Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,166,977 members, 7,866,662 topics. Date: Thursday, 20 June 2024 at 10:33 PM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (16) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (561095 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (13) (14) (15) (16) (17) (18) (19) ... (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:04am On Aug 21, 2016
1234567890A:
@kadunasouth eku irole sir...Olorun yio ma funyin shey...e joo mo ti pe number yin mejeji ni aimoye igba ti e ko gbe beeni to tun send email sugbon mi o ti ri reply. Inu mi o ba dun ti e ba reply me lori email yi. ukadmission01@gmail.com. ..eshey pupo yio ma ju yin shey amin

E send sms pe lati ukadmission si 09090305775 ma get bak siyin ema binu opolopo ama pe lai ni idikan pataki lofa
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by SONIK11: 12:23am On Aug 24, 2016
Baba ejo,kini ogun ti eyan le Lo ti ara eniyan ba n gbon lati inu bi eni ti pajapaja mu, ati ti arin ori ba n fa eyan
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by SONIK11: 12:24am On Aug 24, 2016
Baba ejo,kini ogun ti eyan le Lo ti ara eniyan ba n gbon lati inu bi eni ti pajapaja mu, ati ti arin ori ba n fa eyan ti o si n fa efori
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by SONIK11: 12:26am On Aug 24, 2016
Baba ejo, ogun wo ni eniyan le Lo ti o ba da be ni wipe oro eniyan Fe MA Lo bi eniti o Fe ka Lo lo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by emtar(m): 2:43pm On Aug 24, 2016
kadunasouth:
Gbere Ebe Awon Agba
Igo ngori ewe Agogo igun ao ja 99 odidid atare kan ao jo papo ao fi sin gbere si igbaya otun gbere meta, eyin meta, igbaya osi meta eyin igbaya osi na meta opari odaju
BABA E KU ISE TAKUNTAKUN OOO. SE IGORI AGOGO-IGUN 99 NI TABI 9 NI. E se pupo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:27pm On Aug 24, 2016
emtar:
BABA E KU ISE TAKUNTAKUN OOO. SE IGORI AGOGO-IGUN 99 NI TABI 9 NI. E se pupo

Beeni IGORI AGOGO-IGUN 99
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by SONIK11: 10:58pm On Aug 24, 2016
Baba ejo,kini ogun ti eyan le Lo ti ara eniyan ba n gbon lati inu bi eni ti pajapaja mu, ati ti arin ori ba n fa eyan ti o si n fa efori
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by SONIK11: 10:59pm On Aug 24, 2016
Baba ejo, ogun wo ni eniyan le Lo ti o ba da be ni wipe oro eniyan Fe MA Lo bi eniti o Fe ka Lo lo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sego4(m): 1:19pm On Aug 27, 2016
Ago'nile!!!
Ewure towole tio kago odi eran amu so, Aguntan towole tio kago odi eran amuso, mojuba omode, mojuba agbalagba, ki iba miose. Ewe ama je oooooooooooooooo

@baba:kadunasouth's n'je egba mi laye lati darapomon thread yibii?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by superbouck(m): 9:51pm On Aug 27, 2016
Baba ejowo ULCER ti Fe han mi lenmo, kosi sowo Lati lo si ile-iwosan. Kinni ki n se
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:36am On Aug 30, 2016
ASIRI BIBO TODAJU
Ori Olongbo dudu kan,Ewe wawa topo, ewe aje sefun sefun topo odidi atare meta ao jo papo ao ma fi miliki olope lo ni idaji kutu die die odaju

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by provostkola: 9:46am On Aug 31, 2016
kadunasouth:
Fun ore ati ifokanbale
Ao pan omin sinu roba niwan ba lala ao wure si ao wa gbe sita ti ile bamo laiti soro si eniyan ao fi fo oriwa ao wa fi owo alafia si ori aowa fi owo otun wo igbayawa lemeta ao wa wole pada opari
. ESE gan fun iru abalayi.gege bi Omo Yoruba.

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:15pm On Sep 01, 2016
Eyonu to nmu owo wa ati iferan
Ewe akoko oojo eyokan eso werenjeje 16 ao gun ma ose dudu tawe lekan soso ese kese taba ti gun ose yi lalore we pelu gboloun yi
Aki fewe kewe joye leyin akoko teyi wumi toun wumi lanfi nwo werenjeje gbogbo ibi timo bade kanma nifemi pelu owo owo wan odaju

5 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:22pm On Sep 01, 2016
AWIJARE EJO
Ori owiwi, oronro eran, odindi atare kan, ao jo po ao fi ebu na te ifa Ogbe alara
OFO RE:
Owiwi loni ki e gba temi wi, Oronro loni ki e gba temi ro, ao ma to je, ao tun fi die sari, nire nire la nsoro atare epanupo kie dami lare

