Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,143,340 members, 7,780,899 topics. Date: Friday, 29 March 2024 at 03:35 AM

Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. (4963 Views)

Magic Doctor: CEO Lady's Humble Husband [A Story] / Why I Love The Color Black *a Short Story Of Sexual Abuse* / Don't Laugh Me, Love Me ( A Short Story) (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:38pm On Dec 16, 2017
Idan (Magic) A short Yoruba Fiction

Ni asiko igba kan. Baba kan ati omokunrin re maa n lo kaakiri lati ilu kan si ikeji lati se ere onidan fun awon eniyan.

Opolopo eniyan ni o feran won ti okiki won si kan jale jako. Won ti ni opolopo owo ni idi ise naa.

Gbajumo ni oruko ti won maa n pe baba yii, won a si maa pe omo re ni Omo Baba Gbajumo.

Ni igba kan, won koja lo si ilu Ayetoro lati lo se ere da awon ara ilu naa laraya.

Sugbon ninu ilu Ayetoro yii baba kan wa nibe ti o je Oloogun ika ti awon ara ilu si beru re pupo nitori wipe o lagbara pupo. Oba ilu naa paapaa a maa beru re.
Oruko Baba naa a maa je Aiku Olori nla.

Nigba ti Baba Gbajumo ati omo re de ilu Ayetoro yii, ti awon ara ilu si ti pejo si ita Oba.

Won bere ere won leyin ti won ti juba awon agbaagba adugbo ti n be lori ijoko. Won si ki Oba ilu naa nitori o n be ni ikale.

Awon ara ilu n pariwo, ero si n ya tii lati wo idan ti baba ati omo re fe pa.

Baba Gbajumo ati omo re bere si joo, won si n korin, awon ara ilu si n gbe e....

Leyin igba die, won dake orin.
Baba Gbajumo si ni ki omo oun dubule.
O dubule.

Baba Gbajumo ni ki eni kan bu omitutu sinu igba wa.
Won se be.
Baba naa pe ofo si omi ti o wa ninu igba naa.
Omi naa si di gbigbona ni esekese ti oun yo eruku lailai.
Awon ara ilu pariwo nitori eyi je ara oto ti o si ya won lenu.

Baba Gbajumo gbe omi naa o si da a si ori omo re to dubule.
Kete ti omi yi kan omo naa lara ni o yi pada ti o si di Ejo nla rabata.
Opolopo ninu awon ero iworan ba ese won soro. Won juba eworo.
Se won ni bi omode ba de ibi eru, eru a maa ba iru omo bee.

Oba ilu gan paapaa fe ki ere mole sugbon O ranti owe agba ti o wipe
" Gbami gbami ko ye agba, eranko nle mi bo wa, ko ye ode"
O duro, sugbon oju re ko kuro lara ejo naa.

Gbogbo bi nkan wonyii se nlo. Baba Aiku Olori nla joko si waju ile re, inu re ko si dun si idan ti baba Gbajumo ati omo re n pa ni gbagede.
Oun binu, oun fi ese janle.
Nibiti o joko si ni omodebinrin kan ti sa koja, ti baba naa si bi ni ere oun ti oun sele. Tiberu tiberu ni omo naa fi salaye fun.

Nigba ti Aiku gbo wipe Gbajumo ti so omo re dejo, inu re dun. O taka. O si wo inu iyewu lo....

Ejo ti omo Gbajumo daa ko pa enikeni lara, o kan n lora mole ti o si n fo bi eyan.

Awon eeyan ti o koko salo ti pada wa. Ti gbogbo won si n rerin. Omiran n fi owo kan ejo naa paapaa.

Sugbon nigba ti o ya, ti Gbajumo fe so omo naa di eyan pada, o pe ofo titi, o fi owo pa ejo naa lori sugbon ejo ko yipada.
Nigba to ya ejo naa ko le soro mo. Ko si le kuro ni ojukan.

Baba Gbajumo damu pupo. O ti mo wipe o ti ni owo aye ninu.
O si be ero iworan wipe bi oba ni eni ti o wa nidi oro naa ko ro ti awo, ko si jawo.

Oro di kee. Awon ara ilu ti mo wipe Aiku Olori nla lo wa nidi oro naa, won si fi to oba leti.

Oba so oro yii fun baba Gbajumo.
Baba Gbajumo pa aroko ranse si Aiku Olori nla wipe

"Eta ni tawo, Erin ni ti ogberi...
Wipe ki awo gba awo ni igbowo nitori wipe ti awo ko ba gba awo ni igbowo, awo a te"

Sugbon eyin eti Aiku ni oro yi bo si, o si funra re jewo wipe, oun ni oun ti agadagodo ti omo naa ko fi le yipada. Oun si ti so kokoro re si igbo.
O si wipe ko si idi kan pataki ti oun fi se be sugbon oun fe dan agbara Gbajumo wo ni. Nitori wipe oun ni o ni agbara julo ni ilu naa ati agbegbe re....

Leyin opolopo akitiyan, Baba Gbajumo ni ki won fi baba naa sile. Wipe Olorun loba elejo.

Ni gbogbo igba yii o ti n re omo baba gbajumo abi kani o ti n re ejo naa ti o yipada si ti emi si ti fe bo ni enu re.

Awon ara ilu paapaa ti n sun ekun sugbon baba Gbajumo ko foya.
O so ni okan re wipe, oun yoo fi ye Aiku wipe
" Alagbara ni Oshodi, ole ni l'Agege"

Baba Gbajumo mu okuta kekere kan ni ile, o so si enu, o gbemi. O tu bante idi re O si bere mole bi eni to fe se gaa, o ya ado kekere kan jade lati idi re, awon ero si tun se.
"hmmmmmmmm"

Baba Gbajumo gbe koto si ile, o si ju ado naa si. O ko iyepe le e, o si fi ese kii mole....

