Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,386 members, 7,861,059 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 10:38 PM

.. - Culture (38) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1834049 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (35) (36) (37) (38) (39) (40) (41) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 6:51pm On Dec 04, 2015
ayokomi1010:
ajo osole,oni ijapa ti Mo ju sita yan,oun tole yo Awon eniyan kuro ninu ipoju ni,asimo iru ajo toye ko mawa Lori itakun aiye lujara mise omode Awo,ohun ti o baye eniyan a bere ni o Awon baba wa ni itose lo ni oyo oni ibere Ki si ona,se efe lewa tele ni,emi Mo oun telero pelu eran NLA,emi kise Awo sese de o,ti won tun gbogbo elo ajo pe ni oruko ti awon baba NLA wa o pe ri, gbogbo eni tobafese ajo yi eran Erin Igbo,lawon baba NLA wa pe be to ripe oun na leran to tobiju,emina ni ikanni temi (Ogun Awon baba wa to sonu)Ayokomi1010@gmail,elowo ikilo to wa be,emi kifi ise to bani eran ajiyo or ajata sori ikanni tori ko mu ogbon dani fun Awo ododo yato si Awon Awo soka o,ese pupo ewe a ma je o baba health

Emi o ni ba e ja iyan rara, sugbon mase post anything that has to do with Eran Nla again...to ba mo Yoruba ko tabi inu account to ti ko sita ni won ti si ko...Eran Ajiyo ni awon agba npe ni Eran Nla...so ti gbo. To ba je Eran Erin lo fe ko, ko Eran Erin sibe. inkan oto patapata gba ni Eran Nla.

6 Likes

Re: .. by dosht(f): 8:28pm On Dec 04, 2015
ayokomi1010:
ajo osole,oni ijapa ti Mo ju sita yan,oun tole yo Awon eniyan kuro ninu ipoju ni,asimo iru ajo toye ko mawa Lori itakun aiye lujara mise omode Awo,ohun ti o baye eniyan a bere ni o Awon baba wa ni itose lo ni oyo oni ibere Ki si ona,se efe lewa tele ni,emi Mo oun telero pelu eran NLA,emi kise Awo sese de o,ti won tun gbogbo elo ajo pe ni oruko ti awon baba NLA wa o pe ri, gbogbo eni tobafese ajo yi eran Erin Igbo,lawon baba NLA wa pe be to ripe oun na leran to tobiju,emina ni ikanni temi (Ogun Awon baba wa to sonu)Ayokomi1010@gmail,elowo ikilo to wa be,emi kifi ise to bani eran ajiyo or ajata sori ikanni
tori ko mu ogbon dani fun Awo ododo yato si Awon Awo soka o,ese pupo ewe a ma je o baba health
Just modify your post and write 'eran erin' Nigbati emi gan ri eran nla Moro bi eran malu ni tongue
Re: .. by Aluqman(m): 8:34pm On Dec 04, 2015
Ekale o baba. Ejowo eni to on se egbogi fun ra re ti ko je fun iru oni ton ki lo le lo fun jije ewe ati egbo. eseun o, ewe ama je o.
Re: .. by KolaBELIEVE: 8:38pm On Dec 04, 2015
healthFirst:
104
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
ejowo se ori oka toni iru re lenu ni?

1 Like

Re: .. by Aluqman(m): 8:39pm On Dec 04, 2015
Baba Health first ati Baba Kadunasouth Ekale o baba. Ejowo eni to on se egbogi fun ra re ti ko je fun iru oni ton ki lo le lo fun jije ewe ati egbo. eseun o, ewe ama je o.
Re: .. by KolaBELIEVE: 9:12pm On Dec 04, 2015
kadunasouth:
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
ejowo sir se kosi nkan ti yo se awon omo enitoba lo ise yi? Iba ooo

1 Like

Re: .. by KolaBELIEVE: 9:31pm On Dec 04, 2015
kadunasouth:
Eyonu Ebe Awon Agba
Igi Asorin(igi nla)) epo obo iye igun akopa eyokan ao lo gbogbore ti yio kuna ao wa dasinu adi eyan ao ma fi para odaju sugbon oni eewo eyokan ijo kijo tabati lo ise yi akogbodo lo turare yala fi para abi fi saso odaju
pls sir kadunasouth i need something to get good job am a graduate pls God bless u. Ewe ama je ooooo
Re: .. by Nobody: 9:58pm On Dec 04, 2015
Aluqman:
Baba Health first ati Baba Kadunasouth
Ekale o baba. Ejowo eni to on se egbogi fun
ra re ti ko je fun iru oni ton ki lo le lo fun jije
ewe ati egbo. eseun o, ewe ama je o.

