Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,352 members, 7,957,939 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 04:36 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (330020 Views)
Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Zalam5: 1:29pm On Feb 25, 2016 |
E jor sir se ama gun adiye yen nin aaye ni abi bawo ??[color=#990000][/color] |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by tayooluwole: 2:55pm On Feb 25, 2016 |
[quote author=ayokomi1010 post=40681283]moki gbogbo omo Yoruba mosi ikanni yi fun afani opolopo omo odudua fun Ogun nla Awon baba wa ni ile karo ojire ti o ti sonu ti Ati sodi ohun igbagbe ti awon alawo funfun si fi etan ati owo gba kuro lowo wa,esin o sope ka ma se ASA ibile wa o,omo Yoruba eje karonu o,Ikilo mi o fi aiye gba enikeni lori ikanni yi fun oro ti koye omo Yoruba tabi ebu iwa ibaje fifi ago ibanisoro sori afefe,atipe oun gbogbo tabafe ko si ori afefe komu ogbon dani kosi wulo fun Awon eniyan ki o si ma pawonlara odua agbe wa o[/quote Eku ise ooo Baba, yi o maa ju yin she oooo, agba yin akale... E jowo, OGUN IKIYA nko |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by tayooluwole: 3:14pm On Feb 25, 2016 |
ayokomi1010: Baba, eku ise, agbayin adale... Baba e jowo, OGUN IKIYA TO DAJU nko |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:40pm On Feb 26, 2016 |
e kule o gbogbo omo odudua mo se ise awo losi orilede BENIN, ni koje ki e ri mi lori ikanni yi lati bi ojo meta,sugbon ope fun olorun molo layo mobo layo motun ba eyin na layo eledumare Seun |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:55pm On Feb 26, 2016 |
OSOLE eye igun toni ifun ninu eyokan,okete oojo tutu kan,odidi atare kan,ata ijosin Kongo kan,ewe lapalapa funfun to resile 101,ao jo po ao fi ori po,ao mabu diedie laro laro ao mafi eko gbigbona lo 2 Likes |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 3:09am On Feb 29, 2016 |
Ekaabo Alagba Ayokomi ekuise Eledua omaa ranyinse eosinii saseti lagbara Olorun. Ejowo se ise osole yi ko leyin (repercussion) |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by akingbemi(m): 3:25pm On Feb 29, 2016 |
ojukoro:ese |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by akingbemi(m): 3:30pm On Feb 29, 2016 |
[quote author=akingbemi post=43359254] ese[/quot ejo e funmi no Ogun ifunra |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ayomidegbenga1(m): 1:46pm On Mar 01, 2016 |
Baba e fun wa ni ogun ikiya |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Zalam5: 1:51pm On Mar 01, 2016 |
marv006:Ejo oruko miwo ni atun lepe ,,,,odu ori ewe ahunekun? |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:30am On Mar 04, 2016 |
ALIUDAVID:ejowo se oloyunnbere todabi alangba ni enso ni tabi ambere (kini pelebe kekeke bayi tomaankoro) |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:41am On Mar 04, 2016 |
ayokomi1010:ejowo baba se akoniikuro lojukan naa tabi ki alosi ibiise titi ojomerin tabi marun taofije obe yentan. Se aomaa gbeelena (warm) e lojoojumo. Eseun pupo mo nreti esi yin. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:51am On Mar 04, 2016 |
08101646045atwp:ejowo tani eyin? Se babalawo niyin? Bawoni asele kan sii yim? |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 2:06am On Mar 04, 2016 |
ayokomi1010:ejowo baba efunwa ni e-mail yin mii nitoripe motigbiyanju eleyi leemeji tiwonnsope kowa recognized. Phone temi kosigba whatsapp Esee |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 2:19pm On Mar 04, 2016 |
Lero70: Bee ni alanbere ni won saba ma n pe, won tun pe ni oloyunbere n aa |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by kuddus: 9:07pm On Mar 06, 2016 |
ejo sir efun wa ni aluwo todaju |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 3:54pm On Mar 31, 2016 |
ogun Awon baba wa on wathsapp group, 08135072961 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ECadmin: 8:03pm On Apr 02, 2016 |
nje a ti ri enikeni to confam (confirm) ise baba yi? ki iru eni bee so fun wa. ki a le Ni iwuri die. E shey o. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by taofeekjimoh: 9:55pm On Apr 18, 2016 |
E jowo baba,ewe amaa je o,e seun gan,Oloiun a bawa dupe fun yin o.E jowo se lale lamaa fi foko mu,abi laraaro. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by BermudaTriangle(m): 4:36am On Apr 21, 2016 |
Ejowo sir, ogun AKOJEDI ati IDAKOLE to daju nko. Ese. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 2:57pm On Apr 21, 2016 |
orunmila76:. E jowo mofe bere nkan lowo yin lori ise yi. Bawo ni ma se te odu iwori meji is inu iyo naa. Ati wipe kini eniyan le se lati gba owo ti eniyan ba je(debt payment) nitori awon kan je mi ni owo won is fe san. |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 3:22pm On Apr 21, 2016 |
ayokomi1010:. Baba e jowo e se alaye oro yi fun mi ( ao fi owo iyoku sa ori) e se pupo 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 3:26pm On Apr 21, 2016 |
ayokomi1010:. E jowo baba se adodun nooni eleyi ati wipe se a le lo ise yi fun eniti eniyan ba nfe ki won le ma toju eniyan daada. E se pupo 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sanjayzaman(m): 2:03am On May 06, 2016 |
Baba e se pupo olohun atunbo ma ran yin lowo mofe ki e bami wo akose Jaye mi won bi mi ni 24 July 1988 |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sanjayzaman(m): 2:16am On May 06, 2016 |
Baba e seun pupo se omisinmisin Pele ni abi gogoro? |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by mahmudhathunder(m): 11:21am On May 06, 2016 |
baba edakun mo need iferan ti eyan le fi fa iyawo eyan to koyan sile pada.eseun |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by alexdan1881: 11:33am On May 10, 2016 |
Oogun Eyonu to daju Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe. Ejor se 12pm si 12am Ni abi 12pm to 12pm |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:22pm On May 22, 2016 |
e Ku ile o Gbogbo ile,e Ku atijo la ki ara eni,motide bayi |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:57pm On May 22, 2016 |
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o. 1 Like |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nostradamus: 7:40pm On May 22, 2016 |
ayokomi1010:ejoor sir,kini iwulo ise yi ati ba wo ni o se maa n sise? |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ademotech: 5:30pm On May 23, 2016 |
alexdan1881:ejor sir se lati 12pm so 12pm ni |
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Tayo1one: 6:23pm On May 27, 2016 |
E Jo, ewe WO ni won npe ni EWE OGUNBO(ewe oko)
ati pe nibo Lara ireke ni won npe ni Ade ori ireke. E
Jo, inu mi ma dun gon.. ti nba ri idahun. a tun da ti n
ba le ri aworan Ade ori ireke. |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)
Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / Modern Traditional Attire Of Nigeria
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 38 |