Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,571 members, 7,861,731 topics. Date: Saturday, 15 June 2024 at 05:59 PM

.. - Culture (42) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1834120 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (39) (40) (41) (42) (43) (44) (45) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by omoalade144(m): 8:57pm On Dec 13, 2015
Aboru boye o, baba.
Re: .. by Snowealth: 9:53pm On Dec 13, 2015
E kaale Baba healthfirst ati Baba KadunaSouth, mo se ba eyin agbagba ati omo awo patapata yi o ma ju wa se o. A o si ni te oju ile mole, mo ki yin wipe eku ise takuntakun, eledua yi o ma wa pelu yin. A seye lalakan n se epo, aseye la o se o. Ase .
Re: .. by Nobody: 11:09pm On Dec 13, 2015
Snowealth:
E kaale Baba healthfirst ati Baba KadunaSouth, mo se ba eyin agbagba ati omo awo patapata yi o ma ju wa se o. A o si ni te oju ile mole, mo ki yin wipe eku ise takuntakun, eledua yi o ma wa pelu yin. A seye lalakan n se epo, aseye la o se o. Ase .

E seun o. Isese A Gbe Wa O!
Re: .. by castrol180(m): 10:30am On Dec 14, 2015
E se o baba, e dakun mo fi iwe ranse si yin bayi bayi lori itakun pelu apo iba ni soro yii tydot4ever@yahoo.com, e seun o, yi o ma ju yi n se o.
Re: .. by enigstil(m): 8:08pm On Dec 14, 2015
Baba ki e pe, ashe. Ejowo ewe iyalode yi, se tutu ni tabi gbigbe. quote author=healthFirst post=40921823]112

AFORAN EYONU AYE
Epo obo,
Ewe iyalode
Ewe ajeobale .

Ao lo awon meteeta ni otooto , ao ko po epo obo mose, ao wipe pe eyin aiye o, ao jewo Isele ti o sele si won bi a se n po mose, mo nbeyin lowe, mo si fe ki e ba mi se. Ao tun po ewe iyalode mo ose yi, ao tun se alaye bi ti akoko yen, ao tun po ewe ajeobale moo, ao tun jewoo oun ti o sele ati ise ti a fe ki won bawa se, ao ma wa wipe; Eye kan n se mo mi nsere nsere(2x), Emi lagbaja mo ni ki ni eyin eye fi n se mo mi be, won ni nitori oro {ao so isele na}ti mo da ni, mo ni nitooto emi ni mo da oro naa, sugbon mo fe ki e ba mi foo danu. Otan. Ori ako okuta ni ao ti we.
[/quote]

2 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 9:14pm On Dec 14, 2015
g
Re: .. by Nobody: 9:18pm On Dec 14, 2015
f
Re: .. by Nobody: 9:37pm On Dec 14, 2015
enigstil:
Baba ki e pe, ashe. Ejowo ewe iyalode yi, se tutu ni tabi gbigbe. quote author=healthFirst post=40921823]112

AFORAN EYONU AYE
Epo obo,
Ewe iyalode
Ewe ajeobale .

Ao lo awon meteeta ni otooto , ao ko po epo obo mose, ao wipe pe eyin aiye o, ao jewo Isele ti o sele si won bi a se n po mose, mo nbeyin lowe, mo si fe ki e ba mi se. Ao tun po ewe iyalode mo ose yi, ao tun se alaye bi ti akoko yen, ao tun po ewe ajeobale moo, ao tun jewoo oun ti o sele ati ise ti a fe ki won bawa se, ao ma wa wipe; Eye kan n se mo mi nsere nsere(2x), Emi lagbaja mo ni ki ni eyin eye fi n se mo mi be, won ni nitori oro {ao so isele na}ti mo da ni, mo ni nitooto emi ni mo da oro naa, sugbon mo fe ki e ba mi foo danu. Otan. Ori ako okuta ni ao ti we.

Tutu ni ke lo

2 Likes

Re: .. by Nobody: 9:38pm On Dec 14, 2015
castrol180:
E se o baba, e dakun mo fi iwe ranse si yin bayi bayi lori itakun pelu apo iba ni soro yii tydot4ever@yahoo.com, e seun o, yi o ma ju yi n se o.

Mo ti respond
Re: .. by omoalade144(m): 10:06pm On Dec 14, 2015
Eku asale o baba kadunasouth ati baba Heltfirst ejoo,edakun,e funwa ni ogun Atepa\Isana todaju.
Re: .. by enigstil(m): 12:11am On Dec 15, 2015
Eshe modupe baba, quote author=healthFirst post=41007253]

Tutu ni ke lo[/quote]
Re: .. by Shomar: 11:58am On Dec 15, 2015
E fun wa ni ogun Lagunlagun todaju dada
Re: .. by Nobody: 3:51pm On Dec 15, 2015
x

2 Likes 1 Share

Re: .. by wale259(m): 4:08pm On Dec 15, 2015
Ifadamilola30:
cool
Ejo baba,Agbelepota yii ebu to ba ku kini a ma fi se leyin ti ati lo iwonba ti afi pa oju gbere abi opo eniyan le lo.

