Jophins's Posts
Nairaland Forum › Jophins's Profile › Jophins's Posts
1 (of 1 pages)
Ekale eyin Agbalagba ejowo e add me pada sori whatsapps 07031062770 |
mo ki gbogbo ile 08082988576 ero ibani soroo mi ni yi e add me si whatsapp group. |
[quote author=Ifankaleluya post=45740370]Lofinda Awure Erupe oju-ona ti ese n to dada, ewe-sawerepepe, ati ewe-ominsinminsin mejeji, ao lo kunna dada, ao da sinu lofinda. Iru lofinda WO lale lo tabi eyi keyi,bi St Michael,grace 777 |
e Jooor sir omi omu koye mi
AWURE OJA TITA ATI FUN ENI TI WA ISE Ori--Langba, Oyin die, Omi-Omu, Ewe sawerepepe, Ewe- afomo ajade, ao gun won po mo ose, ao ko sinu igba- olomori, omi-omu yen ni ao fi po ose yen oo. Ao te ose yen ni eji-ogbe, ao ma fi we. Aboru, Aboye, Abo-sise![/quote] |
Ifankaleluya:e jowo sir shey omi inu amu(muld) pot ti awon baba wan lon ni tabi omi yen yato |
ifankaleluyah eku ojo meta sir email mi no jophinsinluv@yahoo.com e jowo sir e kan so mi. |
@estateallen o funny die sugbon emi naa to she iru e ri daada sugbon Orun at I efi ma gba inu ile koda gan o tun ya sugbon e je ji a she bi ti awon Baba wa tin manshe ki o ba ri bitin ri ka ma fi aye Olaju bo lo Aroo eledu tabi Stove tabi Igi |
Ifankaleluya no ki yin sir eku ishe E jowo no Send mail kan si yin ejowo sir E dakun mon reti esi Ayo. |
Ifankaleluya MO ki yin oo MO tun kin yin LEKAN si e ku ise Takuntakun wipe e tie le ni akoko lati ma wa si ori afefe oun ti e fin jeun ti e sin fin she itoju ati iwosan lekan fin fun wa lo fe lo fo ese modupe mo ti gbiyanju ishe meji si meta nibe sugbon awon ti mo she fun won Dupe emi na si Dupe Lowo yin LOLA ELEDUA AMA JO YIN SHE ADAWOLE YIN YIO MA YORI SI RERE E O NI SHI ILE TE NIWAJU ONILE E NI SHI ORO SO NIWAJU OLORO ELEDUMARE A DI YIN MU ATI IDILE YIN. |
1 (of 1 pages)