Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,607 members, 7,812,998 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 02:46 AM

Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (285670 Views)

Owe Yoruba / Akpaala Okwu (idioms). / Igbo Idioms (Ilu) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tunnytox(m): 12:39am On Dec 17, 2010
Eyin eyan mi nile ka'ro ojiire se kii se pe e ti pa tireedi yi ti? owe awon "agba ni pe agba jo owo la fi n so ya, ajeje owo kan ko gbe'ru dori" eje ki a tu bo gbe tireedi yi laruge. cool cool
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by dayokanu(m): 1:14am On Dec 17, 2010
Eyin agba ti e je esebi, e ko ara yin jo o.

Won ni agba ki wa loja, ki ori omo tuntun wo
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tunnytox(m): 12:37am On Dec 20, 2010
Oseun jare alagba Dayo, lori tireedi ti a fi n kedun iku oloogbe Alhaji Dokita Sikiru Ayinde Barrister mo beere fun itoni lorii bi a see le gbe fiimu latori youtube sii ori tireedi nairaland. Ti e ba ka e joo e fun wa ni itoni lori e e seun.

Eyin eniyan mi e joo se e lee tumo awon asaayan oro ti mo ko si isale yi bi ni ede geesi?

A kii leni ni mosan ki a mu kikan

Agbon n se Oyin naa nse bee oju oloko ree kondu kondu

Ko si eni tii fi obe to'nu je'su
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Olumogun: 12:30am On Dec 22, 2010
tunnytox:

A kii leni ni mosan ki a mu kikan

Agbon n se Oyin naa nse bee oju oloko ree kondu kondu

Ko si eni tii fi obe to'nu je'su

^^^^
1.  A kii leni ni mosan (idi igi osan) ki a mu kikan:
You can not have someone under the orange tree and drink sour ones.
Often used when a man is fully represented in an issue.

2.  Agbon nse, oyin na nse, beesini ojo oloko ree kondu-kondu:
The wasp is denying and the bee is also denying, yet the face of the farmer is swollen all-over.
Used when parties involved in an issue are all clamming innocence yet the evidence are glaring.

3.  Ko s'eni ti f'obe to'nu je'su:
No one will ever accept to have make use of (eat yam with) the missing knife.
When something goes wrong, everyone play innocence.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by dayokanu(m): 1:40am On Dec 22, 2010
tunnytox:

Oseun jare alagba Dayo,  lori tireedi ti a fi n kedun iku oloogbe Alhaji Dokita Sikiru Ayinde Barrister mo beere fun itoni lorii bi a see le gbe fiimu latori youtube sii ori tireedi nairaland. Ti e ba ka e joo e fun wa ni itoni lori e e seun.

Eyin eniyan mi e joo se e lee tumo awon asaayan oro ti mo ko si isale yi bi ni ede geesi?

A kii leni ni mosan ki a mu kikan

Agbon n se Oyin naa nse bee oju oloko ree kondu kondu

Ko si eni tii fi obe to'nu je'su

Copy the link like  this : 
https://www.youtube.com/watch?v=tys7_ybRVvA

Highlight it and click on insert flash at the top

remove the  ? and replace with =/

remove the = at the back of v and put /

After the adjustment it would look like this

http://www.youtube.com/watch=/v/tys7_ybRVvA


You can increase the size by changing the 200 size of the flash to any number you want

Post it
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 12:46pm On Dec 22, 2010
eleti kan = a lone child
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by olawonder(m): 10:45pm On Dec 23, 2010
Bi ewure eni ba sa wo ile alagidi, enun ona laa tii pada leyin e,  bi be'ko iya ti alagidi i'ba fi je ewura a pada sole si ori eni!

= Never pursuit a goat into stronhead person house, go back for hin domot,  or else the goat punishment go land for your head!
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 11:19pm On Dec 23, 2010
Melo, melo laaso ninu oja, die n'iso oniru, die n'iso ologiri, eni ba so ni'so alaso, esinsin a boo = You mess in the market with style =

Do the right thing at right place and time to avoid embarrassment.

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by minto(m): 4:31am On Jan 09, 2011
Remii:

fi woroko se ada = take a bold step to make a positive change.

Point of correction. Fi woroko se ada simply means to improvise
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tunnytox(m): 10:31pm On Jan 09, 2011
d
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tunnytox(m): 10:32pm On Jan 09, 2011
@Olumogun
ese pupo fun itumo ti e fun awon asaayan oro ti mo ko siwaju yen

@Dayokanu
Ese pupo fun itoni ti e fi fun mi owo yin o ma ro'ke o amin


Remii:

Melo, melo laaso ninu oja, die n'iso oniru, die n'iso ologiri, eni ba so ni'so alaso, esinsin a boo = You mess in the market with style =

Do the right thing at right place and time to avoid embarrassment.

eleyi pa'ni lerin pupo  grin grin grin
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by minto(m): 4:52am On Jan 11, 2011
Remii:

Melo, melo laaso ninu oja, die n'iso oniru, die n'iso ologiri, eni ba so ni'so alaso, esinsin a boo = You mess in the market with style =

Do the right thing at right place and time to avoid embarrassment.

