Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,004 members, 7,849,053 topics. Date: Monday, 03 June 2024 at 01:57 PM

.. - Culture (45) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1832836 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 5:34pm On Dec 24, 2015
owonoko:
Aboru Boye Oo Baba Wa, E Dakun Bawo Ni A Se Le Se Ebo Awon Agba Metta Fun Ituwo Ninu Oro Eniyan Ati Pe Ki Won Jebure Awo Olugbebe Lori Oro Aye Eniyan, Boya Etutu Awon Agba Abi Ipese.
Re: .. by Nobody: 5:43am On Dec 25, 2015
E wo ori ikani yi fun orisirisi ebe Agba sugbon bie ba fe Ipese tabi Eyonu Nla ti a fi n tu awon agba loju, e kan si mi lori e-mail. kii se inkan ta le fi sori afefe.
Re: .. by admolfemx(m): 8:38am On Dec 25, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.
E jo baba healthfirst, elo ni iwe na fun tita mean(price of the book) ati pe nibo ni a ti le rira, ni ipinle osun state, e se pupo.[color=#006600][quote author=healthFirst post=41238894]Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade
Re: .. by Nobody: 10:13am On Dec 25, 2015
admolfemx:
E jo baba healthfirst, elo ni iwe na fun tita mean(price of the book) ati pe nibo ni a ti le rira, ni ipinle osun state, e se pupo.[color=#006600]

Kii se Iwe ta le fi sori ate fun tita sugbon eni to ba nife si yio kan si wa lori e-mail tabi whatsapp, ao fi ranse si ibikibi to ba wa.
Re: .. by omoerimama(m): 4:11pm On Dec 25, 2015
healthFirst:
4. OOGUN AJEGBE(KI MAJELE MA RAN EEYAN)
Odidi kolobo tuntun kan,osan wewe dede eleyi ti alemu
tan lekanna, ao wa fun sinu kolobo na,ao wa owo eyo ti ko luju eyo
kan, ao ju sinu e, ao gbe pamo fun ojo meta si ibiti enikeni koti ni ri.
Ti ojo re ba pe, ao lo sibe sugbon a ko ni ba owo eyo na nibe mon, ao gbe
ao damu, sugbon ti a ba ba owo eyo na nibe, ko sise niyen o.
Baba, E Jowo, Kini Won Pe Ni Odidi Kolobo Kan?

1 Like

Re: .. by Nobody: 6:41pm On Dec 25, 2015
omoerimama:
Baba, E Jowo, Kini Won Pe Ni Odidi Kolobo Kan?

isasun kekere.

2 Likes 1 Share

Re: .. by Diamond666(m): 2:38am On Dec 27, 2015
Aboruaboye nile awo....!!! Iba omode ileyi, iba agbagba ileyi, tokunrin tobinrin ileyi iba ooooo inu mindun pupo pupo nigbati mori ikani yi,Iba eyin agbalagba ton be ni ikaniyi tio jeo baje,ile ati ona teyina konibaje lase edunmare.inumin dun lati darapomon ikani yi kosini baje lase eledua. Iba ooo....
Re: .. by Naturewonders: 3:11pm On Dec 27, 2015
Ejowo gbogbo ile.ogun wo ni omokunrin le lo ti yio fi ri iyawo fe.
Re: .. by Naturewonders: 3:13pm On Dec 27, 2015
Ati eyi ti obinrin lelo ti yio fi ri oko fe
Re: .. by faray: 1:18am On Dec 28, 2015
hehehe...ibile things
Re: .. by Nobody: 2:51am On Dec 28, 2015
Diamond666:
Aboruaboye nile awo....!!! Iba omode ileyi, iba agbagba ileyi, tokunrin tobinrin ileyi iba ooooo inu mindun pupo pupo nigbati mori ikani yi,Iba eyin agbalagba ton be ni ikaniyi tio jeo baje,ile ati ona teyina konibaje lase edunmare.inumin dun lati darapomon ikani yi kosini baje lase eledua. Iba ooo....

Aboru Aboye, Abo sise nile Awo.
Re: .. by Nobody: 2:52am On Dec 28, 2015
Diamond666:
Aboruaboye nile awo....!!! Iba omode ileyi, iba agbagba ileyi, tokunrin tobinrin ileyi iba ooooo inu mindun pupo pupo nigbati mori ikani yi,Iba eyin agbalagba ton be ni ikaniyi tio jeo baje,ile ati ona teyina konibaje lase edunmare.inumin dun lati darapomon ikani yi kosini baje lase eledua. Iba ooo....

Ki le fi kan?
Re: .. by MANPOLO(m): 8:50am On Dec 28, 2015
BABA EJOWO E FUN MI NI OOGUN ATOSI TO TI PE NINU ARA TO BI ODUN MARUN, ABI AGBO ATOSI TI ENIYAN MA MU TO FI MA TO GBOGBO RE DANU, EJOWO MAA MA RETI ESI OODUA AGBE YIN O
Re: .. by Diamond666(m): 9:38am On Dec 28, 2015
Mofi ogbo ato apala afole afayafa mofikan
Re: .. by MANPOLO(m): 10:40am On Dec 28, 2015
EJOWO E RAN MI LOWO NIPA ATOSI YI OUN KAMI LARA E SANU MI ENI FI AISAN LOGBA,ENIKENI TO BA NI OOGUN YII SOWO KIO RO TI OLORUN ATI OLA OODUA KO RAN MI LOWO, OODUA AGBE YIN O E SEUN.
Re: .. by olabisiazeezish(m): 3:41pm On Dec 28, 2015
Ejo se ele fi ogun yi si ori aff lati lema dabobo awa tiki sepanle, ejo efi ogun apaji ati ogun abilu yio ma ju yin se baba.
Re: .. by fbabs(m): 5:24pm On Dec 28, 2015
Naturewonders:
Ejowo gbogbo ile.ogun wo ni omokunrin le lo ti yio fi ri iyawo fe.
Cc ;
Healthfirst, Kadunasouth keyguy,
Re: .. by MANPOLO(m): 5:35pm On Dec 28, 2015
ejo baba helthfirst ati kadunasouth eranmi lowo kie fun mi ni agbo atosi olodun marun(5year ) ati eyi ti ao mamu e ni damu e seun pupo
Re: .. by enigstil(m): 7:35pm On Dec 28, 2015
Epada seyin ki e lo ka abala yi lati oju ewe kini, ikan nine baba kaduna south tabi healthfirst ti fisi ori abala yi RI.
MANPOLO:
ejo baba helthfirst ati kadunasouth eranmi lowo kie fun mi ni agbo atosi olodun marun(5year ) ati eyi ti ao mamu e ni damu e seun pupo