Leyin iseju meji Igi ibepe nla lo wu jade ni ile ibe. Teso teso.

Awon ero si tun see "hmmmmmmmmm"

Baba Gbajumo mu igi tere, o ka eso kan o si han pelu owo re ki o to bale.

O gbe ibepe yii si ori ile niwaju ejo ti omo re yipada si.
O si yo ada jade ninu ako re.
O be ibepe yii si meji, lesekese naa ni ori Aiku si bo kale ni orun re ni waju ile re ti o joko si. Afi gidi nile.
Lese kan naa ni ejo yipada ti o di omo baba Gbajumo.

Inu awon ara ilu dun.
Won ho geeeee.
Won n pariwo....
Won n joo, won n yo.
Won gbe baba Gbajumo ati omo re sori lo si aafin oba won.

Won si gbe oku Aiku Olorin nla fun awon aja je.

Oba si da won lola lopolopo nitori ti won ba a segun aninilara ti n be ninu ilu re.

2 Likes

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Nostradamus: 8:40pm On Dec 16, 2017
reading in yoruba language is hard for some people,nice storyline you got bro

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:47pm On Dec 16, 2017
Nostradamus:
reading in yoruba language is hard for some people,nice storyline you got bro

awwwww. thanks
yes its somehow tasking and thats why I have to use simple language so that readers can still get the feel without much ado.....
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Debbietiyan(f): 12:22am On Dec 17, 2017
illicit:

Chai...
illicit:

awwwww. thanks
yes its somehow tasking and thats why I have to use simple language so that readers can still get the feel without much ado.....

He even called it simple language embarassed

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by AryEmber(f): 8:27pm On Dec 17, 2017
Ijo ni loju gba leyi je o! E gbinyanju gan ni! Amo sha, mo rope ita Oba ni Baba Gbajumo ati omo re ti n pidan ni? Won tun se wa ko won lo si aafin Oba leyin iku Aiku?
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Ayemileto(m): 9:19pm On Dec 17, 2017
Op, E gbiyanju nipa Aroko yin yii oo. E Ku ise naa.

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by nikky9(f): 9:40pm On Dec 17, 2017
wow,I love to read youruba stories a lot,good job.

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:35pm On Dec 18, 2017
Debbietiyan:

Chai...
He even called it simple language embarassed
lolz, yes na, and thats why I kept it short to just to sustain the interest.... Its hard really and thats why most people shun it lolz. did you read it through sha
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:36pm On Dec 18, 2017
Ayemileto:
Op, E gbiyanju nipa Aroko yin yii oo. E Ku ise naa.

E seun gan ni...
E ma ba wa kalo....
Itan si po ni iwaju fun igbadun yin
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:40pm On Dec 18, 2017
AryEmber:
Ijo ni loju gba leyi je o! E gbinyanju gan ni! Amo sha, mo rope ita Oba ni Baba Gbajumo ati omo re ti n pidan ni? Won tun se wa ko won lo si aafin Oba leyin iku Aiku?
E se gan ni.
E si ku Akiyesi...
Ita oba yii je bi aarin Ilu, ki se iwaju aafin ni o wa....
Nigba ti Aiku ti ku tan, ti ejo si ti di eniyan pada, awon ara ilu gbe baba gbajumo ati omo re lejika, won gbe won lo si aafin oba....
mo lero wipe o ti ye yin bayii
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 8:46pm On Dec 18, 2017
nikky9:
wow,I love to read youruba stories a lot,good job.
awww thanks.
ok.... were u able to read this story easily

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Debbietiyan(f): 8:59pm On Dec 18, 2017
illicit:

lolz, yes na, and thats why I kept it short to just to sustain the interest....
Its hard really and thats why most people shun it lolz.
did you read it through sha

cry I don't even understand yoruba...
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 9:01pm On Dec 18, 2017
Debbietiyan:

cry I don't even understand yoruba...
oh my.... awwww I would have love to write you a special
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by AryEmber(f): 9:50pm On Dec 18, 2017
illicit:

oh my....
awwww I would have love to write you a special
ehn ehn! O sese wa ye mi yeke yeke bayi ni. E ku se takun takun na!
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Debbietiyan(f): 10:00am On Dec 19, 2017
illicit:

oh my....
awwww I would have love to write you a special

You can still write it kiss...then translate it to English grin
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 5:27pm On Dec 19, 2017
Debbietiyan:

You can still write it kiss...then translate it to English grin
hmmmmm I will try
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by nikky9(f): 9:55pm On Jan 06, 2018
illicit:
awww thanks. ok.... were u able to read this story easily
yes,thanks

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by Maymac(m): 12:16am On Jan 07, 2018
Mo gbádùn ìtàn náà. Á dára tí ẹ bá f'àmì si.

1 Like

Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by ghostwritter(m): 11:16am On Jan 07, 2018
Olukotan, isé takun-takun lo sé. Nisé lori n mi wu, leru n sin bami nigba ti mon kaa. Olorun a ran e lowo.
Can't believe I could read in yoruba this good. I completed the story with ease...it's so intresting.
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 7:39pm On Jan 10, 2018
nikky9:
yes,thanks
Nice one
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 4:59pm On Oct 18, 2020
wink
Re: Idan (MAGIC) A Short Yoruba Fiction. by illicit(m): 3:40am On Jul 17, 2023
grin

(1) (Reply)

Latest Nigerian Slangs / The Heart Of A True Believer~ A New Romantic Story / Sex Stories: Jide Part 4

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.