Oscartee's Posts
Nairaland Forum › Oscartee's Profile › Oscartee's Posts
1 (of 1 pages)
aboru aboye sir, e ku agbaale gbogbo eniyan lowo arun gbogbo. e si ku itoni sona nipa sise afihan opolopo ogun lori eto yi. ibeere mi ni wipe bawo ni ao se lo ogun yi ? se lila ni tabi ao po mo ose fun wiwe tabi gbere?................OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan. |
1 (of 1 pages)