Culture › Re: .. by Lero70: 6:38am On Mar 07, 2016 |
healthFirst: OOGUN IFUN ENU(ORAL THRUSH)
Ewe Sayo, Eepo Olobotuje, Eepo Igi Awun, Eriru...ao se won po...yiyo mu diedie.
OOGUN OSI IMUN(BLOCKED SINUSES)
Eepo Igi Obo, ao lo pelu papamilolo, ao kan Oje Igi Oro sii...ao lo won po daada, ao ma fi si imun wa. ejowo kilowa nibiti efi alafo si wonyen? Ewe amaaje o. |
Culture › Re: .. by Lero70: 6:29am On Mar 07, 2016 |
healthFirst: 24 Mo seba eyin iya mi osoronga, afuye gege niye, oyinbiti loruko ti an pe eyin iya mi aje, omobinrin orun...iba o! e jeki iba o se o! Mo juba kekere awo ile aye, mo juba agbalagba awo ile aye, mo seba origun mereerin ode isalaye! iba fun origun mereerin ile ife ooye nibi ojumo rere ti n gbe mon wa le aye...
eyi mo wi loni dase o, nitoripe, ase monamona ni n be lenu oka, ase kolobo ni n be lenu ilakose, tijimere ni se lawujo eranko, eyi mo wi loni, ki aro o ro mo, ki egba orun o gba wole.
Gbogbo eni ti o ba fe tunba fun awon iya mi afuyegege niye, ki o se eto oogun ti o wa nisale yi, lagbara iya odu tii se iya aje, eni naa yio ri oju rere awon agba.
ASINA EBE AJE: Ewe ajeobale tutu, ao lo po mo iyere, ao fi se eyele funfun kan lepo niyo, ao tu iye re sinu agbada, ao ge ori re, ese re, ifun, ao ko sinu agbada, ao ko ewe ajeobale le, ao lo oga oko gbigbe kan ao te ni ofun meji, ao pe ofo re si, ao da sinu aseje na, ao je, ao ko gbogbo eegn rre sinu eroja to wa ni inu agbada, ao jo. Ao tun te ebu ti a jo yi ni ofun meji.
OFO RE: O see se lo bi ewe, ara(do do) lo bi igede, bi ese kan ba wole ekeji a to lo bi ase, ogbonga nii se iya awon aje, oranmiyan lo jagun lo seba orun, o ko eyin mereerin bo wa sile aye, e dele aye tan, e n pa omo olomo je, bi eni peran, e n pa aya alaya lapa danu, e n pa oko oloko lapa sofo, e n di won lowo, e tun jeki won o rise pelu, Orunmila sa to Eledumare lo, Eledumare niki Orunmila o maa lo sile aye, Orunmila lohun o lo, Eledumare tun ni ki Orunmila maa lo sile aye, Orunmila tun lohun o lo, Orunmila ni won ti ba ile aye je tan, won tun fe ba orun se je, Eledumare wa fun Orunmila ni eyele funfun ko se laseje, O fun ni ara to bi igede ko gbemi, O ni ko mu bi ese kan ba wole, ikeji a to to bi ase, ko fifun osun, ko mu Ogbonga tii se iya awon aje, ko kan mo ara ogiri, ko maa ba ise re lo nibe. Jeranjeran kan kii jeran oga lobe, eyin to laye e ma jemi, e ma je aya mi, e ma je omo mi, e ma je ririse mi nile yi, eyele ni mi, emi ko ba won loronro, eyele ni mi, emi ko gbodo wo aso ofo, eyele ni mi, emi ko gbodo wo aso ibanuje, eyele ni mi won ko gbodo ki mi ni iki aburu lori gbogbo inkan ini mi, eyele ni mi, won o gbodo bo bata ibanuje si enu ona mi, totun tosi leyele fii kore aje wole, Orangun meji jeki oro mi o gun gege ju ti egbe mi yoku lo, bi emi ko ba la, bi emi ko ba lowo lowo, egbe mi ko gbudo la. Ao je obe yen, ao ma fi ebu yen foko mu leralera lasiko ti a je obe yen.
IBA AKODA, IBA AISEDA...IBA AWON IYAMI OSORONGA...E JUBA O SE O! ejowo baba iru oga wo ni oga-oko? Kinni iyato towa laarin oga ati alagemo? Eseepupo. |
Culture › Re: .. by Lero70: 6:06am On Mar 06, 2016 |
healthFirst: 93.
