pa ko ni le se buruku fun mi, ariwo ega susu kii pa Odan, Ifa ni ariwo roro ko ni se Oja ni nkan, Ifa ni temi ni tio ma se, ti ng o ma ni ire gbogbo, takese ni se lawujo owu, tijimere ni se lawujo gbogbo eranko.

Ejowo baba kini nje OMU AARO... E seun

1 Like

Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 6:30pm On Dec 13, 2015
healthFirst:

E beere lowo awon Elewe Omo
E Seun Baba ewe ama je
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 1:07pm On Dec 13, 2015
healthFirst:
114
OOGUN ATIKE TI OKUNRIN FI N FERAN OBINRIN
Obinrin na yio mu orogbo kan si abe re moju, a o gba ni ojo keji, a o gun orogbo na pelu epo bodunbawo ti o wo sile funrare ati ifo ejo die, a o lo kunna dada, a o po mo atike, obirin na yio ma ku si oju re.

E jowo Baba kin lo nje EPO BODUNBAWO ati IFO EJO, nje ale rira lodo awon alagbo.....E seun On ama je o

1 Like

Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 7:33pm On Oct 20, 2015
healthFirst:
97.
AYETA ONI CHAIN Ao wa Chain ti o gun daadaa ( Eyiti o le ka Idi wa po Tabi eyiti ale ma gbe ko Orun waa.) Ao bu Omi Agbara Ojo Eyiti o darogun si Orita meta,
Ao lo awon ewe won yii 1. Ewe Osan wewe
2. Ewe *****
3. Ewe Owo
4. Ewe *****
Ao lo gbogbo re po daadaa ao maa fi omi Agbara yen po papo.. Ti o ba ti kunna daadaa, ao pa Ibepe to robi kan daadaa ni Pansa ao ko awon ewe ti alo yen sinu re ao da Omi Agbara yen sinu re ao wa ko Chain yen sinu re pelu...
Ao wa de pa... Ao lo ri mo Orita meta ti ati bu omi Agbara yen fun ojo 7... Lehin Ojo keje ni ao lo yo..
Ti abaa fe dan wo... Ti abati gbe Ibepe yen Jade ninu Iho yen... Ki ato yo chain yen ki a yin ibon si.... Mo promise yin pe Ibon o le ran Ibepe yen..
Ao ko chain yen, ale de mon idi tabi ki a fise Chain Orun
Ejowo baba efun wani Ogun yii tan, Adura yin ama gba...Mojuba oo

1 Like 1 Share

Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 6:38pm On Oct 03, 2015
Aboruboye mojuba eyin agbagba o...ejowo e fun wani Ogun IMO tabi eyi ti alefi ha nkan sori
Culture / Re: .. by jamiu3209(m): 6:25pm On Sep 30, 2015
Eku deede asiko yi, ewe ama je o....ejo wo moni nidi Ogun Ariran ati Ki Ogun maa ran Eniyan tiwon ba naa yan ni nkan...e seun mojuba

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 26
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.