Osole Nla Todaju - Culture - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › Osole Nla Todaju (1741 Views)
| Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 7:33am On Feb 04, 2021 |
Osole je ogun ti ona fi Nla fun eniyan. Ti eniyan ba ri Osole toto Osole to tona Darin, Gbogbo nkan yio dabi igba wipe oluwa re Mose ju awon yoku lo. Nitori wipe, Gbogbo nkan ni yio ma dara, Owo yio maa wole fun ni ni Gbogbo ona ti ao si ma gbe nkan mere mere se bi ilekiko, moto Rira, opolopo ona ni yio sii. Sugbon Orisirisi ni Osole, nitori wipe tako-tabo ni ile aiye, bee naa ni Osole. Osole tutu wa,oso ako naa si wa pelu. Osole ti emi nsoro nipa re Yi je eleyi ti koni ipalara kankan, beeni Kosi ni ewu tabi alebu kankan. Osole Yi sise pupo tosi daju. Eleyi yato si ogun Owo gedegbe. Sugbon Osole Yi naa wo ni ati se re. Fun alaye ati ibeere, e le kan simi Lori whatsapp number mi : 08108458712 tabi email address mi : ogunfrayo@yahoo.com. Ewe nje Ogun todaju si wa bi ti Atijo. |
| Re: Osole Nla Todaju by Pearlyakin(m): 12:03pm On Feb 04, 2021 |
Ogun owo ni osole na, won si man lo eya ara eniyan lati shey, abi shey mo puro. |
| Re: Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 1:45pm On Feb 04, 2021 |
Emi o mo Osole toni Eya ara eniyan ninu o. Emi o de daruko ogun Owo rara. Lilo Eya ara eniyan lodi si ofin ijoba. Ewe ati egbo ni mo nsoro nipa re. IMO lo jantirere ni. |
| Re: Osole Nla Todaju by Pearlyakin(m): 2:06am On Feb 05, 2021 |
ogunfrayo:Okay, kosi wahala oluwa yo ma wa pelu yin. E jhur e ma bawa so fun awon onishegun ati babalawo to ku ki won jawo ninu ogun owo shishe fun awon odo orile-ede naijeria. |
| Re: Osole Nla Todaju by ogunfrayo(op): 4:14am On Feb 06, 2021 |
Eledumare yio ko wo inu awon odo orilede yi ati awon Odaju tiwon pe arawon ni babalawo. Sugbon ki gbogbo eniyan ni itelorun ati opolopo suuru, nitori wipe bintin laye. Pearlyakin: |
Ogun Osole To N Sise Aje • Osole Gbewa 15 Million Tabi 9million. • Osole Fun Eniti O Nse Yahoo • 2 • 3 • 4
No Benin Oba Was Buried In Ile-ife – Esogban Of Benin Kingdom, Edebiri • Oba Of Benin Visits Ile-ife • Simple Explanation On How Money Rituals Bring Wealth