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.

4 Likes

Re: .. by Nobody: 9:58pm On Dec 04, 2015
KolaBELIEVE:
ejowo se ori oka toni iru re lenu ni?

Beeni.
Re: .. by opeey360(m): 9:58pm On Dec 04, 2015
Iba
Re: .. by Oluokunoluwole: 11:06pm On Dec 04, 2015
Ejowo baba healthfirst kadunasouth mo nilo bi eeyan sele se ipese etutu ebe awon agba,e ran mi lowo ooooo
Re: .. by Nobody: 12:24am On Dec 05, 2015
Oluokunoluwole:
Ejowo baba healthfirst kadunasouth mo nilo bi eeyan sele se ipese etutu ebe awon agba,e ran mi lowo ooooo

Se e ti se iwadi ti won ti so fun yin pe Etutu ni ke lo se? Ni opolopo igba, o ye ki a beere lowo Ifa lati mo iru Etutu pato ti won yio gba lowo yin...opolopo igba ni o je wipe bi ao ba se iwadi ti a kan lo se Etutu, won o ni gba. Ma gba yin niyanju lati lo se iwadi ki e to soro nipa Etutu.
Re: .. by ayokomi1010(m): 1:29am On Dec 05, 2015
kilode ti eyin eniyan ma tan Awon eniyan je ri,won kipe ajata ajiyo ni eran NLA ni odo Awon agba ife e ma serantipe odua o fe iro, eje Ki a se Awon eniyan lore tori ola, elowo gbogbo oun ti Mo post lori ikanni yi baba eleba ise buburu nibe,Awo ire lawa,boya keso pato pe bi won se pe ajata lodo tiyin nu,mise ota yi rara o,emi asi mako ogbon Mo ogbon ni, oruko meta ni afi pe Erin lodo tiwa ajinaku Eran NLA, oun ti Awon baba tiwa fipe ni eran NLA nipe ti eba pa Erin lodo tiwa won a ni Ki logun pa won a ni eran NLA,tori kosi iru eran Igbo teni ba lara re,emaje kama kabuku arawa kama fi ona ogbon han arawa loto ,ese ifa kan wipe okan nikun awodi okan nikun Omo ASA,kaluku lajo ni OKokan Ni kun, kabiye si o

1 Like

Re: .. by rsedo: 8:14am On Dec 05, 2015
[quote author=kadunasouth post=33530358][/quote]

Ese lopolopo.... I'll try it
Re: .. by rsedo: 8:15am On Dec 05, 2015
ayokomi1010:
kilode ti eyin eniyan ma tan Awon eniyan je ri,won kipe ajata ajiyo ni eran NLA ni odo Awon agba ife e ma serantipe odua o fe iro, eje Ki a se Awon eniyan lore tori ola, elowo gbogbo oun ti Mo post lori ikanni yi baba eleba ise buburu nibe,Awo ire lawa,boya keso pato pe bi won se pe ajata lodo tiyin nu,mise ota yi rara o,emi asi mako ogbon Mo ogbon ni, oruko meta ni afi pe Erin lodo tiwa ajinaku Eran NLA, oun ti Awon baba tiwa fipe ni eran NLA nipe ti eba pa Erin lodo tiwa won a ni Ki logun pa won a ni eran NLA,tori kosi iru eran Igbo teni ba lara re,emaje kama kabuku arawa kama fi ona ogbon han arawa loto ,ese ifa kan wipe okan nikun awodi okan nikun Omo ASA,kaluku lajo ni OKokan Ni kun, kabiye si o

Ese lopolopo.. I'll try it
Re: .. by Ifadamilola30: 9:25am On Dec 05, 2015
Mo ki gbogbo ile, e dakun iru ewe wo ni won npe ni "Ewe La"?? E dakun se Ewe Lapalapa ni abi iru ewe wo ni Eyin awo E dakun e tomi sona!! Awon onile yio gbeyin!! Ewe a ma je!!
Re: .. by Shomar: 10:55am On Dec 05, 2015
[color=#000099][/color]
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.

