₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,462 members, 8,422,204 topics. Date: Sunday, 07 June 2026 at 09:03 PM

Toggle theme

Planner75's Posts

Nairaland ForumPlanner75's ProfilePlanner75's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by planner75: 12:11am On Oct 13, 2015
Eku ojumo Sir Baba oninure...Odua ati awon Alale yoruba a gbe yin ....oooo. Inu mi dun fun gbogbo ise takunkun ti eti fi se anfani fun awon omo yorubawa lori ero ayeiujara(internet- binaryteck@gmail.com) ni iyi ti opolopo awon eniyan ti ri itude, agbala, ati ona abayo fun orisirisi isoro ti mutumuwa nba kakiri.
Baba...ajinde ara ama jee..oooo, koda inu mi dun gidi gan ni nigbati mori ASIRI NLA lori OWU ALANTAKUN isaleyi. Modupe lopolopo lori awon eroja wonyi, sugbon gegebi eti se salaye, mori wipe eko fi idi re han tan- boya a o fi po ose fun wiwe tabi ebu lila lowa funni koyemi rara. Ni afikun, moti gbiyanju ati pe yin lori ero alagbeka(08148398067) yi, sugbon paabo lonjasi. idi ni yi ti mo se fi apo iwe rese lori ero ayelujara......Ejowo e gbami lowo ogun idikudi awon eleye....AGBA KINI TAN LORI ILE...E O PE FUN WA.....AO MA RI YIN BA Oooo.....

OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.

4rm planner75

SAHEED OLUSEGUN
CultureRe: .. by planner75: 12:10am On Oct 13, 2015

Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo ka
CultureRe: .. by planner75: 12:07am On Oct 13, 2015

planner75

1 (of 1 pages)