₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,327,308 members, 8,430,332 topics. Date: Saturday, 20 June 2026 at 10:26 AM

Toggle theme

Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. - Politics - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralPoliticsEto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. (1620 Views)

1 2 3 Reply (Go Down)

Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(op):
Iwulo ede abinibi ninu eto oselu.
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(op): 1:05am On Jun 21, 2020
Bawo ni a se le fi ede abinibi tun ilu se?
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:05am On Jun 21, 2020
Ani lati tun korikuloomu wa ko
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:05am On Jun 21, 2020
Oye ki awon asoju wa moju to oro yi
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(op): 1:07am On Jun 21, 2020
Fun apeere, ipa ti gbolohun "O to ge" ko ninu idibo abenu ti ipinle Kwara odun 2019
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by AbakalikiPress: 1:08am On Jun 21, 2020
....
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Mastakija(m): 1:09am On Jun 21, 2020
ewo tun leleyi ni tori oloun
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:11am On Jun 21, 2020
Ose koko
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:12am On Jun 21, 2020
Oye ki a jeki awon omo ton bo mo nipa ede ati asa
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by YourNemesis: 1:12am On Jun 21, 2020
Ipade awon aderinposunu ree o grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(op): 1:13am On Jun 21, 2020
YourNemesis:
Ipade awon aderinposunu ree o grin
grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by AbakalikiPress: 1:14am On Jun 21, 2020
Ndi uchu niile!
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:14am On Jun 21, 2020
E ku apero o
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Trutharenas: 1:15am On Jun 21, 2020
Oga o
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by ajailer(m): 1:17am On Jun 21, 2020
opon dandan ki awon omo wa mo npa ede wa... eje ki ama ba awon omo wa so ede wa nile, ko ki nse ede geesi nikan
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(op): 1:17am On Jun 21, 2020
Fatalityyyy:
Ki lo fa sababi
Sababi koor, abebi nii. grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:17am On Jun 21, 2020
Ose pataki
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Factshunter: 1:18am On Jun 21, 2020
Killo'nselehuh
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Factshunter: 1:18am On Jun 21, 2020
grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97:
Mo n gbadun ikanni yi bi eni n gbadun tea gbigbona
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97:
Eyin omo iya mi
1 2 3 Reply

2027: Timi Frank ké gbà àwọ̀n aṣáájú Guusu àti Àríwá pé kì wón má jẹ́ kí TinubuAwọn Dokita Olugbe Ni Naijiria Bẹrẹ Idasesile AilopinIroyin COVID-19 Lorilede Naijiria Loni234

I LEFT NNAMDI KANU AFTER I DISCOVERED HE IS A DICTATOR & SERIAL LIAR- KALU IDIKAPMB Loyalists,i Will Like To See Things From Your Perspectives.Alleged Video Of People Hailing Unknown Gunmen In Imo State Sparks Mixed Reactio