Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,746 members, 7,824,148 topics. Date: Saturday, 11 May 2024 at 12:40 AM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (3) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (97658 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:12pm On Jul 08, 2008
kokoye:

translate:

oruku tindin tintin, oruku tindin tintin, oruku b'igba omo, gbogbo l'ole tiro o. kini o?


Aalo apamo ni eyi, ki ise owe. Sibe-sibe itumo re ni EWA.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 5:02pm On Jul 08, 2008
Ojo n pa iyo ori n du nun-----------------------
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 5:11pm On Jul 08, 2008
bluehorizo:

Ojo n pa iyo ori n dunun,
Ojo n pa iyo ori n dunun, ki ori mayo layoju nitori to'jo ba tida orun nbo.

@bluehorizo
se o wa pa?


Agba ti ko ke'wun soro,_________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 5:32pm On Jul 08, 2008
Kola mo wa pa. Se alaafia ni? Awon owe e yen ga ju. Nibo lo ti n gbe won wa na? grin grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 9:25am On Jul 09, 2008
bluehorizo:

Kola mo wa pa. Se alaafia ni? Awon owe e yen ga ju. Nibo lo ti n gbe won wa na? grin grin
grin grin grin Omo odo agba ni mi grin grin grin.Ede yoruba ma nmu inu mi dun gan an ni. Maa se jeje o.

Agba ti ko ke'wun soro,_________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 2:56pm On Jul 09, 2008
Agba ti ko ke'wun soro,_________________________

Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SARE

Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:18pm On Jul 09, 2008
tybanky:

Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SARE
Omo odo agba,o kare laye.Mo gba fun o,o peregede. grin grin grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 5:25pm On Jul 09, 2008
Insert Quote
Quote from: tybanky on Today at 02:56:49 PM
Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SARE

Omo odo agba,o kare laye.Mo gba fun,o peregede.


E se sir
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 12:38pm On Jul 12, 2008
Alangba to f'oju di ere,__________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 1:25pm On Jul 15, 2008
Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________

Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won bi iya adie lati de be lo woran
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:24am On Jul 16, 2008
OLAADEGBU:

Alangba to f'oju di ere,_________________________________

ikun ejo ni yo ba ara e

Afopina to ni oun o pa fitila,_____________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by CH3COO(m): 7:25am On Jul 16, 2008
OLAADEGBU:

ikun ejo ni yo ba ara e

Afopina to ni oun o pa fitila,_____________________________________



ara re nio pa.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:45am On Jul 16, 2008
Egbirin ote________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:23am On Jul 17, 2008
kola oloye:

Egbirin ote________________________

Bi a ti npa ikan ni nkan nru (This was copied from kola oloye) wink

Eni aigbon pa lo po,___________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 8:15pm On Jul 17, 2008
OLAADEGBU:

Bi a ti npa ikan ni nkan nru (This was copied from kola oloye) wink

Eni aigbon pa lo po,___________________________________

eni ogbon pa o to nkan

Eni maa je oyin inu apata,______________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 8:21pm On Jul 17, 2008
- - -- - Ki i wo enu aake.


@post

oo sa igi logbe, oo ta oguro lofa, o wa de idi ope, o gbe enu soke - - - -
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:09pm On Jul 17, 2008
mishooo:

- - -- - Ki i wo enu aake.


@post

oo sa igi logbe, oo ta oguro lofa, o wa de idi ope, o gbe enu soke - - - -

o fe mu emu grin

Eni a wi fun ko gbo, eni a fo fun ko gba,___________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 5:00am On Jul 18, 2008
OLAADEGBU:

o fe mu emu grin

Eni a wi fun ko gbo, eni a fo fun ko gba,___________________________

eyi ti ko gbo yo file bora

Maalu ti o n'iru,______________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 7:27am On Jul 18, 2008
OLAADEGBU:

o fe mu emu grin


it continues - - - -

- - - - Ofe ko ni yio ro.

OLAADEGBU:

eyi ti ko gbo yo file bora

Maalu ti o n'iru,______________________________

olurun ni o m ba le esinsin !!
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 9:45am On Jul 18, 2008
mishooo:

it continues - - - -

- - - - Ofe ko ni yio ro.

Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. wink

Were dun wo,_______________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Femonjay(m): 12:29pm On Jul 18, 2008
Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. wink

Were dun wo,_____ko se bi lomo



ile la awo -------------
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 1:04pm On Jul 18, 2008
Femonjay:

Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. wink

Were dun wo,_____ko se bi lomo



ile la awo -------------

ile la'wo ka to somo loruko



o fi nu we'nu----------------------
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by nana(f): 1:06pm On Jul 18, 2008
bluehorizo:


ile la'wo ka to somo loruko



o fi nu we'nu,
O mo pe inu jin ju orun lo.



Larin egun ni- - -
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 2:27pm On Jul 18, 2008
nana:

O mo pe inu jin ju orun lo.



Larin egun ni- - -

Larin egun ni mariwo ti n soge

T'eni be'gi loju----------------------
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 7:33pm On Jul 18, 2008
of course - igi a ruwe grin grin


@post

Ata aato (do-re re-do-do) OR oun ta ta ti aa to (meaning something - like an animal, shot but not traced/followed up) - - -

Someone must find the answer oo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:20pm On Jul 18, 2008
mishooo:

of course - igi a ruwe grin grin


@post

Ata aato (do-re re-do-do) OR oun ta ta ti aa to (meaning something - like an animal, shot but not traced/followed up) - - -

Someone must find the answer oo

Eni ba ri he lo maa sun je shocked

Atele owo eni,________________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 1:15pm On Jul 20, 2008
OLAADEGBU:

Eni ba ri he lo maa sun je shocked

Atele owo eni,________________________________________

Atele owo eni,ki tan ni je


Ope oyinbo fi dundun sewa---------------
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 8:22am On Jul 21, 2008
mishooo:

Ata aato----
Someone must find the answer oo

ni o n di eran idin. (becomes meat for the maggots)
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by obuchineme: 9:10am On Jul 21, 2008
Agba to rofo ika,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by olawunmi05(f): 2:13pm On Jul 21, 2008
obuchineme:

Agba to rofo ika,


omo re aje ni be


gbami gbami ko ye agba
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 3:24pm On Jul 21, 2008
olawunmi05:



gbami gbami ko ye agba

gbami gbami ko ye agba, eranko ni nle mi bo ko ye ode cheesy

Alagbede t'onlu irin ni oju kan__________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:52am On Jul 24, 2008
Omo ti yo je asamu,____________________________

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 25
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.