Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (22) - Nairaland
Nairaland Forum › Entertainment › Forum Games › Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (107835 Views)
1 2 3 ... 19 20 21 22 23 24 25 Reply (Go Down)
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Phunmibi: 10:04am On Nov 02, 2015 |
OLAADEGBU:òwe làófii wa |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Phunmibi: 10:06am On Nov 02, 2015 |
OLAADEGBU:gbogbo ara lògun rè |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Phunmibi: 10:12am On Nov 02, 2015 |
OLAADEGBU:Bi ina ba ku, yoo fi eeru boju_____________________________________ Bí ògèdè b'ákú áfi omorè rópò |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 10:35am On Nov 02, 2015 |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 10:38am On Nov 02, 2015 |
OLAADEGBU:Ba mi na omo mi,__________________ (As you complete the sentence please feel free to start another for others to complete) |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Phunmibi: 10:43am On Nov 02, 2015 |
OLAADEGBU:kòdénú olómo kòkòrò tíún j'èfó ..................... |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by delpee(f): 7:29pm On Nov 02, 2015 |
Phunmibi:Ara efo lo wa |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 3:59pm On Nov 05, 2015 |
delpee:Okare. Ile Oba to jo,__________________ (As you complete the sentence please feel free to start another for others to complete) |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 6:15pm On Nov 11, 2015 |
bolorunfem:Ninu ofii, ninu olaa________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 12:19pm On Nov 14, 2015 |
OLAADEGBU:Ni omo pandoro n dagba si. Bi ina ba ku, yoo fi eeru boju_____________________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 12:42pm On Nov 14, 2015 |
[quote author=OLAADEGBU post=39917892]bi a ni ki a d'iju k'eni buruku koja ____________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 12:57pm On Nov 14, 2015 |
AdeniyiA:Ogbeni AdeniyiA, ekaabo si ori eto yi. Mofe ki egbinyanju lati daun ibere ki eto bere ti yin. ![]() |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 1:03pm On Nov 14, 2015 |
OLAADEGBU:ko si ibeere n'ile ati dahun... |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 1:06pm On Nov 14, 2015 |
OLAADEGBU:... bi ogede ba ku, afi omo re r'opo ![]() |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 1:35pm On Nov 14, 2015 |
AdeniyiA:Igba ti eni rere maa koja aoni mo. Se mo gbaa? ![]() |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 2:18pm On Nov 14, 2015 |
OLAADEGBU:beeni omo Yoruba rere ... #Bi ina ba n Jo ni j'omo eni _____==== |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 2:42pm On Nov 14, 2015 |
AdeniyiA:Tara eni l'ankoko gbon. Abi beeko? ![]() |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 5:40pm On Nov 16, 2015 |
OLAADEGBU:Ole lo mo ese ole,_________________________ ? |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 4:58pm On Nov 19, 2015 |
OLAADEGBU:Ni ori apata. Eni ba ja si koto,________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 3:50am On Nov 20, 2015 |
OLAADEGBU:... ko awon toku l'ogbon /tabi, ko ara to n bo leyin l'ogbon. Eni da éeru... |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 8:08pm On Nov 20, 2015 |
AdeniyiA:Ni éeru ntan. Maluu ti o ni'ru,________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AdeniyiA(m): 7:54am On Nov 21, 2015 |
OLAADEGBU:olorun ni i ba lesisin. sàn laarin ... |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 6:21am On Nov 22, 2015 |
AdeniyiA:ajé ní múni pá kọ̀rọ̀ A nwona ati fi asiwere sile,_________________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 12:18pm On Mar 22, 2016 |
OLAADEGBU:A nwona ati fi asiwere sile, o ni bi a ba de oke odo ki a duro de oun ![]() E pari owe yi: A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu,________________________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 5:16pm On Apr 05, 2016 |
OLAADEGBU:A ki i fi ika ro eti, ki afi ro imu, ki awa tun fi ta eyin ![]() Ala ti aja ba la,____________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by MacMath(m): 4:50pm On Apr 06, 2016 |
Phunmibi:E ko pari owe yi tan: Bi ina ba ku afi eeru boju, b'ogede ba ku afi omo re ropo, bi aladi o ba si nile omo won ni n jogun ebu. Eni to ba gbon(wise) bi owo(money) ko le gbadun owo, ___________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(op): 8:45pm On Apr 06, 2016 |
Gbogbo aluala ologbo ___________________________ |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by theV0ice: 5:30pm On Apr 30, 2016 |
OLAADEGBU:Ogbon ati ko eran je ni ![]() E pari owe yi Ti aba la o se ogun ika mo-------------------------- |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by modath(f): 5:39pm On Apr 30, 2016 |
theV0ice:Awon ti won fe je iwo o ni ye beere .. @ OLADEEGBU Tiwa n Tiwa niyin? Mo ro wipe awon Araabi ti won fi yoruba boju ni o.. |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by theV0ice: 8:15pm On Apr 30, 2016 |
modath:Haba modath?? Even after seeing the Ola?? Anyway, how you and the little ones? ![]() |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by razor123(m): 8:46pm On May 04, 2016 |
. |
| Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by razor123(m): 8:48pm On May 04, 2016 |
eyin eyan omo yin kiyin o. owo omode o to bo akpe.... |
Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. • Colts Vs Jaguars L-ive • Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her • 2 • 3 • 4
Make A Sentence From 5 Letters **reloaded** • Logically Who Would Come Out Alive From These Four? • Words Ending With 'ing'