ASEGBE OLOPELE TO GBONA Igbe ewure, igbe aguntan, agbari Inaki Igboro to seku, alakan ti ara re pe, odindi atare kan, a o jo po, a o wa ra opele kan ti o la enu sile, a o wa di ogun yi sinu efeowu, a o wa we ni owu dudu ati funfun, a o wa ju sinu opele yen, a o wa ran ni awo dudu, a o wa dalu ni otun ati osi, ti a ba fe lo, a o ma pe ofo re si ibiti a dalu yen. OFO RE: ha 3x, e ma bimi 3x, ti ewure ba su, a ki fi bi, e ma bimi 3x ti aguntan ba su, a ki fibi, e ma bimi 3x aki bere oro ana lowo oku, e ma bimi 3x, a ki bere epo lowo alakan, e ma bimi 3x, a ki bere gbigbe sanle lowo opele, - a o so ohun ti a fe si nitori enu ti opele la sile ki pade mo lailai, ki gbogbo awon enia wonyi(Ao daruko awon to fe ba wa ro ejo si) ma le pa enu isale mo toke ba mi fi ro ejo bayi bayi mo lailai - a o ju si apo. ekuise o baba ewe amaa je o, ejowo se odidi agbari inaki ni a o wa ni tabi die lara egungun agbari inaki, atipe ti okobari eyitoseseku se alelo eyitotikutipedie? Esee. |
Culture › Re: .. by Lero70: 5:36am On Mar 05, 2016 |
healthFirst: 141
IFA IWE ISE ATI OSI DANU I I II II I. II II. II OBARA DAGISE NU Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si. OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin re nina ejowo se kosi asiko ti kole we ose yi, atipe se alemaa wee lojoojumo. Isese ogbewao |
Culture › Re: .. by Lero70: 4:26pm On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya: e dakun kin ni e-mail yin yen? Tori orisirisi e-mail lo wa lori e-mail mi. ( tailadoriginal@gmail.com ) Aboruboye o baba Olaifa, esee pupo o motiri esi ti efiranse simi Eledumare yo maa tiyinleyin eesiniisaseti lagbara Olorun. Moni awon ibeere bii melo kan timofe beere, inumiosidun teeba damilohun lekunrere. 1. Iru awo wo ni anpeni ABOKADELE? 2. Kinni owa ninu alafo mejeeji teefisi isale yi IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO. 3. Se egbo ajeofole ti ogunto ika-aarin ni a o ge meta re, abi eyokan tia bati fiwon ika-aarin yen naa ni amaa ge si meta? Eseun pupo o, unomaa reti esi yin |
Culture › Re: .. by Lero70: 3:33am On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya: IFA-ISOYE
ODIDI OROGBO KAN, ODIDI ATAARE KAN, OBI-ABATA OLOJU MERIN KAN, EJA-ABORI KAN, EWE-ONIYEMIYE,EWE-EERAN ATI EWE ATORI. AO GUN PAPO TI YIO KUN NA DADA BI AGUNMU,AO WA TE NI ODU-IFA OLOGBON-MEJI,AO WA PE IFA RE SI
IFA RE: sabe lawo sade, asa lawo asagede,arara abori patoki awo ile orunmila, lodifa fun orunmila nigba ti baba nsawo ti ko ni iye ninu, ifa ni to ba bi ise tohun(to ba se bi ise temi lagbaja omo lagbaja ba ni. Ni e ma lo larin yen) ba ni, ifa ni iye-orogbo kiiku mo orogbo ninu ka je ko ma le koro,iye obi kiiku mo obi ninu ka so ko ma le yan,iye ataare kiiku mo ataare ninu ka je ko mo le ta ni lenu, eyi ti mo jaja gbagbe eja loni ko ja simi ninu,eeran loni kin ma ranti, atori loni ko to nikun mi worowo,ipanan merindinlogun ni ewe-oniyemiye ma n ni,gbogbo ara ni fi so. Ologbon-meji fun mi ni iye temi kin gbon sara-sara. AO MA FI MU EKO-TUN DIE-DIE. NOTE mo fi ifa yi sile fun iwulo awon eniyan ni. Ti iwo ti o n ta iwe ba ko sori iwe-re,lagbara lowo eledumare wa ri ija awon eleye. Mo fi odu-mererindinlogun bura.
FUN IMONRAN TABI OHUNKOHUN, E KAN SI WA LARI ifankaleluya@gmail.com Ela boru, Ela boye, Ela bo sise. alagba Olaifa ejowo se ewe iyeye naani wanton npe ni oniyemiye? Atipe bawo ni ase ntefa ologbonmeji? Esee ifa o gbeyin o. |
Culture › Re: .. by Lero70: 2:56am On Mar 04, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43423633]Mo dupe pupo lowo gbogbo eyin ti e pe ati eyin ti e ba mi soro lori whatsapp to fi de odo eyin ti e lo e-mail. E seun mo dupe.
