₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,328,219 members, 8,434,668 topics. Date: Saturday, 27 June 2026 at 06:14 AM

Toggle theme

Ogboliagba's Posts

Nairaland ForumOgboliagba's ProfileOgboliagba's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by ogboliagba: 5:40am On Aug 15, 2016
Baba please add me on Isese lagbara whatsapp group my number is 08066161217(ogoliagba)
CultureRe: .. by ogboliagba: 5:21am On Aug 15, 2016
ifasheun:
Mo ti dan ti akoko ti nse ti iwe na wo, mo si ri apere rere, awon eniyan nyonu si mi, even awon eniti mio mo ri ntami ni ore.
Tested vere very ok.
Baba eku agba, ewe koni ko ohun yin o, e jowo e Funmi ni oogun ti tan (IMULE AWON AGBA ) number mi niyi 08066161217.
CultureRe: .. by ogboliagba: 5:06am On Aug 15, 2016
scholes0:
Ododo oro.
ati wipe, ni igba miran- bi awon akopa itakun yii se n ko ede Yoruba won sile ko danto rara.
Bi apere, elomiran le fe so wipe:
"Ni Igba ti mo lo si Ilu Eko, mo ri omoge arewa kan"

Ki o si ko o bayii:

"Ni gba timolo silu Eko, mori omo ge are wa kan"
Nje eyin naa rii wipe, o ma soro fun elomiran lati ka?
Baba, eku agba Otito ni wipe bi awa omo yoruba ode oni se nko ede wa ko muna doko idi ni eyi ti elomiran fi maa nsi oogun lo, ki olorun gbawa lowo awon Oyinbo tiwon wa bawa ledeje.
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ogboliagba: 5:20am On Aug 07, 2016
Baba, Iba agba o, e jowo e Funmi ni oogun ti nkan omo okunrin ba kere ti yio fi gun ti yio si Tobi. Ewe yio ma je funwa o.
CultureRe: .. by ogboliagba: 2:58pm On Aug 05, 2016
baba ejowo e fun mi ni agadagodo yi pe, isese a gbewa oooo ooo number miree 08066161217. tabi olugbogiy@yahoo.com.
CultureRe: .. by ogboliagba: 2:28pm On Aug 05, 2016
@ifankaleluya, number mi niyi ooo, baba ejowo e Funmi ni ise naa tan 08066161217. Aboru boye oo.
CultureRe: .. by ogboliagba: 7:44am On Jul 31, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=43240733]FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE
EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E.
IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.

SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.

1.
IWE ASEYORI.

EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO.
FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO.
AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.

GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.

IKILO RE OOO
OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.

2
IMULE AWON AJE TO DAJU
ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO
Baba, kie pe ooo number miree oo e jowo, onile a gbewa oooo 09058241388
CultureRe: .. by ogboliagba: 7:27am On Jul 31, 2016
Iba agba o, baba healthfirst, e jowo apa ona OJO ni mo ngbe ni ilu eko, bawo ni mose le ri iwe yii ra tabi ti o se maa tomi lowo. number mi ree 09058241388 atipe eeloo ni Iwe naa.

1 (of 1 pages)