Janle's Posts
Nairaland Forum › Janle's Profile › Janle's Posts
1 (of 1 pages)
AGBERO ONIFUNPA:- Ao wa akuko adie to ti nko daadaa, ao yo abaweku re, ao fi kudi tio luju kan sinu re, ao wa sa ti yo gbe daadaa, ao wa ra ni awo funfun. Akiyesi pataki. E maje ki nkan kan ibi ise yi tie ba npa lawo o. Pelu ogo olohun ti wo bafe lu wa tabi won fe fi nkan kan luwa apa won koni lo soke bi won ba ti ngbe yo ma ro won ni. Moseba agba ikanni yi. |
OGUN TI WON BA FI MAGUN SI OBINRIN LARA TABI SILE.< Ao wa iruke agbado to dori kole, pelu odidi atare kan, ao jo po. Ao fi singbere yipo ikun wa ao ni je ko de ibi idodo wa o. Moseba ajunilo. |
[OGUN IFURA] ao se'wo si omo oniguguru ao gbodo pe o. Ao ra iwon ba bi oni [50]naira. Ao gbe kale si ibi ti opo eyan bawa won o bawa je. Ka se be fun igba meta tabi ju bee lo. O daju gidi gan o. Mose iba agba o |
[OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. |
[FUN ANFANI ENI TON WA AYETA TO DAJU] ewe efirin, osedudu bi oni.[100]naira pelu oju olongbo kopo die. Ao gun ewe yi mo osedudu yi, ao te oju olongbo yi si lara. Ao ma fi we. Pelu kaninkan adayeba. Osi tun sise fun ada. Ao bu die sinu oti schnapes. Sugbon oni eewo o. Aye mo juba o. |
E jowo kinin won npe ni omundun ewe ege |
Kanbo loni mun, agbo 'sale loni ohuohu bi a ba n soro awon to ni imo nipa esin abinibi wa oga baba healthFirst adura temi si yin niyo. Eo ni feyinti sukun omo, ibanuje koni fi'le yin se'bugbe, gbogbo ohun te ba dawole ni yo ma yori si rere. Kori be ko se be. Ni agbara olodumare |
Bawo ni mose le ri number yin tabi email yin |
Mo nfe oogun ki nkan omokunrin tobi e fi ran mi lowo. Ifa yo gbe wa o |
healthFirst eku ise ajinde ara yoo ma je o. Baba mofe iranlowo yin lori nkan omokunrin mi to kere. Mofe kie funmi ni ogun timo le lo si ni kia_kia. Oju koni tiyin o. |
1 (of 1 pages)