Emi ko dede ma ba enikeni ja,sugbon o semi ni aanu nigbati mo ri awon obayeje kan ti won n fi dudu pe fun-fun fun awon eniyan loje ki oro fe se bi ija nitori emi ko fe ibi ti ko ba si otito. Nigbati a si bawon soro ni tutu,won ba bere si leri ogun,to je wipe won o ni ogun eyo-kan ti n sise lowo gan. Koda ti won ba tie ni gan,awa ti tayo eni ti enikeni le ma leri ogun si,notori wipe ifa ni kaka ki aye o ja ko pare,igbin ni a mu to,Ibi won ka sai sun siwon lorun,ibi won.
IFA NI KOKO IGI NI O BERE OJO,ADIFA FUN EJO N BE LORUN TI SE OMO-AWISUNKUN,IFA NI IRE LO BA MO SE. MA SE LOO,IKA LO BA MO SE, MA SE LO,AT'ORE AT'KA OKAN KAN KIIGBE.
Gbogbo eleyi to ba se ni wa je ere re...!
ela-boru, ela-boye, ela-bosise.[/quote alagba Olaifa eseun pupo esikuafomoniyan se yio maa ju yin se o ase. Modupe fun esi e-mail mi akoko ti efiranse, sugbon awon ibeere bii melo kanlesile timobeere ninu e-mail keji timofi ranse siiyin eedahun sii, looto momope owoyin ha, sugbon ejowo ewa aaye lati fesi si ibeere mi. Esee aseti konii bayi o. |
Culture › Re: .. by Lero70: 2:32am On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya: IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE. SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO. alagba Olaifa atipe baba healtfirst ebajebure awoolugbebe keefi suuru gboraayin lagboye keesimaaranti oro eyinagba teewipe awooniitojuogberi dafanu laelae atipe eteawo erin ogberi nio torinaa efi suuru yanju gbogbo ohuntoba jebii ede-aiyede laarin yino isese a gbewa o. |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 2:06am On Mar 04, 2016 |
ayokomi1010: enikeni ti o ba ni oro ida konko lati bami so Ki o kan simi lori (prophet.nase.Solomon10@gmail.com) tabi whatsapp 08135072961 tabi 07087811181,abanise a ba wa se tiwa o amin ejowo baba efunwa ni e-mail yin mii nitoripe motigbiyanju eleyi leemeji tiwonnsope kowa recognized. Phone temi kosigba whatsapp Esee |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:51am On Mar 04, 2016 |
08101646045atwp: ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye, opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o ejowo tani eyin? Se babalawo niyin? Bawoni asele kan sii yim? |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:41am On Mar 04, 2016 |
ayokomi1010: OSOLE OWO Okan maalu ti ko wo omi,omudun ewe akoko 101,pati omonigedegede,epo jebo,ao lo awon ewe yi,ao ge okan maalu yan si 16,ao se pelu epo iyo,ati ata ijosi,ti o ba tutu,ao da sinu Awo funfun,ao wo aso to dara,ao joko si aye to dara,ao pe Ohun re si,ao wa je obe na, Ohunre:- igbe nla ni eran nla ke,e ma GBE owo nla wa fun mi,enikan kiridi omonigedegede o,ki e wa Fi owo nla bemi nise loni. ao ma je obe na diedie fun ojo merin tabi marun,osise gan ni o ejowo baba se akoniikuro lojukan naa tabi ki alosi ibiise titi ojomerin tabi marun taofije obe yentan. Se aomaa gbeelena (warm) e lojoojumo. Eseun pupo mo nreti esi yin. |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:30am On Mar 04, 2016 |
ALIUDAVID: EYONU AWON AGBA ATI APAMOWO OWO.. Ikoide meta, Alanbere meta, Odidin atare meta, Ao jo won po, ao fi sin gbere yii orun owo wa mejeeji, ao po eyi ti o ku mo ose dudu ao ma fi we...
OGUN ATUDE TODAJU... Ewe tude, Egbo tude, Odindin atare, Ao jo po, ao lo kuna dada ao ma fi epo pupa lo.
Iba eyin agbagba iba eyin to laye.. ejowo se oloyunnbere todabi alangba ni enso ni tabi ambere (kini pelebe kekeke bayi tomaankoro) |
Culture › Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 3:09am On Feb 29, 2016 |
Ekaabo Alagba Ayokomi ekuise Eledua omaa ranyinse eosinii saseti lagbara Olorun. Ejowo se ise osole yi ko leyin (repercussion) |
Culture › Re: .. by Lero70: 6:17am On Feb 26, 2016 |
@ Ifankaleluya ejowo efunmi ni ifa yen ni pipe (complete) 07039006806 |