Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,513 members, 7,854,193 topics. Date: Saturday, 08 June 2024 at 12:17 PM

Kalamklm4ever's Posts

Nairaland Forum / Kalamklm4ever's Profile / Kalamklm4ever's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Kalamklm4ever(m): 1:07pm On Feb 16, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:

Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.

E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.

Numeber mi niyi- 08020407962
Culture / Re: .. by Kalamklm4ever(m): 5:37pm On Feb 10, 2016
healthFirst:
120

OGUN ISORA TABI FUN OWO TABI KI OHUN BURUKU MA SELE SI WA.
Igi legunsoloko tabi egbo re,eru awonka,ako alangba kan,odidi atare kan ao jo po ao fi singbere kan si iwaju ori.
OFO RE: Aye e ma ka mi mo won, a ki ka legunsoloko mo igi ile, aye e ma ka mi mo won, a ki ka eru mo ohun elo obe, aye e ma ka mi mo won, a ki ka eran alangba mo eran ori ate. Gbere kan si iwaju ori, ti won ba n pa okunrin tabi obimrin won yio yo e si oto ni to ripe o ki se ara won.
kini oruko emi fun egbgi yi
Igi legunsoloko tabi egbo re
Culture / Re: .. by Kalamklm4ever(m): 5:33pm On Feb 10, 2016
healthFirst:
120

OGUN ISORA TABI FUN OWO TABI KI OHUN BURUKU MA SELE SI WA.
Igi legunsoloko tabi egbo re,eru awonka,ako alangba kan,odidi atare kan ao jo po ao fi singbere kan si iwaju ori.
OFO RE: Aye e ma ka mi mo won, a ki ka legunsoloko mo igi ile, aye e ma ka mi mo won, a ki ka eru mo ohun elo obe, aye e ma ka mi mo won, a ki ka eran alangba mo eran ori ate. Gbere kan si iwaju ori, ti won ba n pa okunrin tabi obimrin won yio yo e si oto ni to ripe o ki se ara won.

kini ourko emi fun egbogiyi
Igi legunsoloko tabi egbo re

1 Like

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.