₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,906 members, 8,447,658 topics. Date: Saturday, 18 July 2026 at 05:54 PM

Toggle theme

Olajuwonryan's Posts

Nairaland ForumOlajuwonryan's ProfileOlajuwonryan's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 17 pages)

SportsGuardiola Boosting Opponent's Morale by Olajuwonryan(op): 2:18pm On Feb 17, 2015
Abolade Olajuwon Ryan

Guardiola as shown enough respect to this Ukrainian side Shakhtar Donetsk who won the Uefa cup in 2009 and have won the Ukrainian League for five times consecutively.

They boast of the Champions League group stage's MVP... /p5LgSU-h
SportsOro Buruku Ti Messi So Fun Luis Enrique by Olajuwonryan(op): 8:06pm On Jan 29, 2015
Abolade Olajuwon Ryan

Sebi awa so fun yin wipe gobe sele ni Barcelona, wipe ko si irepo laarin Messi ati Luis Enrique. Mo so wipe oka ma fo, wipe a ma to ri fur* adiye.

Gbogbo oro ti Bartomeu ati Enrique n so fun wa wipe ko si gobe kankan, oro ife ni o, iro bansa!

Mathieu Jeremy, alayo Barcelona lo ba awon elero amititi orile ede France, RMC, wipe "igba ti a de lati isinmi ni gobe sele.

Ni Messi ba gbagbe ara re, bi a se n gbaradi, ni o ye ki won fun fere fun Messi fun ika ti won se e fun, Enrique ko si fun fere fun boolu na.

"Ni gobe ba sele, Messi ba so oro buruku si Enrique, o binu so awon oro won yi ni, Enrique ko lati dake fun, awon mejeeji ba wo'nu ija oro.

"Sugbon, ko ye ki oro na fa wahala to yen, awon oniroyin lo gbe gbigbona ju. Nitori a si je Barca ni oro na je be, awon eyan ma n karamo gbogbo nkan ti a ba se, won ko reti iwa buruku lati odo wa rara."

Ese ti kika.

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 17 pages)