Osole te so,se ologbo kekere ni abi nila ati wipe nibo la ma ro ogun na si fun lilo diedie. E se
Re: .. by Nobody: 7:58pm On Dec 15, 2015
wale259:

Ejo baba,Agbelepota yii ebu to ba ku kini a ma fi se leyin ti ati lo iwonba ti afi pa oju gbere abi opo eniyan le lo.

Osole te so,se ologbo kekere ni abi nila ati wipe nibo la ma ro ogun na si fun lilo diedie. E se

Agbelepota ewo? Emi o post Osole kankan o, mo de ti ba awon to n post Osole wi. E sora fun Osole o. Eni tio ba ni Ajesara Imunle Agba to gbona gbudo jina si oogun Osole. Igboran san ju ebo riru lo o.

1 Like

Re: .. by Shomar: 9:15pm On Dec 15, 2015
healthFirst:
115

EYONU FUN ENIKENI
Ileke itun,
Ileke ifa,
Irun abe obinrin,
Ewe eeyo
Ewe ata ijosi
Iiye agbe,
Iye aluko,
Iko Odide,
Egungun agbari ologbo die,
Awo ijimere

A o jo won papo, a o sun awo ewure ninu ina, a o ha edu ara re sinu ise ti ajo yen, a o wa lo gbogbo re papo, a o da sinu konjo kekere kan, a o fi ori, epo ati lofinda bintu tabi Miss paris sinu re pelu, a o fi iyerosun te ifa OgbeWonrin.

OFORE:
Siju womi, abifa gbuuru, siju womi la npe ifa, abifa gburu la npe esu odara, itun loni ki e fi enu rere tun mi se, ifa loni ki won fenu rere fami mora, ogbo loni ki won mu temi gbo,oro mi ka sai yo won ninu gerere, bi epo bafoju kan oorun ayo gerere, bi adi ba foju kan oorun ayo gerere , bi ori ba foju kan oorun ayo gerere bi awo ba fi oju kanna woranworan agun, bi oloko ba joko bi olobo ba debe a fi aye gba, Orisa sanu agbe o se aso re laro, orisa sanu aluko ose aso re losun, Ao se iwure fun ohun ti a fe.
Ipara abi?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 10:48pm On Dec 15, 2015
Shomar:
Ipara abi?
Beeni

1 Like

Re: .. by Nobody: 10:49pm On Dec 15, 2015
Shomar:
Ipara abi?
Beeni

1 Like

Re: .. by Shomar: 11:44pm On Dec 15, 2015
healthFirst:

Beeni
BABA, lagunlagun nko?
Re: .. by BABAODE: 9:15am On Dec 16, 2015
OGUN OWO NLA TODAJU-Bi awon era ti ma nbo ounje beni ogun yiri. Ori oka kan,ori ere kan,ori eiye osin kan,owo osi eran aluki,(........),(........),odidi eiye etu kan,awo ekun die,iye agbe mewa,iye aluko mewa,ikoride mewa,(........),(........),eiyele funfun meji,iyanrin okun ati ti osa,ileke ifa,abeere lopolopo,ose dudu lopolopo,ao ko gbogbo re si inu odo, ao si gbe owo eyo(aje)nla kan le lori, ao gun gbogbo re papo, ao ko sinu awo fun fun olomori kan. ao fi obuko kan se sara fun ose yi, Aso funfun lao mofi bora sun, ao mo we ose na lemeji lososu. EWO RE:Obinrin ko gbodo de ibiti osena bawa................Gbogbo iseyi ko ni mofi sita o,sugbon enito ba nife ati gba eyi toku ko pemi sori number mi. 08063121300
Re: .. by BABAODE: 9:25am On Dec 16, 2015
Ise yi dara gan ni,ti obinrin ti nse nkan osu o bati debe rara, kosi wahala kankan(no repercusion) sugbon ewu wafun eni to se ogun owo na ti obinrin to nse nkan bati debe.
Re: .. by fbabs(m): 4:32pm On Dec 16, 2015
kadunasouth:
Ogun iferan gbogbo aye
Ao fo eyin agiriki meji sinu igba ao se adua si ao gbe agbada kana ao da omi agban si to bati ho ao da eyin yi si ao fidin lai si iyo nibe ao koje opari

GOD BLESS YOU for this
Se a le lo dish tabi plate dipo igba (calabash)
Se a le lo frying pan dipo agbada

1 Like

Re: .. by fbabs(m): 4:34pm On Dec 16, 2015
kadunasouth:
Ogun Aleko
Ori Apanri oko atare kan ao jo papo month ose ao ko sinu ikarahun igbin ao ma fi fo oko wa
NB ogun yi tun sise fun eni tiwan ba mu okore

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .

