₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,328,807 members, 8,437,502 topics. Date: Wednesday, 01 July 2026 at 11:14 PM

Toggle theme

Miftahudeen's Posts

Nairaland ForumMiftahudeen's ProfileMiftahudeen's Posts

1 (of 1 pages)

HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by miftahudeen(m): 9:13pm On Mar 25, 2016
kadunasouth:
Turare Aworo
Epa to ni epo lara tanti yan ewe omisimisi gogoro ao gun papo ao ma fi ni turare pelu ogunna
Ejo sir,lori ogun promotion,se gbere 16 tabi 61 ni ama sin si ori ewo ni ninu mejeji? .
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by miftahudeen(m): 3:07pm On Mar 23, 2016
kadunasouth:
Ogun Promotion
(Agbega lenu ise)
Ori Asa awodi, Awo ekun odidi atare ao jo ao fi sin gbere 61 si ori iyoku ao fi oyin la tan patapata odaju osi dara pupo
Ejo sir,se gbere 16 tabi 61 ?.


Iba fun alaye lorun (s.a.w)ti gbogbo aye wari fun iba fun umul li abati(aramu alai naru kolibu habahu) iba awan agbagba ti wan ti ile ife oye wasaye, iba fun gbogbo emi toma kanga kanga, iba emi keji moju bao



eyin mi eje ki ojumi se. Amin
Ejo sir,se gbere 16 tabi 61 ni? .
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by miftahudeen(m): 8:44am On Jan 04, 2016
eku dede asikoyi sir,esiku agbale wa, Olorun koni fiyinsile fun ota mu laelae.

ejo sir,ije eniti koni cancer lelo ogun cancer fun idabobo e, sir kini nma fa ki erikerike ara majoni bi ina debi ori, ati wipe kini molelo lati fi dekun e ,nitoripe moti lo orisirisi ikan,bi ero ata, ofa,kokoro inu eje,papa ogun oyinbo sibesibe koye majomi di asikoyi edakun sir egbami kale o.
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by miftahudeen(m): 7:34pm On Jan 02, 2016
kadunasouth:
Ogun cancer
Ewe arunyanyan, eru Alamo ao se ti yio jina dada ao ma mu laro losan lale fun 30days
Noted sir.
thank u, God bless sir.
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by miftahudeen(m): 4:53pm On Dec 28, 2015
please sir i need cormfirm cancer treatment sir.thanks.

1 (of 1 pages)