Yes oo. Opani lerin looto but then it's a good one. I never heard it anywhere before now; It's sure an addition to my yoruba idioms collection. Bless you Remii. Te siwaju mo ngbadun e.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 10:42pm On Jan 26, 2011
Aaye laa j'ogun ore, bo ba ku tan, ogun ko see je = You can only inherit a living friend, after his death, you are an unlikely heir = make hay when the sun is shining.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tjskii(f): 8:10pm On Jan 31, 2011
kaka ki eku ma je sese,afi she awadanu ni= loose translation= if i can't have it,no one else can
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 8:20pm On Feb 07, 2011
Pata Pata laa n foju, Kumo Kumo laa n dete, oju afo fotan ija ni muwa.
Often used when someone, overhearing a specific part of a conversation not minding the full jist and decided to comment, but was totally off in a tangent.
Could be used when someone felt insulted even when none was intended.

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 10:30pm On Feb 07, 2011
Omo atiro to ra bata ese kan fun iya re, oro lo fe gbo.

2 Likes

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 10:37pm On Feb 07, 2011
Oun tin tan leegun odun ti n mu omo alaagba wa fowo rakara jeko.
Children of the masquerade clan had all the free bean cake they wanted, cos it was surplus during annual eegun festival. As soon as the festival is ended, they had to buy like everyone else.

Used as word of advice that nothing lasts forever.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 10:38am On Feb 10, 2011
Ajala ta n na o? e yin naa koun. Used to respond to hippocrates crocodile tears.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 11:00pm On Feb 16, 2011
Teni ni teni , b'apon sun isu a bu fu aguntan re = One takes care of one's own: when a bachelor roasts yam, he shares it with his sheep
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by whiteroses(f): 1:56am On Feb 17, 2011
kaka k'eku o ma je shebe, shebe afi shawadanu.

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by whiteroses(f): 1:59am On Feb 17, 2011
otun ji ouje aburo e je, iwo omoyii ti'n ba gbaemu waa rope motto lo kolue
kilo n paalerin? oniranu ole ole t'oba ti rokunrin oju e mama tan wai wai
(my mums daily idioms growing up grin

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 7:08am On Feb 17, 2011
link=topic=414603.msg7641661#msg7641661 date=1296501022]
kaka ki eku ma je sese,afi she awadanu ni= loose translation= if i can't have it,no one else can
[/quote]

[quote author=whiteroses link=topic=414603.msg7745286#msg7745286 date=1297904190]
kaka k'eku o ma je shebe, shebe afi shawadanu.
lol,

sese (do mi) is beans, rat may not eat the beans but you have to throw it away since it would urinate and defecate in the on it. so rat didn't have it, you too could not have it either.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by whiteroses(f): 3:44am On Feb 19, 2011
olorinla j'ogun yeye, elego modo jogun arifin, opon iwaju ori temi ogbon l'okun inu re oo

1 Like 1 Share

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 7:44am On Feb 19, 2011
melo ni eera to wo wipe aran nyo oun lenu - how big is ant that is complaning of belly worms. Used when an upcoming person is complaining of too much responsibilities,
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by whiteroses(f): 2:41pm On Feb 19, 2011
Remii:

melo ni eera to wo wipe aran nyo oun lenu - how big is ant that is complaning of belly worms. Used when an upcoming person is complaining of too much responsibilities,

grin grin me when i started university, first year i'd complain of referencing, evening tutorial blah blah blah, ashe mo sheshe bere ni, unitil i entered second year when work placement and job + assignmnet met each other shocked igba yen ni momo pe olorun o kola
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 5:42pm On Feb 19, 2011
Afopinna To loun o pa fitila, ara re ni o pa
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 5:42pm On Feb 19, 2011
Ile ti a ba fi ito mo, iri ni yo wo
(The house built with saliva will fall apart when dew sets on it) Meaning: Don't cut corners
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 11:03pm On Feb 24, 2011
Olowo o ni gba arodan ki iwofa lo oun agun mate.

There cannot be 2 captains in one ship.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 5:45pm On Feb 26, 2011
A kìí bá ara eni tan kí á fara eni nítan ya: Meaning don't abuse the priviledges given to u
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 5:47pm On Feb 26, 2011
Àsegbé kankan ò sí,àse pamó lówà
Meaning: be sure your sin will find you out.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 9:35pm On Feb 26, 2011
Abu ni nje abuni, afini han nje afini han, ewo nti ewo ara ibadan ti nlo lojude ogunmola.
Used when someone while seemingly making a joke is really putting you in trouble.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 9:42pm On Feb 26, 2011
Apé kó tó jeun,kò ní jè bàjé Meaning: Delay is not denial

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply)

Keggites Members : Introduce Yourself & Ilya / Igbo Kwenu! Kwezuo Nu! Join Us If You're Proud To Be An Igbo Guy/lady / Nigerian Pidgin English And Their Meanings

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 31
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.