E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o
Re: .. by Shomar: 11:01am On Dec 05, 2015
[/quote][i][quote author=healthFirst post=40696185]
E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o
Re: .. by Nobody: 11:14am On Dec 05, 2015
healthFirst:

Oogun isoye ti wa lori thread yi..e lo wa sita.

BABA MI...HEALTHFIRST...EJO WO TORI TELEDUA
E FUN MI NI OGUN TO MA MUN OKO OLOMOKURIN TO KERE TI O FI TOBI?...EJO....ELEDUA KO NI JE KI IKAN AYO YIN DI IBANUJE. PLS DADDY
Re: .. by Youceemeri: 1:07pm On Dec 05, 2015
WiLdFLame:

BABA MI...HEALTHFIRST...EJO WO TORI TELEDUA
E FUN MI NI OGUN TO MA MUN OKO OLOMOKURIN TO KERE TI O FI TOBI?...EJO....ELEDUA KO NI JE KI IKAN AYO YIN DI IBANUJE. PLS DADDY
Re: .. by Oluokunoluwole: 3:08pm On Dec 05, 2015
healthFirst:
beeni baba,won ni ki nru ebo fun awon aye ati fun omo emere kan ti mo feri

Se e ti se iwadi ti won ti so fun yin pe Etutu ni ke lo se? Ni opolopo igba, o ye ki a beere lowo Ifa lati mo iru Etutu pato ti won yio gba lowo yin...opolopo igba ni o je wipe bi ao ba se iwadi ti a kan lo se Etutu, won o ni gba. Ma gba yin niyanju lati lo se iwadi ki e to soro nipa Etutu.

1 Like

Re: .. by omoalade144(m): 10:31pm On Dec 05, 2015
ejoo sir baba helthfirst e funmi ni ogun ako jedi
Re: .. by Oluokunoluwole: 10:48pm On Dec 05, 2015
Baba moti se iwadi tele,ejowo eran mi lowo
Re: .. by Oluokunoluwole: 10:51pm On Dec 05, 2015
Won ni ki nru ebo fun awon agba ati omo emere kan ti moferi erami lowo
Re: .. by dotsdavidson(m): 5:40am On Dec 06, 2015
healthFirst:
16 IPARA EBE AWON AGBA
Eepo Obo, Eepo Igi Nla, ao gun won po, ao lo won po kuna daada, ao da mo Ori tabi Ipara, ao ma fi para.

E Ku ise Baba, e jo ise wo ni eyi nse?

1 Like

Re: .. by dotsdavidson(m): 5:47am On Dec 06, 2015
healthFirst:

ha! inkan te beere yi lagbara pupo...ni soki, onitohun ni lati tera mo ise Ebe awon Agba kiakia....gege bi eyin na ti se alaye, ifaseyin nla ni...ayafi ki a be awon agba ki won yonu si wa.

OGUN IMULE TI AJE ATI OSO FIN JAWO LARA ENI TABI TI WON BAN DINI LOWO IRE ENI
Awo'ekun'die, Ewe'afomo'ishana'die, Eyele'dudu kan, Odidin'atare'kan, Ikoride'kan, Iye'agbe'kan, Iye'aluko'kan, Ao mu eyele'dudu yen lai ti ku, Ao ti iye agbe bo eyele yen nidi titi iye'agbe yen yio fi yo jade lenu eyele'dudu yen die , Ao wa ti iye'aluko bo oju'otun eyele yen titi yio fi jade loju'osi eyele'dudu yen die, Ao wa ti ikoride yen bo oju'osi eyele'dudu yen titi yio fi jade loju'otun eyele'dudu yen die, Ao wa jo won papo pelu awo'ekun ati ewe'afomo yen, Ao wa te ifa osa'da'meji si ori'ebu yen, Ao wa pe ofo're si, LILO'RE: Ao bora si ihoho omoluabi ninu iyara wa, Ao wa ta epo'pupa si enu ona inu iyara wa, Ao wada ebu eyele'dudu yen die si ori'epo'pupa yen, Ao wa sun sile, Ao se adura si, Ao wa fi ahon laa epo ati ebu yen, IKILO: Ahon ni ao fila.