1 Like

Re: .. by MANPOLO(m): 10:21pm On Dec 28, 2015
kin se wipe mio ri iyen sugbon iyen agunmu ni, agbo eleyi to je wipe a ma se lori ina ti ao sin ma mu ni mo un bere kie jo
Re: .. by heritagesat: 10:32pm On Dec 28, 2015
Ejo mo ni di aworo si ile ball (view center) eyi to gbona gan
Re: .. by Nobody: 12:36am On Dec 29, 2015
MANPOLO:
kin se wipe mio ri iyen sugbon iyen agunmu ni, agbo eleyi to je wipe a ma se lori ina ti ao sin ma mu ni mo un bere kie jo

Ki le wo lo...odindi odun marun!....
Re: .. by Nobody: 12:37am On Dec 29, 2015
Diamond666:
Mofi ogbo ato apala afole afayafa mofikan

kare awo...ogbo akokoniko...je ka fi sile beyen...ori afefe la wa.
Re: .. by Nobody: 12:39am On Dec 29, 2015
olabisiazeezish:
Ejo se ele fi ogun yi si ori aff lati lema dabobo awa tiki sepanle, ejo efi ogun apaji ati ogun abilu yio ma ju yin se baba.
Eyin o ki n se ipanle sugbon e n fe ka fun yin ni Abilu? Ki le fe fi Abilu se?
Re: .. by Nobody: 12:40am On Dec 29, 2015
heritagesat:
Ejo mo ni di aworo si ile ball (view center) eyi to gbona gan

Aworo ti wa lori ikani yi sugbon tio ba te yin lorun, e kan si mi lori e-mail...ke ranti wipe te ba ti wa sori e-mail, ao gba owo lowo yin o.
Re: .. by Maleekridwan: 9:59am On Dec 29, 2015
Agbo atosi, eda , inu kikan fun obinrin,bi ori ba yo kokoro . E .t.c.
Ao wa bara odidi kan ao wa fi obe ha gbogbo ara re danu ao ge kekeke lehin igba ti ati yo egusi inu re danu tan ao wa omi osan orombo ti atun masi omi osan wewe ati kanhun bilala die ao da gbo re po sinu ike olomari fun ojo meta lehin ojo keta ao mamu ni sibi imuko meta lojun mon.
IBA EYIN AGBA OOO. YO JUWA SEO.AMINA

1 Like

Re: .. by Nobody: 10:14am On Dec 29, 2015
Wow. very interesting... cheesy
Re: .. by MANPOLO(m): 11:21am On Dec 29, 2015
e seun pupo sugbon eni to ba tun ri imiran to gbona ju eleyi ko fun mi, nitori wipe moti lo to bi orisi risi meta si merin, idi niyen ti mo fin bere fun agbo to gbona dada,sibe eni toba ni imiran to tun gbona ju eleyi kio fun mi, mo un be yin ni baba helthfirst ati eyin egbon mi gbogbo edakun layo lama fi sodun
Re: .. by Shomar: 11:30am On Dec 29, 2015
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.
Re: .. by Nobody: 12:54pm On Dec 30, 2015
Shomar:
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.

E kaabo saarin wa. Aye wa lati ba wa da si eto yi lati gbe asa ati ise ile wa laruge. inu wa yio dun ti e ba ba wa da si. Sugbon awon ilana wa niwonyi;

A ko fi aye gba itumo awon oogun wonyen ni ede geesi rara. Ede Yoruba nikan ni ki a ma fi ko won.

Gbogbo ogun te ba fe fun awon eeyan, ke ri wipe kii se ayederu oogun ati wipe ko je oogun ti e ti se ri.

A ko fi aye gba ogun to ba nilo eya ara eniyan rara

A ko fi aye gba ero ibanisoro rara. Awon to ba fe kan si yin le ko iwe si yin ni idakonko(PM)

E seun.
Re: .. by Nobody: 1:15pm On Dec 30, 2015
x

2 Likes

Re: .. by fbabs(m): 1:50pm On Dec 30, 2015
healthFirst:
119

OOGUN TI AYE KII FI PA OKO OKUNRIN

Ase Oka kan, ao fi sinu agbada, Ogede agbagba to pon kan, ao bo eepo re sinu agbada, Ataare odindi kan, ao yo eyo kan pere ninu re, ao ju sinu agbada, ao jo won po, ao wa fi sin gbere eyo kan si gerugeru idi, ao fi ogun na ra daada ko wole...ao wa fi epo ra ogede to ku, ao yan lori ina, ao fi je ebu ogun yoku. Pelu Ase awon to laye, bi Ejo oka o ba ku, iru idi e kii fi sile lo.

Aye o ni mu wa o!.

Iba ni mo se.

Baba kinni oun je "gerugeru idi"

1 Like

(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.