Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,939 members, 7,863,315 topics. Date: Monday, 17 June 2024 at 03:09 PM

.. - Culture (44) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1834253 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (41) (42) (43) (44) (45) (46) (47) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by wale259(m): 1:06pm On Dec 21, 2015
Baba,E jo kini a ma fi lo ogun yi ati wipe igbawo ni lilo re dara ju...
kadunasouth:
Ogun eyonu
Eyin ororo kan ewe ewuro 100 ao fi tele koko ao fi eyin ororo le ao tun ko ewe ewuro 100 le lori ao fi atare kan si ao ma jo to bati jotan dada ao sokale ao wa sadua si ewe ewuro eyokan ao waju si leyin tati sokale ao lo ao pin si ona meje ao bere lilore lojo sunday fun ojo meje
Nb ojo sunday nikan lale jo ise yi odaju
Yio je funyin o+++++++++++++++++++!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:33pm On Dec 21, 2015
moffymichael:
Eku dede iwo Yi sir...

Ejo wo, mo ni ilo iranlowo nipa awon nkan ti awon eni ibi fi n bami nja.

Ti n ba ti sun, mo ma n ri awon emi okunkun(evil spirit) ti won ma wa n ge mi ni orun(neck). LeYin eYi, mo ma wa ri wipe won Yo owo(moneY) ku ro ni owo(hand) mi. Ti n ba ti wa ji, mi o nile ni agbara lati se ise mo.

Ejo, iru isoro wo leYi? Kini ona abaYo? Ese pupo.

Aye o ni mu wa o!. E kan si mi lori e-mail. oro yi kii se tori ategun.
Re: .. by Sobandemojisola: 10:19pm On Dec 21, 2015
E
Re: .. by wale259(m): 11:05pm On Dec 21, 2015
healthFirst:
IFA IBASIRI TI ENIYAN BA FE SE INAWO
TI FI YE ENIYAN
Ao da iyerosun sinu aso funfun ao wa teni
OTUAMEJI.
OFO RE:Amilara, amiloro, iyi ni seru akora
baba yin, orunmila o to gege, kowa fun
emi lagbaja omo lagbaja niyi temi nibi n
kan ti mo fe se yi, ka siri mi o bo, asiri
aso funfun ki tuu, ifa moje kasiri temi
lagbaja omo lagbaja o tu o, otuameji moje
kasiri temi lagbaja omo lagbaja o tu o, kin
gba iyi kin gbeye, aso funfun kisi loju
oloosa.

Baba,e jo se ojo inawo yen ni a ma te ifa na sinu asofun ati wipe ti a ba pe gbolohun na si ifa na ki la ma wa se leyin e,e se alaye na fun wa ko ye....agba yin oni baje

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 11:12pm On Dec 21, 2015
wale259:
Baba,E jo kini a ma fi lo ogun yi ati wipe igbawo ni lilo re dara ju...
Ale fi eko tutu lo, tabi omi tutu igbakugba lale lo ise yi sugbon aro kutu dara

2 Likes

Re: .. by Naturewonders: 7:12am On Dec 22, 2015
Mo ki awon baba wa healthfirst ati kadunasouth fun ise takuntakun ti won se.Eku oro ohun isedale wa .Mo ki gbogbo ile lapapo yio ma ju se o.

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:48pm On Dec 22, 2015
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.

5 Likes

Re: .. by Shomar: 12:53pm On Dec 22, 2015
E jor. Eyin Baba mejeeji. Kaduna ati health. E jor sir.
Ti obinrin ba gbe omo wa sa kuro lodo wa, a jo wo la le se. E dakun, e fi se anu fun wa.
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 3:18pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.

E jowo baba nibo ni a ti le ri iwe naa ra, ati wipe ondo state ni mo wa
Re: .. by jamiu3209(m): 4:01pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.

E Seun Baba, inu mi adun tia bale ri iwe naa ra ni arowoto lati Ilorin...ewe ama je o
Re: .. by Nobody: 4:50pm On Dec 22, 2015
Iwe na yio ti wa fun tita lati Ojoru Ose to n bo. Yio wa ni Ado Ekiti ati Ilu Eko sugbon a le fi ranse si ibikibi te ba wa. Eni to ba fe iwe na, ko kan si mi lori e-mail tabi whatsapp.
Re: .. by Naturewonders: 4:53pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.
.Eseun,ejo ti iwe na ba jade e ri wipe ororun lati ri ra.Ajinde ara yio ma je
Re: .. by Naturewonders: 5:00pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Iwe na yio ti wa fun tita lati Ojoru Ose to n bo. Yio wa ni Ado Ekiti ati Ilu Eko sugbon a le fi ranse si ibikibi te ba wa. Eni to ba fe iwe na, ko kan si mi lori e-mail tabi whatsapp.
.Odara be baba.Maa ma reti re ati location ti won ti ma ta.
Re: .. by omoalade144(m): 7:34pm On Dec 22, 2015
Eleyi dara pupo!.ejowo ilu eko ni mowa, ti iwe na ba jade bawo ni mo sele rira atipe elo gan ni yio je.Opolo yin koni ku o.Ase.
Re: .. by Ousmaf(m): 8:43pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.
Ejoo Baba Cotonou ni emi wa ni Benin republic bawo mo se le ri iwe na ra tioba jade, eseun.
Re: .. by scholes0(m): 9:06pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.

