₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,445 members, 8,426,567 topics. Date: Sunday, 14 June 2026 at 01:21 PM

Toggle theme

Olateju77's Posts

Nairaland ForumOlateju77's ProfileOlateju77's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by Olateju77: 1:26pm On Jun 21, 2016
ekasan o gbogo ile
CultureRe: .. by Olateju77: 3:57pm On Jun 19, 2016
baba ifankealeluya ati baba heathfirst mofe peyin si ori ago ero temi re 08033589537 ati 08129953818 ejowo mofi edua beyin o
CultureRe: .. by Olateju77: 3:50pm On Jun 19, 2016
iba olorun ,iba eniyan,iba abatenije,iba atuntenise,iba adahunse,iba afa ,iba pastor ,iba gbogbo agbagba ton be ni ile yi ,ifankealeluya iba yin o ,baba wa healthfirst iba yin o ,oruko mi ni olateju ejowo ofe iranlowo yin ogun ibalopo enu orun nibamija lati bi odun mefa seyin i osi somi di alaini nkoko gbogbo ogu ni moti lo ko duro afi ifaseyin nikan mofi eledumare ati ifa be gbogbo ile esanu mi kini mole lo si won ni awon agba ni
CultureRe: .. by Olateju77: 3:35pm On Jun 19, 2016
gawab:
E jowo e bami se ekunrere alaye lori olugbohun.
Yio ma ju se fun yin o!
Ifankaleluya:
IFa ni
Akere finu sogbon
Ni oruko ti an pe ifa
iran Ija gidigidi ko kan agba
Eniti olorun ba pe ni agba
Baba la ma pe
Adifa fun osetura ti o ma ti kere
Gba agba lowo olodunmerinlogun
Ebo won ni kose
Ogbe'bo nbe o si sebo
Ko pe, ko jinna
Ka wa bani ni jebutu ire
Ijebutu ire la ba ni lese oba-orisa.
Mo toro fun gbogbo wa losu titun yi, ti won ba gba ire ni ile ti won gba ni ita, odo gbogbo wa ni won o dari re si. Ase!!!
Aboru, Aboye, Abo-sise.
gawab:
E jowo e bami se ekunrere alaye lori olugbohun.
Yio ma ju se fun yin o!
iba olorun .iba eniyan,iba abatenije ,iba atuntenise ,iba babalawo iba afa iba pastor mose iba gbogbo ile oru mi ni olateju

1 (of 1 pages)