E SEUN

2 Likes

Re: .. by ALIUDAVID: 9:45pm On Dec 16, 2015
OGUN IFERAN FUN ENIKENI TO DAJU.
Awo ewure dudu,
Irun abe,
Ewe amunimuye,
Odidi atare kan,
Ekanna owo(10) ati ese(10),
Iru ipenpeju eniyen die,
Irun ori die..
Ao jo gbogbo re po ao ma fi sinu ounje tabi obe die fun eni naa, ti o ba ti je yio nife re.. Odaju
Iba eyin agbagba, aye mujuba.

2 Likes

Re: .. by Shomar: 9:47pm On Dec 16, 2015
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
lizard ati one set out of three set of aligator peper.

2 Likes

Re: .. by ALIUDAVID: 9:51pm On Dec 16, 2015
Ekale ni ile, ejo talo ni ogun catach ton fa aya(heart),oju ati imu didun ti aba ti sin tan...
iba eyin agbagba, ao ni fi inra logba.
Re: .. by Nobody: 1:09am On Dec 17, 2015
BABAODE:
OGUN OWO NLA TODAJU-Bi awon era ti ma nbo ounje beni ogun yiri. Ori oka kan,ori ere kan,ori eiye osin kan,owo osi eran aluki,(........),(........),odidi eiye etu kan,awo ekun die,iye agbe mewa,iye aluko mewa,ikoride mewa,(........),(........),eiyele funfun meji,iyanrin okun ati ti osa,ileke ifa,abeere lopolopo,ose dudu lopolopo,ao ko gbogbo re si inu odo, ao si gbe owo eyo(aje)nla kan le lori, ao gun gbogbo re papo, ao ko sinu awo fun fun olomori kan. ao fi obuko kan se sara fun ose yi, Aso funfun lao mofi bora sun, ao mo we ose na lemeji lososu. EWO RE:Obinrin ko gbodo de ibiti osena bawa................Gbogbo iseyi ko ni mofi sita o,sugbon enito ba nife ati gba eyi toku ko pemi sori number mi.

te ba fe fi oogun sita, ao fe Oogun Owo, ao de fe ke fi ero ibanisoro sita. ao fe awon 419 rara.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 1:14am On Dec 17, 2015
fbabs:


Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .

E SEUN

ori Aponri ni Ori Alangba Adaripon. Oko Ataare ni ida kan ninu ida meji to wa ninu Ataare

3 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 2:29am On Dec 17, 2015
fbabs:


GOD BLESS YOU for this
Se a le lo dish tabi plate dipo igba (calabash)
Se a le lo frying pan dipo agbada
Beeni sugbon ti ibile lo daraju

3 Likes 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 2:52am On Dec 17, 2015
OGUN IFERAN Gbogbo nkan lalelofun
Ewe omisimisi gogoro ati pelebe, gilasi tiwan nfi wo oju dada, koro sugar meta ao lo kuna dada ao teni eji ogbe ao pe ohunre si ao da sinu oyin ao mala
Eleri ikan 3x Aba orisa 3x Amunidele ire 3x Arile rere yasi woni lewu ola 3x,
Awon mererin niwon da ifa fun orunmila nigbati ifa nlo ba olokun sore 3x won ni olokun ma binu siyan ni 3x orunmila ni olokun koni binu si ohun, won ni ibinu omo araye nko, orunmila ni koni binu si omo araye, oni nitoripe oba ilu kibinu oba ilu, oba osin kibinu oba osin, Oba Ajalaye kibinu Oba Ajalawarun, Oba ajalawarun kibinu oba olomerenmere, Oni bi omode bawo digi arerin bi agbalagba bawo digi arerin, nitori adun duntan niti ewe omisimisi ndun kan araWon, Adun denu ni sugar ndun, omode ki fi oyin senu ki opose, Agbalagba kifi oyin senu ki opose, EJIOGBE gbe ife mi si okan............tabi gbogbo araye ki o fi ife aje sin mi

5 Likes 4 Shares

Re: .. by Nobody: 5:59am On Dec 17, 2015
x

1 Like

Re: .. by segwise(m): 7:05am On Dec 17, 2015
Baba healthfirst, mo ti fi iwe ranse si ori email yin ni owuro yi pelu email address segwise@gmail.com. Mon reti esi laipe. Ese pupo.

1 Like 1 Share

(1) (2) (3) ... (39) (40) (41) (42) (43) (44) (45) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 94
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.