Inu mi dun lati gbo iroyin yii.
Fun elo ni iwe yi yio jade fun tita? E ku ise takuntakun.
Re: .. by Nobody: 1:30am On Dec 23, 2015
E kan si mi lori e-mail tabi whatsapp/call fun oye ti a fe fi sita ati bi awon to wa ni ona jinjin yio se ri gba.
Re: .. by Naturewonders: 5:21am On Dec 23, 2015
keyguy59:
Bi oti le je wipe won ni ogun wa opee.......sugbon kaluku loni account ti re.....ati wipe account o le dogbo...........
EBO AYE TODAJU*
Eyin meje,
Odidi Okete, Orogbo meje,
Eyin Open meje,
Oti ati epo,
Awo sobi kan,
Ao fi Ifa osa meji koru,
Otan.

ese bawo lao se fi ifa osa meji koru.edakun ese alaye
Re: .. by Nobody: 9:45am On Dec 23, 2015
Aboru Boye Oo Baba Wa, E Dakun Bawo Ni A Se Le Se Ebo Awon Agba Metta Fun Ituwo Ninu Oro Eniyan Ati Pe Ki Won Jebure Awo Olugbebe Lori Oro Aye Eniyan, Boya Etutu Awon Agba Abi Ipese.
Re: .. by finalboss(m): 11:05am On Dec 23, 2015
baba ejor erawakale... ogun wo lale lofun eni ti oban fi nkan omokunrin shere(masturbation) bi emi buruku (evil spirit) woh inu e ni
Re: .. by wale259(m): 11:24am On Dec 23, 2015
tundebadmus:
ewo wo ni oni eje ka mon ewoye ki atoda owole,ewe yio maje o
baba,efun wa ni Ewo ise yi...ewe a ma je o
Re: .. by kemkem303: 11:36am On Dec 23, 2015
Aku imura odun o
Re: .. by kemkem303: 11:38am On Dec 23, 2015
Baba healthfirst, e jowo se mo le ba yin soro ni idakonko?
Re: .. by wale259(m): 1:20pm On Dec 23, 2015
Se a ma lo ewe abamoda yen ati ata ijosi yen papo ati pe se lepo niyo la ma se je..
keyguy59:
¤I HAPPILY GAVE ALL THESE TO PEOPLE WHO HAD BEEN
COMMENTING REGULARLY ON MY UPADATES ONLY
BECAUSE I PAGE WITHOUT COMMENTS IS A "GRAVE
YARD"¤
(1) OGUN BASIRI FUN INAWO¤
Ewe abamoda, ata ijosi, ao ko sinu Isasun titun, ao fi oju Malu(eyes of a cow) mejeeji se laseje. O DAJU !!!
(2) OGUN IRIRAN
Ao be Gbaguda Oojo, ao gun ninu Odo, ao fun omi re.
Ao fipo Efun ile, ao maa kan sinu oju wa mejeeji.
O DAJU!!!
(3) OGUN IDANWO Ojele ewe olosan ati glass, ao waa fi Ewe Olosan na
pa GLASS na loju.
ao maafi glass na wo oju nigba EXAM
Re: .. by wale259(m): 1:33pm On Dec 23, 2015
Sir,se lepo niyo ni aseje na?
KolaBELIEVE:
ejowo se ori oka toni iru re lenu ni?
Re: .. by omoalade144(m): 10:27pm On Dec 23, 2015
Baba HELTFIRST ati Baba KADUNASOUTH,ejowo lasiko ti awa yi,ejowo afe kee fun wa ni iwure odun toni ese ifa ninu.Odun a yabo ooooo!
Re: .. by omoalade144(m): 5:14am On Dec 24, 2015
w
Re: .. by omoalade144(m): 5:24am On Dec 24, 2015
ejoo sir baba HELTFIRST,owo malumi towa ni page 1.No 9, se ao we lowu dudu ati funfun pelu eyo atare kan ni abi ti aba fe ran lawo funfun lao fi atare eyokan si legbe ao wa ran po.
Re: .. by Nobody: 11:52am On Dec 24, 2015
kemkem303:
Baba healthfirst, e jowo se mo le ba yin soro ni idakonko?

beeni, e pe mi tabi ke e-mail
Re: .. by Nobody: 11:55am On Dec 24, 2015
omoalade144:
ejoo sir baba HELTFIRST,owo malumi towa ni page 1.No 9, se ao we lowu dudu ati funfun pelu eyo atare kan ni abi ti aba fe ran lawo funfun lao fi atare eyokan si legbe ao wa ran po.

E tele bi a se se alaye sise re ni sise n'tele
Re: .. by Nobody: 11:58am On Dec 24, 2015
finalboss:
baba ejor erawakale... ogun wo lale lofun eni ti oban fi nkan omokunrin shere(masturbation) bi emi buruku (evil spirit) woh inu e ni

Opolopo igba lo je wipe iwa ai le kora eni nijanu(lack of self control) lo ma n fa ki okunrin tabi obinrin se iru inkan te so yi. Kii se oro emi buburu rara. Sugbon ko si ona ti aye o le gba mu eeyan. Mo gba yin niyanju lati ni emi ikora eni nijanu ni gbogbo igba ti ero iru inkan bee ba ti wa si yin lokan lati se.

1 Like 1 Share

(1) (2) (3) ... (41) (42) (43) (44) (45) (46) (47) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.