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:22am On Sep 04, 2016
Ekaro sir, please help me interpret this dream, I had a dream that I was coming from a woman shop and on my way, I met three secondary boys, we were talking and we gets to a place and I sits down on a bench and place my bag beside me and suddenly two of the boys started searching my bag and taking the money they found inside the bag and as I was walking toward them to stop them from stealing the money in my bag, the third guy grasped me from behind and hold my two hands and urged the remaining guys to hurry up and escape with the money and which they did and fortunately I manage to grasp the guy that hold me from behinds and started beating the hell out of him and demanded my money from him which his colleague took from my bag, I didn't stop beating him until I wakes from my dream.
Please sir,kindly interpret this dream for me
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:20am On Sep 04, 2016
EYONU AWORO TODAJU
ORI OLOGBO,
EWE REKUREKU,
EWE SAWEREPEPE,
ODIDI ATARE KAN
AO JO PAPO,AOLO SUGAR ONIKORO EYO MARUN MO,AOMA LA NI ARARO

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 2:59pm On Sep 05, 2016
Salam alaikum Baba, eku ipalemo Odun Ileya Sir. Olohun ajeki odun naa bawa laye.

Baba mo fe Ogun OLE fun ninu ile ati fun OKO.

e seun sir
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by pat077: 5:47pm On Sep 06, 2016
superbouck:
Baba ejowo ULCER ti Fe han mi lenmo, kosi sowo Lati lo si ile-iwosan. Kinni ki n se
emi nor need solution si problem yi.

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sego4(m): 11:35am On Sep 09, 2016
Eyonu Atude Asina owo ojo
Ao wa ogorun naira tuntun eyokan itana
rerinkomi topo ewe ola die atare kan ao
jopo ao lo ao da sinu oyin ao ma la ni aro


mojuba aye o, ewe ama je o
@baba kadunasouth eku ise sir, ejowo se padi atare kan ni tabi eyo atare kan
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:01pm On Sep 23, 2016
Sego4:
Eyonu Atude Asina owo ojo
Ao wa ogorun naira tuntun eyokan itana
rerinkomi topo ewe ola die atare kan ao
jopo ao lo ao da sinu oyin ao ma la ni aro


mojuba aye o, ewe ama je o
@baba kadunasouth eku ise sir, ejowo se padi atare kan ni tabi eyo atare kan
Odidi atare kan

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by tabithababy(f): 7:25am On Sep 24, 2016
kadunasouth:
Eyonu to nmu owo wa ati iferan
Ewe akoko oojo eyokan eso werenjeje 16 ao gun ma ose dudu tawe lekan soso ese kese taba ti gun ose yi lalore we pelu gboloun yi
Aki fewe kewe joye leyin akoko teyi wumi toun wumi lanfi nwo werenjeje gbogbo ibi timo bade kanma nifemi pelu owo owo wan odaju
. E Ku use takuntakun baba eweje. E jowo se a le ri ewe akoko oojo ra lowo a won elewe omo? Ati wipe we e le fun mi ni ero ibaraniso yin. E se pupo baba eweje.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by seyisolomon: 9:59pm On Sep 27, 2016
thanks baba, mo fe mo akose jaiye mi. ojo ketala osu keta
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 10:03am On Oct 05, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o


Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Homogeneositys(f): 1:09pm On Oct 05, 2016
baba ejowo Ogun WO ni eyan le lo fun iko to le. to tun fa eebi
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 1:33pm On Oct 06, 2016
08101646045atwp:
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o


Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o


eseun pupo. Oluwa yio ma so agbara dotun . mo Fe darapo mo MAJEMU LAILAI

08085632313

. eseun
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:30am On Oct 13, 2016
superbouck:
Baba ejowo ULCER ti Fe han mi lenmo, kosi sowo Lati lo si ile-iwosan. Kinni ki n se
Aidan nla kan eo ge egbegbere nibi isure keke eo ko sinu roba ti owo lewo ose dudu gbigbe bi elubo sibi meji sinu re omin swan abi omi ojo leo dasi eko gbodo de eo fi le be toba di ojo keji eo ma yomu die die kie to jeun larara koto to ose meji ulcer na yio lo pata pata

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by HorlarhMheporzy(m): 9:02am On Oct 14, 2016
moni ibeere kan ti mo fe ki edami lohun kiakia. kini iyato to wa larin olugbohun ati afose ati wipe ewo lo man yara sise ju ninu mejeji.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by durocityrich: 10:18am On Oct 14, 2016
Baba please I need confirm isoye and confrim fast money making sir.thanks a lot.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Abtub: 12:00am On Oct 17, 2016
Ekale ooo baba....iku ise oluwa,ejowo sir agbo WO ni eniyan le lo ti aya ba n dun yan mo oyan,ti aya nah yo ma gbona,ti oyan yi o ma so eniyan je die die....ti gbogbo aya yo si ma gbona..Ejo sir agbo wo ni eniyan lelosi....atipe iru isan wo ni yen.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sego4(m): 7:47am On Oct 18, 2016
ekaro ooo, ewe ama je o, ejo e add me si whatsap group 08147506432
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AdiscoPele: 9:24pm On Oct 19, 2016
Baba, eku ise takuntakun. Olodumare a ma wa pelu ni. Amin.

Ejowo, e add mi si whatsapp group yin. 08024449355
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 9:18pm On Oct 20, 2016
Ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045!
Sugbon!
Bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o

(1) (2) (3) ... (13) (14) (15) (16) (17) (18) (19) ... (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.