Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,404 members, 7,853,787 topics. Date: Saturday, 08 June 2024 at 12:56 AM

Rubbyplus's Posts

Nairaland Forum / Rubbyplus's Profile / Rubbyplus's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 8:26am On Oct 31, 2016
IBA EYIN AGBAGBA!!!
E dakun enikeni to ba mo awon ise IMULE AGBA to daju to si lagbara
Ki won fi sori ikanni yi eg imule "owonrimiki" ati "alapamasise amona owo ma re"

@baba ayokomi1010 ati eyin aworo shasha e fi oju agba wooo
E gbami Oooooo!!!!!

IBA AGBA, EWE AMA JE

ASE EDUMARE
Culture / Re: .. by rubbyplus: 1:11pm On Oct 29, 2016
@Baba domonicson e ku ise takuntakun. [color=#006600][/color]
Mo juba ooooo. Iba omode, iba agba!!!. Iba gbogbo eyin awowo sha sha ori ikani yi. Eku ise itusile omo araye.


Ejowo e fun ni. Ise imule Alapamasise, amona owo ma re...
E jowo email m niyii: rubbyplus@gmail.com.

A ma ju yin se oooo

Ase Edumare
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 4:38pm On Oct 25, 2016
Agoo nile yi o, iba oo iba,

E jowo mo ni ibere:
Iru ise aajo wo ni yio je fun eniti irawo re je ERUPE.

Baba ayokomi1010, gbogbo iile e bami foju agba woo, e bami dahun si

Ama juwa se

Amin!!!!!
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 7:07pm On Oct 24, 2016
08101646045atwp(m):
Fun idahun onibere nipa IMULE!
Ose Pataki kamaase IMULE tabi EBE awon Agba!
Ki ohun gbogbo le maaja si irorun!

Mo dupe pupo fun idahun ati alaye yin. Mo ti se awon igbiyanju die lori imule agba.
Sugbon mo fe mo boya o DARA tabi o LEWU lati se OSOLE lehin ti. Eniyan
Ba ti se. IMULE AGBA. Kini EWU to wa nibe tabi anfani.

Ejoo e lami loye!!!

IBA AGBA. Ajuwase ooooo
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 6:58pm On Oct 24, 2016
08101646045atwp(m):
Fun idahun onibere nipa IMULE!
Ose Pataki kamaase IMULE tabi EBE awon Agba!
Ki ohun gbogbo le maaja si irorun!

Mo dupe pupo fun idahun ati alaye yin. Mo ti se awon igbiyanju die lori imule agba.
Sugbon mo fe mo boya o DARA tabi o LEWU lati se OSOLE. Kini EWU to wa nibe.

1 Like

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 12:09pm On Oct 24, 2016
Agoo nile yi o, iba oo iba, mo se ba gbogbo eyin awo lori ikani yi,
iba okunrin iba obinrin lori ikani yio, idunnu mi loje lati darapo moyin

@Baba Ayokomi1010 & others
E jowo e la mi loye lori ibere mi yi:
Nje ti eniyan ba lo ise imule agba, nje o le tun ma lo ise awure ie osole?
Ama ju se. Isese a gbe wa.
Culture / Re: .. by rubbyplus: 5:22am On Oct 16, 2016
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:05am

ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o


Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Bere lati Omo ogbon odun soke

Be sini awon ojogbon ti angba wlole Ni awon ojogbon bi AWO' ALFA' ATI WOLI
Kajolasepe'o
AJUWASE'O


E seun pupo fun alaye yin. E dakun, nibo laa fi ojo ibi naa ranse si,
email ati phone no mi ni yi:rubbypls@gmail.com; 08034290951. Add me to Whatsapp
A ma juse fun yin
Culture / Re: .. by rubbyplus: 4:35pm On Oct 14, 2016
Ifankaleluya:
FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

Baba ifankaleluya -aboru boye.
Eddakun e sanu mi; email mi niyi: rubbyplus@gmail.com

1 Like 1 Share

Culture / Re: .. by rubbyplus: 2:46pm On Oct 14, 2016
@Baba domonicson e ku ise takuntakun. Eku ise itusile omo araye.
Ejowo e fun ni. Ise imule Alapamasise, amona owo ma re...
E jowo e fi ranse si email mi: rubbyplus@gmail.com.
Phone no:08034290951 for whatsapp. Pls add me
Culture / Re: .. by rubbyplus: 2:25pm On Oct 14, 2016
Mo ki gbogbo tomode tagba lori ikani yii. Mo je olufe ikanni yiii lati
2015. Inu mi lati join finally. Ewe a ma je oo. Ase

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 18
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.