OFO'RE
Akin'soro'3xs, Atobo'seje'idi' iya'aje'3xs, Olubeleje'idi' iya'aje'3xs, Awon meteta parapo odi ori'tameta'ele, Won kuro nibe, Odi ile omo olotu'ife, Won dele omo olotu'ife, Won ba gbogb ohun ini omo olotu ife'je, Won kuro nibe, Odi ile omo orunmila, Orunmila kigbe'tooo, Oni rara'ooo, Won ni awon yoo ma ba omo orunmila gbe ile, Orunmila ni ki won'o'bura fun owun, Akin'soro'lo'koko bura, Oni ti owun ba ba inkan ini omo orunmila je, Ki oju'otun owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki oju osi owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki owun ma po eje lenu titi owun yio fi po gbogbo ifun inu owun jade teje'teje, Atobo'seje idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Olubeleje'idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Emi omo lagbaja omo lagbaja di omo orunmila loni, Toso'taje ilu kie ma bowo fun mi, ki e mase ba ise owo mi je mo, ki e fori jimi, ki e je ki gbogbo idawole mi yori si rere ni tori modi omo orunmila loni'ooo.

NB ODU IFA OSA LOWO OTUN ATI NI OWO OSI. NI WON PENI ODU OSA TOWA LONA MEJI! LAN PENI OSA'DA'SI'MEJI.

A ma ju yin se o baba, e jowo bawo ni e se le bami se ise yi?

2 Likes

Re: .. by OPCNAIRALAND: 11:15am On Dec 06, 2015
Agoo o! Eku kaale o! Aki yin, eku se, eku eyan, ewe a jee o!

Mo n ka ninu awon idahun ti e ti ko koja, nise ni mo nbu s'erin. grin. Mo gbadun imoran yin ati pe e tun fi oyaya se pelu. Aapere: ninu idahun gbehin nibi te wi pe "ihoho omoluabi". Lol, nise ni mo tun bu erin.. cheesy
Ema binu si ibere mi o, n je ihoho kan tun wa ti eya re ya'to, to ba kuro ni t'omoluabi?

Ooduwa agbe wa o!

Ooni ma gun ori oye ni imole ola , Adimula aagbe wa nigbogbo igberigbe omo Yoruba kaakiri agbaye, Ase Edumare!

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:47pm On Dec 06, 2015
OPCNAIRALAND:
Agoo o! Eku kaale o! Aki yin, eku se, eku eyan, ewe a jee o!

Mo n ka ninu awon idahun ti e ti ko koja, nise ni mo nbu s'erin. grin. Mo gbadun imoran yin ati pe e tun fi oyaya se pelu. Aapere: ninu idahun gbehin nibi te wi pe "ihoho omoluabi". Lol, nise ni mo tun bu erin.. cheesy
Ema binu si ibere mi o, n je ihoho kan tun wa ti eya re ya'to, to ba kuro ni t'omoluabi?

Ooduwa agbe wa o!

Ooni ma gun ori oye ni imole ola , Adimula aagbe wa nigbogbo igberigbe omo Yoruba kaakiri agbaye, Ase Edumare!

Bi won se ma n so Yooba e niyen...Ihooho Omoluabi.
Re: .. by Nobody: 3:48pm On Dec 06, 2015
dotsdavidson:

A ma ju yin se o baba, e jowo bawo ni e se le bami se ise yi?

E kan si mi lori e-mail tabi whatsaap
Re: .. by Nobody: 3:49pm On Dec 06, 2015
dotsdavidson:

E Ku ise Baba, e jo ise wo ni eyi nse?

Bi awon agba ba n binu si wa ni ise yi wa fun.
Re: .. by Nobody: 3:49pm On Dec 06, 2015
Oluokunoluwole:
Won ni ki nru ebo fun awon agba ati omo emere kan ti moferi erami lowo

E kan si mi lori e-mail
Re: .. by Nobody: 3:53pm On Dec 06, 2015
omoalade144:
ejoo sir baba helthfirst e funmi ni ogun ako jedi

JEDIJEDI

Elo wa Egbo Igi Udi...ke ge keekeke sinu omi fun ojo meta, lehin ojo meta, eo ma mun laaro, losan ati lale ni ife kan.

3 Likes 1 Share

(1) (2) (3) ... (35) (36) (37) (38) (39) (40) (41) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 49
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.